Ki lo kan musulumi ni pa oba awon were,omo ibile ni governor seyi makinde, olodumare yo ma wa pelu re ati gbogbo omo luabi ile yoruba ❤ ki ile yoruba gba omi ni ra, ase edumare
Tani Oliorun kudos to you for this program. You delivered a great speech and straightforward talk that the new young king should know. I wish he can follow your suggestions. That is what we yoruba is expecting of him that will preserve the dignity of yoruba kings. It shouldn't be difficult for him to do. He'll be respected for thuse 4 things you asked him to do without fear of anybody. He'll be 1sr class king that will rubbish others who are jegudujera and bow for fulani.
I love this man. God bless you for the good job that you are doing. God bless you with long healtjy life. Yoruba is so sweet in your mouth. I healthily envy you.
Esin islamu esin jagidijagan esin ikonileru esin ofo esin iro ni isilamu. Omugor alainiran alaileko ni awon musulumi yen. Omo eru ni awon musulumi. Imon lile.
E mura SI, ki e da ilu baba yin ru eyin agbalagba iya, kinlode ti e ko Fi wa difa yin ni Nigeria? Laise Ani Ani, Tani olohun lo bere wo, musulumi lonpo ju nilu Oyo lati ojo pipe wa, kiise isisiyi ni e o wa ma Fi Oro musulumi kewo Yan oba Le wa Lori nipinle oyo. Ninu gbogbo gomina ti a ti nni ni ipinle Oyo melo ninu won lo je musulumi? E lo beru olorun o
@@lolasobande8663 been. Nkan ti mo un so gan niyen. Awon musulumi ko le yan Iman. Oba ni yio yan Iman ti oun le fi okan bale lati joko si mosalasi lati gbo waasi re.
Igbese ti gomina gbe to dun momi niipe o fi lo adiifa ti o je ilumooka lati da ifa lati le fi yon Oba na.Gomina gbe igbese to ye ki awon Oyo Messi gbe.❤
Kabiyesi o, Oba tiwa, Oba Alafin OYO, ki Ade pe lori, ki bata pe lese Oba wa, ki abere di okinnin o. Gbogbo Oba ti won bati fi esin gbe gun ori apere ni ile Yoruba, iru Oba yen kole ni aseyori ti odara. Nitori wipe esin ti won pe ni esin alafia, ibanuje, ekun, ose ati ipayin keke ni omun wa fun gbogbo ibiti won ti gba esin yen ni aaye ni orile ede agbaye. Won fe fi esin da ogun sile ni ile Yoruba, ki won le pa opolopo awon odo danu, ki awon ajoji le gba ile wa, Olorun koni fun yin se o.
Oluwo Tani Olohun, video kan wa ti Gomina ipinlę Oyo ijęrin, Omololu Olunloyo ti s'alaye bi Ooni ijeta, Adesoji Aderemi ti ba ohun se iwadi ninu emi ki ohun to yan Alaafin ana, Oba Lamidi Adeyemi, s'ipo. Oro ko l'ojutu nigba yen na ni. O ti pę ti awon Oyomesi ti nşe madaru, o.
I sincerely give kudos to Gov. Seyi Makinde for this singular honor. Those mention Chiefs with unclean hands be make to face the law in respective of their position in the Oyomesi. Shameful especially to those elders. They can never be respected any longer. Their mischievous lives forever.
E se pupo Tani Olohun. Mo ngbadun eto re daadaa, bi o tile je pe Kristeni ni mi. Inu mi dun nipa bi Olrun se lo gomina lati doju ti awon afobaje ilu Oyo. Ni agbara Olorun, otito ni yoo maa leke nigba gbogbo. Mo mo Prof. Wande daradara. Odun mejo ni won fi se Vice Chancellor mi ni Ife (4 yrs B.A., 2 yrs. M.A.). A mo won gege bi olooto ti kii gba ibode, tabi je ijekuje. Ki Olorun je ki emi won o pe sii. Ijesha ni mi, sugbon ipo Alaafin se pataki fun gbogbo wa. Ki emi Alaafin tuntun o gun lori apere. Imoran mi ni pe, ki Alaafin tuntun se ibura fun awon Oyomesi pe won o ni gbabode fun pun tabi ilu Oyo. Won ni lati bura loju gbogbo ara ilu (ni gbangba), ki won si se ileri ni iwaju Alaafin tuntun pe awon gba fun, ati pe ti won ba gba ibode, ki Ogun pa won. This is similar to swearing to an oath of allegiance to the throne of Alaafin. I am a Christian, but I believe that the throne of Alaafin or Ooni, & any genuine 1st class Oba in Yorubaland, is a traditional throne/stool. Period.
Inu wọn bajẹ pé Ifá o yan Imale as Oba Ọ̀yọ́ 😂😂😂 Not to worry, Ifa will not choose the next Emir tabi Chief Imam but they are free to take the candidates names to Ifa.
I don't understand why the Muslims in yorubaland are doing this. Is that why akewugba..... tried to pass a wrong message across by saying all the kings in Oyo have been Muslims? So as to lay a wrong premise for Oyo to have another Muslim as the king? Is it only Muslims that are in yorubaland?
Isilamu to ya were gan ni. Awon omo iya me nini esin lon nilati gbe owo yen nle because they normally raise funds based on we must not lose the role. That why they even started Sharia court ni Oyo! Alaafin need to sack all the Oyomesi and appoint new one from their families in their place, Bashorun included. Alaafin need to send the prime minister parking asap.
Tani olohun bi mo se feran re to, o ti Fe ma koja aye re o. Se Iwo ro wipe awon Oyomesi Le fi ilu Oyo Le awon Fulani lowo? Mo Fe ki o wadi ohun gbogbo daju ki o to ma soro Lori ilu baba mi ilu Oyo. Se Kosi awon Ile orisa ni Afin wa loyo ni abi Iwo de Inu Afin Oyo ri?
Ki lo kan musulumi ni pa oba awon were,omo ibile ni governor seyi makinde, olodumare yo ma wa pelu re ati gbogbo omo luabi ile yoruba ❤ ki ile yoruba gba omi ni ra, ase edumare
Tani Oliorun kudos to you for this program. You delivered a great speech and straightforward talk that the new young king should know. I wish he can follow your suggestions. That is what we yoruba is expecting of him that will preserve the dignity of yoruba kings. It shouldn't be difficult for him to do. He'll be respected for thuse 4 things you asked him to do without fear of anybody. He'll be 1sr class king that will rubbish others who are jegudujera and bow for fulani.
Tani Olohunnnnnnn!!! Always on point!
😊
Thank you Governor Seyi Makinde. We owe you for this.
Well done Tani Olohun....you spoke excellently well. We have Governor Seyi Makinde to thank for this.
I love this man. God bless you for the good job that you are doing. God bless you with long healtjy life. Yoruba is so sweet in your mouth. I healthily envy you.
Governor Seyi Makinde kudos to you.
Olodumare bless you Prof. Tani Olohun (PhD)❤❤❤❤❤❤❤❤❤
Taniolohun is becoming more handsom
U are right,
Keep glowing Ifatimilehin
Owo ti Te koropon gbogbo awon Janduku, jagidijagan eru Saudi.. 😂😂😂
Isese lagba..
😂😂😂😂😂 Tani Olorun ti te koropon won fo! 😂😂😂
Yoruba yari patapata o😂😂😂
Tori ki won ba le ṣe Sariah ni nwọn ṣe kánjú Ọba jije, Haa ẹyìn onimale ilẹ Yoruba oju tiyin.
Always otito oro Tani Olorun wa gbo wa to
May Olodumare bless Governor Seyi Makinde abundantly ❤
TANI OLOHUN
OLOHUN BLESS YOU 🙌 🙏 ✨
Your Excellency gov seyi Makinde
Kaabiesi oooo Alaafin ti oyo ti Yoruba
Oba Sijuade was used to speak our Yoruba language during his visits abroad.
Always on point 👍
Good talk, Professor Tan’Olorun!
Great job buddy 👏🏽 👍🏾 ❤
Seyi makinde gan mope ohun ogbodo fi oro Ifa se awada
Dey play , if e do we no go do anything….. make we just glad he’s real
God bless you our dear governor Taloloun
God bless our new king 👑
IFA NI BABA BABA OLOHUN BLESS IFA 🙌 🙏 💖 ❤ ♥ ISESE
Ẹ ṣe pupọ fun gbo gbo iṣẹ ti e nṣe
This our new Alafin is not going to party ooo.
And is going to support every religion equally without sentiment.
God bless you Tani-oloun, You are on point.
Tani Olorun you are very intelligent
Esin islamu esin jagidijagan esin ikonileru esin ofo esin iro ni isilamu. Omugor alainiran alaileko ni awon musulumi yen. Omo eru ni awon musulumi. Imon lile.
E mura SI, ki e da ilu baba yin ru eyin agbalagba iya, kinlode ti e ko Fi wa difa yin ni Nigeria? Laise Ani Ani, Tani olohun lo bere wo, musulumi lonpo ju nilu Oyo lati ojo pipe wa, kiise isisiyi ni e o wa ma Fi Oro musulumi kewo Yan oba Le wa Lori nipinle oyo.
Ninu gbogbo gomina ti a ti nni ni ipinle Oyo melo ninu won lo je musulumi?
E lo beru olorun o
Tani olohun ko ran ipinle Oyo lowo pelu eto yi Rara nitoripe to Oro yi ba di wahala, IPA seyi Makinde oloriburuku gomina wa ko ni ka rara.
@HammedAderemi-sg5iw islam is all about conquest, wake up my bro!
Thanks brother
Alaafin nii ma yan Iman ni Oyo ati ni Ogbomoso. Oba ana ni o yan Iman Ogbomoso ki o to waja.
Oba Ajagungbade 3, Soun ana, lo fi Imam Ogbomoso je.
@@lolasobande8663 been. Nkan ti mo un so gan niyen. Awon musulumi ko le yan Iman. Oba ni yio yan Iman ti oun le fi okan bale lati joko si mosalasi lati gbo waasi re.
Awon alfa oniyeye dede
Makinde nse bebe..
KO si nidi mogo-mogo..
Inurun lo fe PA gbogbo awon Eru Saudi ti won sunkun kakiiri
Every governors should emulate Oyo state governor on this aspect.
Kudos to Seyi makinde
You have done a good job, and remain blessed.
Kudos to the governor , kudos to you.
I always gbadun your program keep it up 👍
Baale ju emir lo ooo nitori emir olori esin ni... Baale olori abule ni ati wipe baale loni Ile... Olodumare agbe wa oooo
What is the difference between Oluwo and Aregbesola. Both of them are fanatics
We always supported you, God bless you.
ILE YORUBA O NI BAJẸ
I am very happy with the king
Ifatimileyin... good analysis always...
Very well said
Awon alfa oni lawani ofo.
😅😅
Igbese ti gomina gbe to dun momi niipe o fi lo adiifa ti o je ilumooka lati da ifa lati le fi yon Oba na.Gomina gbe igbese to ye ki awon Oyo Messi gbe.❤
Gov. seyi makinde ❤❤❤❤❤❤❤
TANI OLORUN, I LOVE YOU
Good of you
Governor Seyi Makinde is a good man ❤❤❤
Kabiyesi o, Oba tiwa, Oba Alafin OYO, ki Ade pe lori, ki bata pe lese Oba wa, ki abere di okinnin o.
Gbogbo Oba ti won bati fi esin gbe gun ori apere ni ile Yoruba, iru Oba yen kole ni aseyori ti odara.
Nitori wipe esin ti won pe ni esin alafia, ibanuje, ekun, ose ati ipayin keke ni omun wa fun gbogbo ibiti won ti gba esin yen ni aaye ni orile ede agbaye.
Won fe fi esin da ogun sile ni ile Yoruba, ki won le pa opolopo awon odo danu, ki awon ajoji le gba ile wa,
Olorun koni fun yin se o.
Oluwo Tani Olohun, video kan wa ti Gomina ipinlę Oyo ijęrin, Omololu Olunloyo ti s'alaye bi Ooni ijeta, Adesoji Aderemi ti ba ohun se iwadi ninu emi ki ohun to yan Alaafin ana, Oba Lamidi Adeyemi, s'ipo. Oro ko l'ojutu nigba yen na ni.
O ti pę ti awon Oyomesi ti nşe madaru, o.
The truth is to tell you I am very happy with you 💪
KI OLORUN JE KI NEW OBA OYO YI JE ELEYI TI,.... IFA ATI AWON ALALE YAN.
Tani olorun you no go kill me🤣🤣🤣 sultan of sokoto kee
Wisdom is embedded in you. Thanks a lot.
Ifa ni ona,se Muhammad yan oba ni igba aiye re ni,won fe gba ile wa tan ni,ki won so di asale, Orunmila oni gba fun won,ifa ti yan eyi na.
Need more yoruba people to reason independently like this man..
You are welcome prof ❤
I sincerely give kudos to Gov. Seyi Makinde for this singular honor. Those mention Chiefs with unclean hands be make to face the law in respective of their position in the Oyomesi. Shameful especially to those elders. They can never be respected any longer. Their mischievous lives forever.
E se pupo Tani Olohun. Mo ngbadun eto re daadaa, bi o tile je pe Kristeni ni mi.
Inu mi dun nipa bi Olrun se lo gomina lati doju ti awon afobaje ilu Oyo.
Ni agbara Olorun, otito ni yoo maa leke nigba gbogbo. Mo mo Prof. Wande daradara. Odun mejo ni won fi se Vice Chancellor mi ni Ife (4 yrs B.A., 2 yrs. M.A.). A mo won gege bi olooto ti kii gba ibode, tabi je ijekuje. Ki Olorun je ki emi won o pe sii.
Ijesha ni mi, sugbon ipo Alaafin se pataki fun gbogbo wa. Ki emi Alaafin tuntun o gun lori apere.
Imoran mi ni pe, ki Alaafin tuntun se ibura fun awon Oyomesi pe won o ni gbabode fun pun tabi ilu Oyo. Won ni lati bura loju gbogbo ara ilu (ni gbangba), ki won si se ileri ni iwaju Alaafin tuntun pe awon gba fun, ati pe ti won ba gba ibode, ki Ogun pa won. This is similar to swearing to an oath of allegiance to the throne of Alaafin. I am a Christian, but I believe that the throne of Alaafin or Ooni, & any genuine 1st class Oba in Yorubaland, is a traditional throne/stool. Period.
If Allah come gan, o ma dobale
Nice message
Inu wọn bajẹ pé Ifá o yan Imale as Oba Ọ̀yọ́ 😂😂😂 Not to worry, Ifa will not choose the next Emir tabi Chief Imam but they are free to take the candidates names to Ifa.
Ogbo ato Taniolorun
Amem ase edumare 🙏🙏🙏
Ogbo Ato Baba
Ogbo Ato o, Prof. Tani Olohun 😂😂😂😂
You are correct God bless you you get it
I don't understand why the Muslims in yorubaland are doing this. Is that why akewugba..... tried to pass a wrong message across by saying all the kings in Oyo have been Muslims? So as to lay a wrong premise for Oyo to have another Muslim as the king? Is it only Muslims that are in yorubaland?
Akewu is a faced human being
Iwaju iwaju ni e o melo.Ami,ase
Tanii Olorun koboko awon oni lawani
Igba ti o ję wipe ọba tuntun yi kìí şe MUSULUMI
Ara wa nta wọn 😅
Musulumi Ni Akeem
Am not sure he practice it@@olabodeolajuwon4318
I pray too he won't be fanatics even though he practices it
😅🤣🤣😂😂😂😂
Sorry to disappoint you...
He is a Christian and we love it.. @@olabodeolajuwon4318
He is a Muslim! But not the one the oyomesi want@@OmoIrunmole29
Ogbo l'ogbo ato yin brother mi
Eku ise takuntakun brother mi
I’m waiting for muft iwo on this oba oyo
😅😅😅
MURIC has already spoken.
Akewugbagold ati Mufti Iwo are in shame now.
Ogbo ato Tani olorun
Lol 😂
If Owoade carries himself well as a real Yorùbá king, trust me nobody will respect Enitan Ojaja again.
Adalu ru ni won, awon Oni jagidi jagan musulumi ni won.
So ifa always choose us citizens oga oooo
Emir is Muslim leader.
Oyo mesi na bad market this time around oooooo
Isilamu to ya were gan ni. Awon omo iya me nini esin lon nilati gbe owo yen nle because they normally raise funds based on we must not lose the role. That why they even started Sharia court ni Oyo! Alaafin need to sack all the Oyomesi and appoint new one from their families in their place, Bashorun included. Alaafin need to send the prime minister parking asap.
It will be difficult for Adebayo Shittu to emerge on this note
Akewugba-bribe intermediary between Oyomesi and Emir Sokoto
👍👍
Tani Ọlọ́run is right that if the governor should have been a Muslim.
😊😊😊😊😊
Se baba wande abimbola wa kere ninu babalawo ni?
Oriyomi tewonde Odaran Apayan na inu re kodun si
EMIR OF ILORIN OLE 4 1 9 MABULLA OMO FULANI OLE MABULLA
Oriyomi in Shame now too
Oyo o mesi mo oh
Musulumi e ti n je tan lo
Aye awon musulumi ko wun mi rara daru dapo won po pupo ju
Oju ma ti gbogbo oda le ile yoruba
Ekueto baaami
Tani olohun bi mo se feran re to, o ti Fe ma koja aye re o. Se Iwo ro wipe awon Oyomesi Le fi ilu Oyo Le awon Fulani lowo? Mo Fe ki o wadi ohun gbogbo daju ki o to ma soro Lori ilu baba mi ilu Oyo.
Se Kosi awon Ile orisa ni Afin wa loyo ni abi Iwo de Inu Afin Oyo ri?