They have their Emir there so they should go complain to their Emir. Oluwo didn't learn from Afonja, He actually thought they would be on his side for pushing and preaching Islam. He's gonna learn the hard way. The same man that opened his cap to honor another people's culture and traditions say people should be coming to Iwo to buy stuff now they're destroying one of the things being produced in Iwo. Nonsense king.
Awon omo ale jati jati,rede rede,raun raun,pala pala ilu apala. Awon enia buruku ,omo ale ti nfi owo osi juwe ile baba re ni Oluwo ati mufti omo igbira akkotileta yi je.
Since the Kabiyesi is the sponsor of Herdsmen in Iwo, he should be sent the bill for the damage. Oluwo and his 'agenda' will be exiled to Ilorin laslas ni! 😂
@@arinolamayaki7487 Awọn màdàrú to wa ni Ilorin ni wọn fẹ ki gbogbo ilẹ Yoruba wa ni abẹ àlejò, so it is better he is exiled to Ilorin to join his friends. 😌
Ekotiri nkankan , oba oluwo ti so wipe Fulani Omo iya yin ni. Elo beere lowo awon Benue Ati plateau ohun to won foju ri ni pa gbigba won laaye tori esin. .
Weldone oo Tanioloun. Get us the juju, apepa,eedi,sanponna ti yio pa awon ota Yoruba. We don't need to ague with mouth .Let us use Yoruba power to fight our enemies.
@@user-wu4su7br9i Omode o moogun o npe l'efo. Nkan ti awon agbalagba fi njeko, abe ewe lo wa. Nkan ta fi ju omode lo, a ki fi han, ta ba fi han, a ki fi le lowo. Gbogbo aso ko la nsa loorun. Ki owe je ti awon agbalagba. Ire o!
If you talk, they will say Islam. They should go and tell their Emir of Iwo nah why complaining? Las las, Una go learn the hard way. If they don't even collect the entire land from you ehn!
Mufti of Iwo and Oba Rasheed Oluwo said Iwo is Fulani land. So, expect nothing less. However, it's a pity that efforts at addressing herders problems and the food crisis can't yield positive results when mufti and oluwo are playing religion
Fulanis were having a welcome party for their emir. Iwo has fetched a firewood with many ants called emir Rashidi and mufuti iwo so it must witness the visit of lizards called foolanis
Eyin iwo egbodo complain oo, awon family yin lati ile hausa ti oluwo ko wale ni won wa kiyin. Obayin ni fulani ni ohun, eyin naa si gba bee nitori esin ati owo, Eyin ara iwo, eku tiyin. Ema losi police staion elo fi ejo sun Ana won Emir lwo to kowon wale
Eyin ara ilu iwo won sese bere si yin ni o.sebi nkan ti oba yin se fee ni yen eloba abudulrosidi oba yin kie lofi ejo sun.sebi awon family re ni awon Fulani.
Tani Olorun e kú ètò. Se kò sì akoya nile Yoruba mò ni?. E jeki awon agbe wá lo ṣe eto Yorùbá sí inú okò wọn.. Se bí ẹrí ohun tó sele ni ilu Ekiti ti ará bi sá pa gbogbo malu awon fulani. Ogun Fulani tí wọ ilẹ̀ Yorùbá e jeki a mura dada.
Gbogbo ohun ti won she si yoruba There can't try it in southeast just they are not in same page, until ti e ba fi esin won sile fun because you people will get rest
Is the work of your King .When you are ready the Town will do necessary things to your king.Fulani lose omo lya wa. Apaniyan no won.Oba yin lo nse yin. Oro ni gbogbo re Sebi Yoruba ni o .Oro ko lo ni lo Paws da Simeon.
Oloye Sunday igboho was shouting crying thar we should all unite against this injustice against yoruba by fulani, some idiotic and bastard in our midst said that Sunday igboho should keep quiet. Now Sunday igboho is enjoying with his family in Germany while we are still here continuing in our complain...this is just the beginning
There is nothing in this video to prove that this thing happened in iwo! It's lacking in substances required to be accepted as evidence. 1. It's not dated; the person who recorded it did not tell his intended viewers the date and time that he did it. 2. No mention of the name of the town or village where the video was recorded; the owner of the video failed to address this important information. 3. The police station and amotekun offices must have addresses; these addresses were not mentioned. While the efforts put into this video materials are appreciated, the facts remain that anyone who looks at the video critically, or reads the comments objectively, will see that it is compromised or biased. You have to have your proofs before you put anything out there; the source has to be reliable and credible. Learn from iya oloshun and Affa Okutagidi.
Kilode ti E ke se bill won Ke ke nigbati Oba yin fi fulani je oye won so fun yin se bil ohun te ni pe ki won fi Oba yin sile kaye ma soro is Oba so tan yin so ju yin ti ja
O se nrin awon Yoruba ni, ko i ti ja’won je. Ni igba ti o ba ge won je, won a parapo, won a dide OGUN ti awon Fulani ni ibikibi ti won ba f’ara pamo si ni Ile Yoruba. Won a bere lati ori Oluwo ati Muftau. O ku ise takuntakun o brother wa Tani Olohun.
ELEYI TUN LE OO, KINI AWON ARA IWO NWO TIWON FI YAN OMO FULANI NI OBA YORUBA? NIGBATI OBA WON NSE GBOGBO AWON NKAN BURUKU NI ILU IWO, KINI AWON ARA IWO SE LORI RE? ESAN NI NKAN TO NKE LORI ARA ILU IWO. KIWON LO TORO AFORIJI LOWO OLORUN OLODUMARE.
Se ko awon ijoye ni ilu Iwo ni ,emi rope oye ki oloye kan ti dide lati soro soke kinni awon ti kii se musulumi se? Awon Odo nko?tabi awon otookulu to lenu Titi de federal because I don't understand
They have their Emir there so they should go complain to their Emir.
Oluwo didn't learn from Afonja, He actually thought they would be on his side for pushing and preaching Islam. He's gonna learn the hard way.
The same man that opened his cap to honor another people's culture and traditions say people should be coming to Iwo to buy stuff now they're destroying one of the things being produced in Iwo.
Nonsense king.
He will never live long to destroy Yoruba heritage by the grace of God.
@geraldjohn1588 BY the grace of OLODUMARE not God or Allah
@@geraldjohn1588 Ase Edumare
Funra oniko lo fenu e pe iku, Olu Iwo loni ohun feki ilu ohun dabi Mecca, awon Fulani ko Malu wa sise haji ni 😎
😂😂😂😂😂😂😂
😂😂😅😅
Hahaha 🤣😂😂🤣😂 okaayyyy 😹
😂😂😂
Didirin mufti Oro esin loba gbogbo won Iba kuku Fulani, esin Islam tiwon o ni jere re.
That is oluwo prayer point in mecca that people should come and invest in iwo and he's prayers has been answered Fulani have started there business 😅
🤣
Nothing but the truth life’s are changing with your programs ❤
Never hausas will never allow Yoruba man to lead them in Islamic prayer, never
Oluwo is an in-law to Fulani, his wife is a fulani woman.
Awon omo ale jati jati,rede rede,raun raun,pala pala ilu apala. Awon enia buruku ,omo ale ti nfi owo osi juwe ile baba re ni Oluwo ati mufti omo igbira akkotileta yi je.
Tani olorun you are right. All what you are saying is pure truth.
When oloye Sunday igboho rise to face the wicked fulani hearders then, they were the first to stand against him. Karma is a bitch
Eyin ara Iwo eku amumora o
New age Afonja and Alimi😅
Since the Kabiyesi is the sponsor of Herdsmen in Iwo, he should be sent the bill for the damage. Oluwo and his 'agenda' will be exiled to Ilorin laslas ni! 😂
Ilorin ke, abi Kano nilu baba iyawo e 😂
@@arinolamayaki7487 Awọn màdàrú to wa ni Ilorin ni wọn fẹ ki gbogbo ilẹ Yoruba wa ni abẹ àlejò, so it is better he is exiled to Ilorin to join his friends. 😌
@@AncientHebrewNeverDied 😂😂😂😂😂
Iyawo are tinubu sope ki awon eniyan lo da oko, la I si eto abo, tinubu divide Nigeria ki oni ka Lu ku lo je oruko baba e,
I talk am before say this oba go scatter ilu Iwo
I really appreciate oloye Laji Abbas of itan Yoruba
He opened my eyes to know how delicate IWO and ILORIN is to the survival race of Yoruba people
Ekotiri nkankan , oba oluwo ti so wipe Fulani Omo iya yin ni. Elo beere lowo awon Benue Ati plateau ohun to won foju ri ni pa gbigba won laaye tori esin. .
Sebi oko ni maalu si je? Won nbo wa do iyawo, iya ati awon omo won laipe. E ri.
Iyawo oba yin lonjeko
❤❤😂😂😂😂
😂😂😂😂
Fulani and Iwo people. It is a family matter.
😂😂
Huuum, a word is enough for the wise. May God increase you in knowledge, wisdom and understanding.
Nígbà tí Ọba wọn ṣe woọ́nran-wọ̀nran wọn ò sòrọ̀
Tani Olohun, E, so o fun awon agbe ki won lo o ba Emia Iwo Rashid fun e ti se le, fun a tun se o.
Weldone oo Tanioloun.
Get us the juju, apepa,eedi,sanponna ti yio pa awon ota Yoruba.
We don't need to ague with mouth .Let us use Yoruba power to fight our enemies.
@@user-wu4su7br9i Omode o moogun o npe l'efo.
Nkan ti awon agbalagba fi njeko, abe ewe lo wa.
Nkan ta fi ju omode lo, a ki fi han, ta ba fi han, a ki fi le lowo.
Gbogbo aso ko la nsa loorun.
Ki owe je ti awon agbalagba. Ire o!
Olodumare bless you ❤❤❤
@@dbanjjoseph2137 Aseeee
If you talk, they will say Islam. They should go and tell their Emir of Iwo nah why complaining?
Las las, Una go learn the hard way. If they don't even collect the entire land from you ehn!
I have no pity for the people of Iwo, Yoruba nation is the only way out let them stay with their Emir and solve their problems for themselves
Their Oba has sold iwo people to the Fulanis. He said he is an Emir.
Abi o they should face the consequences themselves 😢
Kílódé tó fi jé pé ariwo lásán lèyin èèyàn wònyí mòón Pa! Kíní se téò lè yánlè, kée yán oko yín?
Tíjoba ò bá gbèjà yín, èyin náà e gbèjà ara yín.
Islam ti so awon Yoruba didirin
Yoruba wake up
You wan chase your olori family out of Iwo ni? 😂😂, Try to adapt to them okay, because they will collect back their daughter from your king oo😂😂
Woman finish for Yorubaland? 😂😂😂
Never pity them, they haven’t seen anything. Where were they when their king was inviting Fulani?
God bless you
This na family problem, when Iwo people allow their Oba to allow Fulani’s in Iwo, they should stop complaining and their Oba.
Ki awon omo Iwo ja fun rara won.
One Nigeria is not working.
Mufti of Iwo and Oba Rasheed Oluwo said Iwo is Fulani land. So, expect nothing less. However, it's a pity that efforts at addressing herders problems and the food crisis can't yield positive results when mufti and oluwo are playing religion
Lovely brother you always says the truth ❤
Talolorun eku ishe takun takun ki agbe ilu iwo loba mufty iwo ati oluwo ko gba won low anan re now
Awon omo musulumi ile yoruba lolo sile sunday igboho
Ilorin Afonja and Fulani Alimi. Yoruba! Yoruba!! Yoruba!!!
Oba igbolabi da ko wa kilo fun awon oga Fulani oooo
ONE LOVE,...TANI OLORUN
Fulanis were having a welcome party for their emir. Iwo has fetched a firewood with many ants called emir Rashidi and mufuti iwo so it must witness the visit of lizards called foolanis
Igbawo ni oye to kan ara Iwo ko ni kan ara Ede?
Ti fulani ba le se eleyi fun igi opoto, what is the joy of igi gbigbe (dry wood)
Ano oba iwo ni Fulani,ki won loba ona won Oluiwo kio lo ba awon ano e Fulani tio Fi eran je oko won
YORUBA NATIONA NO GOING BACK
Malu ana won ni eje ki malu jeun oo
They are supporting their emir
I am from iwo 😂 congratulations to us 😅I love 💕 this
😂😂
I pray Fulani won't take over the land soon because oba oluwo is there servant
They should go n meet emir of Iwo land now 😂😂😂😂😂 na emir family so no comment..😂😂😂😂😂
Olu iwo of Iwo is there na
Olohun mu o,,,,,,,😂😂😂 gbogbore niwon maje tan 😂 Sunday igboho Dey shout,,una Dey mock him,,,,,seh Sunday igboho get farm
Let their emir come to their aid, odo to ba gbagbe orisun gbigbe ni yoo gbe.
Ja fori e maja feni kan, emir won o ja fun won ilu onilu lon ja fun,
Yoruba nation no going back
ALAHU DON ANSWER OLUWO PRAYER IN SAUDI ARABIA
Awon olori were ti won hun dari iwo, okuta lo ye ki awon omo iwo fi le gbogbo awon alatenuje esin.
TANI OLOHUN
OLOHUN BLESS YOU
Ki lo so,sebi o ye ko lo si odo emira won ni,se oluwo o si ni aye mo ni. Gbogbo yi ni ilu lwo alabosi ni yin,esese bere ni ni ilu lwo.
Eyin iwo egbodo complain oo, awon family yin lati ile hausa ti oluwo ko wale ni won wa kiyin. Obayin ni fulani ni ohun, eyin naa si gba bee nitori esin ati owo, Eyin ara iwo, eku tiyin. Ema losi police staion elo fi ejo sun Ana won Emir lwo to kowon wale
OLOHUN BLESS YORUBA LAND ❤❤
I love this Tani olorun 😂
Emir yin ni iwo ni ki e bi lere o ni lati ma si nitori fulani iyawo re awon ana re lo se e
Iya o ti je won, sebi oko ege ati agbado ni maalu won si je, won nsi bo wa do awon iyawo, omo ati awon iya won loju won. Won o ti ri nkankan.
Eyin ara ilu iwo won sese bere si yin ni o.sebi nkan ti oba yin se fee ni yen eloba abudulrosidi oba yin kie lofi ejo sun.sebi awon family re ni awon Fulani.
Malu Rashidi ni
Eku eto ❤❤❤❤❤❤
Elo so fun emir ilu iwo, ana fulani
Tani Olorun e kú ètò.
Se kò sì akoya nile Yoruba mò ni?.
E jeki awon agbe wá lo ṣe eto Yorùbá sí inú okò wọn..
Se bí ẹrí ohun tó sele ni ilu Ekiti ti ará bi sá pa gbogbo malu awon fulani.
Ogun Fulani tí wọ ilẹ̀ Yorùbá e jeki a mura dada.
Awon Omo iya yin loje okoyin , malu loje oko malu
Gbogbo ohun ti won she si yoruba There can't try it in southeast just they are not in same page, until ti e ba fi esin won sile fun because you people will get rest
they will learn and they will learn in a hard way
Thier emir is capable of talking to his boys, fulani
His inlaws 🤣🤣🤣🤣🤣
Otito oro,
Iya koi ti je won ti Fulani ba so won di elebi won yio ronu
No case , gambari pa fulani , fulanis are your brothers.
This guy get bad mouth wahalahi 😂🤣
Is the work of your King .When you are ready the Town will do necessary things to your king.Fulani lose omo lya wa. Apaniyan no won.Oba yin lo nse yin. Oro ni gbogbo re Sebi Yoruba ni o .Oro ko lo ni lo Paws da Simeon.
Àwọn ẹbí olú ìwo ni wọ́n.
Rashid Oluwo lo ni maalu
Ko bu nka si oju ese malu
ebu oju ese won
igba ti won lerin ni won da maalu
i can't pity person that wicked me
Oloye Sunday igboho was shouting crying thar we should all unite against this injustice against yoruba by fulani, some idiotic and bastard in our midst said that Sunday igboho should keep quiet.
Now Sunday igboho is enjoying with his family in Germany while we are still here continuing in our complain...this is just the beginning
Isele yi si nbo nilu oyo oooo,Ti awon Afobaje ilu oyo ba le se,asise yan bakannaa.nitori owo,aye afowoba fiile.
Se bi gbogbo won ni won lo se iyawo oba won eran oba lo nfisu oba je esese bere eti ri nkankan
Fulani ni iyawo rashidi e lo ba rashidi ki e so fun e ti ri kankan
There is nothing in this video to prove that this thing happened in iwo!
It's lacking in substances required to be accepted as evidence.
1. It's not dated; the person who recorded it did not tell his intended viewers the date and time that he did it.
2. No mention of the name of the town or village where the video was recorded; the owner of the video failed to address this important information.
3. The police station and amotekun offices must have addresses; these addresses were not mentioned.
While the efforts put into this video materials are appreciated, the facts remain that anyone who looks at the video critically, or reads the comments objectively, will see that it is compromised or biased.
You have to have your proofs before you put anything out there; the source has to be reliable and credible.
Learn from iya oloshun and Affa Okutagidi.
Won si maa payin daada nilu iwo gege bi eto ti rasheed ati mufti ,pelu gbogbo awon tofi je oye tifowo si ni odo awon fulani ati awon arab.
Tani olorun emi yin yoo gun ipa ota koni ka yin,awon oro isiti yin olorun yoo je ki won o gbo
❤❤❤
Ara Owo e pele tiyin. Oba yin lo ko ba yin.eti gba satani lalejo
E lo pariwo fun oba yin Oluwo iran foolani!!!
Kilode ti E ke se bill won Ke ke nigbati Oba yin fi fulani je oye won so fun yin se bil ohun te ni pe ki won fi Oba yin sile kaye ma soro is Oba so tan yin so ju yin ti ja
Kabiyesi Olodumare, kabiyesi Ifa 😊
O se nrin awon Yoruba ni, ko i ti ja’won je.
Ni igba ti o ba ge won je, won a parapo, won a dide OGUN ti awon Fulani ni ibikibi ti won ba f’ara pamo si ni Ile Yoruba. Won a bere lati ori Oluwo ati Muftau.
O ku ise takuntakun o brother wa Tani Olohun.
It serves the lwo people right. When their king turned himself to emir and together with his mufti invited the fulani, where are they?. What did do?.
Ai ma da sẹria fun wọn lati ibẹrẹ lo nda yọnpọn yọnrin yi. Bẹ naa ni o na ṣe ri ti awọn ti o wa ni akoso ba kọ lati fi oju ofin han awọn fulani yi.
ELEYI TUN LE OO, KINI AWON ARA IWO NWO TIWON FI YAN OMO FULANI NI OBA YORUBA? NIGBATI OBA WON NSE GBOGBO AWON NKAN BURUKU NI ILU IWO, KINI AWON ARA IWO SE LORI RE? ESAN NI NKAN TO NKE LORI ARA ILU IWO. KIWON LO TORO AFORIJI LOWO OLORUN OLODUMARE.
Se ko awon ijoye ni ilu Iwo ni ,emi rope oye ki oloye kan ti dide lati soro soke kinni awon ti kii se musulumi se? Awon Odo nko?tabi awon otookulu to lenu Titi de federal because I don't understand
FactZ. What is the solution tho.
Iwo no get Oba na Emir dem get. So Fulani can put cows to wack dia farm crops. E ma ji giri ke le were yen danu.
Wonti fi tirah ati huntu ko opolo won kuro, asan panti lasan lowa ninu opolo won
Make them ask that Baba