ODO ONIPASAN

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 29 ก.ย. 2024

ความคิดเห็น • 21

  • @olanrewajuabdulkareem-yz5si
    @olanrewajuabdulkareem-yz5si วันที่ผ่านมา +3

    HLA lemina loo aaaaa areee. Otun mumi ranti eruobodo.adelakun.tile wonko eyin si HLA.omi lolaaawa ATI Ile adelakun eruobodo.

  • @olanrewajuabdulkareem-yz5si
    @olanrewajuabdulkareem-yz5si วันที่ผ่านมา +3

    Oluwa eledumare yioma ma waa peluyin lojogbogbo Amin aseeeeeee

  • @usmanwahab6262
    @usmanwahab6262 วันที่ผ่านมา +3

    North is not like this, federal government spend a lot of money in the north

  • @adeniyitemilola2560
    @adeniyitemilola2560 วันที่ผ่านมา +3

    Yoruba Nation is the solution to yoruba land

  • @moreadeyemo1630
    @moreadeyemo1630 วันที่ผ่านมา +1

    School Methodist ni emi na lo lati odun 1959 si 1965. Omo Oke-Adu ni emi na. Odo Onipasan yen lama nwa pelu odo Alapata na.

  • @usmanwahab6262
    @usmanwahab6262 วันที่ผ่านมา +4

    Yoruba nation lafe

  • @al-aminsalami929
    @al-aminsalami929 วันที่ผ่านมา +2

    Kí wọn tún ibi yíi ṣe. Ayika re doti

  • @hassanyusuf1655
    @hassanyusuf1655 วันที่ผ่านมา +1

    Omi ti awa mu da gba ni ye wahalahi be ni opafun loyi ka Ile wa ni oni pason. Baba god bless un HLA ni eni na lo niye omo oni pason ni mi.ati odo koteyemu wa ni iwaju die ti e ba ti jade sita odo koteyemu wa ni waju die ni oni pason ye naa ni Ile tiwa ni ye baba yio dara fun yin ni agbara eledumare.

  • @Babaowe-wh6uj
    @Babaowe-wh6uj 15 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    Why are there bricks in the river?
    What's in that bricks covered with pan?

  • @olanrewajuabdulkareem-yz5si
    @olanrewajuabdulkareem-yz5si วันที่ผ่านมา +1

    Areee opitan aaaa oni tan lailai Amin aseeeeeee orimi sinwuu.ki oluwa pese funmi kiarira nijokan.

  • @olanrewajuabdulkareem-yz5si
    @olanrewajuabdulkareem-yz5si วันที่ผ่านมา +1

    Aaaaa areee opitan.omumiranti laarookutukutu lamajilo ponmi lonpasan.

  • @loantha2996
    @loantha2996 วันที่ผ่านมา +1

    Nothing will change under one liegeria

  • @ollyofkent007
    @ollyofkent007 วันที่ผ่านมา +1

    Aragodo at Irefin ati odo Iya’wo at Agugu

  • @hassanyusuf1655
    @hassanyusuf1655 วันที่ผ่านมา +1

    Baba atun unpe ni odo alagba fo e bere dada adupe baba

  • @ollyofkent007
    @ollyofkent007 วันที่ผ่านมา +1

    I remember this place 😅

  • @suadahitv1684
    @suadahitv1684 23 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    Toor ❤ mansah allah 💯🙏💯😊❤

  • @kehindejosephkashimawo9410
    @kehindejosephkashimawo9410 วันที่ผ่านมา +1

    Àmọ́ ìyà ni.. Ká jí ni aago mẹ́ta òru lọ máa fi ori ru omi.. Àwa náà tí ṣe rí ní Abẹ́òkúta, nigbati a wà ní kékeré.. Ṣùgbọ́n kii se bí pé ká jí ni aago mẹ́ta òru o... Ìyà ni.. Ẹ wo bí ìlú Ibadan ṣe tóbi tó tọ́ sì lòkìkí

    • @itanyoruba
      @itanyoruba  วันที่ผ่านมา +1

      Asiko ẹ̀rùn ago mẹta oru ni ero mọ pọ ju

    • @kehindejosephkashimawo9410
      @kehindejosephkashimawo9410 วันที่ผ่านมา

      @@itanyoruba Aarẹ̀, nígbà wo lẹ wá sùn ti ọ́ di pé ẹ máa jí laago mẹ́ta òru..?? Èèyàn lè lọ pọn omi tí yóò lò tá bá ti ilé ìwé de, àti ní weekend.. B'èrò bá tiẹ̀ wá pọ̀ yẹn gan ni ọ̀ dáa.. Èmi gẹ́gẹ́bí ẹnìkan prefer nígbà tí odò bá dá díẹ̀ tó jẹ́ pé un tètè pọn gbogbo omi tí ń ọ́ pọn.. B'èmi ṣe ríi nìyẹn o.. Níbi tí aiyé de bayi,, kò yẹ ká tún sì rí àwọn èèyàn ti yoo maa lọ fi ori ru omi láti odo mọ́.. Ọ́ yẹ kí omi ẹ̀rọ máa yọ nílé olúkúlùkù ní.. Ẹ wo bí ìlú Ibadan ṣe tóbi tó.. Ká tún sì ríi pé àwọn èèyàn ṣì nlọ fi ori ru omi..Bẹ́ẹ̀ lọ sí ṣe rí ní gbogbo àwọn ìlú ńlá ńlá wa,, State Capitals,, Tọ́ sì ń bá èmi nínú jẹ́ ti mo ba ronú nípa rẹ̀.. Ààrẹ o!! ! Ìyà ni.,, suffering and smiling.. Àsìkò tí a lọ nfi orí ru omi a le lò fún nkan anfaani àti ìdàgbàsókè míì fún agbegbe àti fúnra wa.. Bo jẹ́ pé a fi wákàtí kan sùn nínú rẹ̀ ni ó ní anfaani to ńṣe làgọ́ ara.. Àbí ẹ ní mo ti wí?? 😁😁😁😁

    • @moreadeyemo1630
      @moreadeyemo1630 9 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

      @@kehindejosephkashimawo9410 Otito oro leso, sugbon nigbati awon ti ndari wa nilu je awon odaju ika eniyan, ti ko se gbogbo eto ti oma ro wa lorun nko,.
      E je ka fowo-sowopo lati pariwo sita ki orile ede Yoruba (Yoruba Nation) duro, ki aiye ro gbogbo omo Yoruba lorun o.

    • @kehindejosephkashimawo9410
      @kehindejosephkashimawo9410 8 ชั่วโมงที่ผ่านมา

      @@moreadeyemo1630 Òdodo ni.. Kò si irọ́ ńbẹ̀.. A ò lè máa bá lọ báyì.. Rárá àti rárá..