Alejo to foru wolu to ntoka si saare baba afoju,, e ti mo wipe o lowo onile ninu.. Bee ni oro awon Fulani se ri ni ile Yooba.. Ko yo Aare Tinubu gan funra alara won nibe.. Nitoripe won gba opolopo nkan laaye lEko ti awon ajeji n we ile je fun omo onile ni Eko.
Ara ohun ti emi o faramo ni isinmi ayajo ojo isese ti ijoba ya soto yii.abosi lasan ni mo ri sii. Idi ni pe, Musulumi n se asepo odun,beeni kiriyo naa n se ase papo odun bee naa. Sugbon n je ti,awon onisese ri bee bii? Sugbon ti ijoba ba fe fun wa ni ayajo ojo ise tooto,a je wipe ise si ku fun won lati se,ise nla si ni pelu. Ti gbogbo wa ni isese
Òpìtàn gidi n'iyin, Ààrẹ Laji Abass, ṣugbọn báwo ní IFÁ se máa sọ wípé, ki ọmọ Yorùbá o ṣe imọle, ti quran o si sọ pe ki ọmọ lárùbáwá o di ònífá. Irọ nlá gbà ni ko si imọlẹ ninu IFA
That's what any African spirituality, religions or esin ibile supreme to all other imported religions. Olodumare is not a jealous god, there's no there's no other Olodumare before me, or thou shal not worship other deity before me.
Odu Ifa on Islam never advised Omo Yoruba to practice Islam. But the archival aspect it recognized Islam as a system of belief and which still nullifies Ogbomosho Imam’s proposition that Islam is isese more than Yoruba isese. Why? It is earlier belief that can talk about the later one, particularly at its arrival. Besides, Islam practitioners only need to tone down wanting to validate their beliefs by downplaying the beliefs of others. I think this is what brought about the controversy sparked by the Imam.
Aare Opitan, the amalgamation of Yoruba Nation with other nations in Nigeria is the problem that is taking away our culture and traditions from us. The problem cannot be solved as long as we are still in the contraption of Nigeria.
Aaaree, agbe fun yin lori itan Sugbon e mu enu kuro lori ifa….if ifa should talk about Imole truly that means awon omo babalawo to di musulumi ni won mu ese yen wo inu ifa…. My question for you is that…who started the story that Oduduwa is from Mecca? Awon musulumi ko ni?
Kii se ejo won. Part-time yoruba ni gbogbo awon to tabuku iran yoruba. Muslim to ba ntabuku nkan ile yoruba, Part- time yoruba ni onitohun. Christian to ba ntabuku nkan ile yoruba, Part- time yoruba ni onitohun.
May Almighty Allah bless you and your generation
Great job 👏👏👏👏
Kii Aare Opitan Pe Fun Wa La'Aiye❤
May God increase you in knowledge. You're well versed in Yoruba history, religious history & general knowledge. Being a Muslim is an added advantage.
Sedandan ni kiajojowa pelu fulani ni yoruba nation no going back ni eku eto sir❤❤❤
Gbefun baba oloye nla worldwide
Logunòfé ooooo i don miss you are welcome sir✌️🕊️👑
Ekujo meta sir emowa daada ati gbogbowa na Amin odaro sir 🙏💯💖💯❤
Hmmm allahu akbar 🔥
I miss you 💖 sir
Eku ishè baami
Olohun koni pada biznllah 🙏
Ayige gan ni a n pe agege teletele..Oluko agba.. koda adugbo to n je be si n be titi di oni
Iyì kìí kú mọ́ ataare nínú, iyì yín kò ní dìbàjẹ́ lásẹ Òdùmàrè
Alejo to foru wolu to ntoka si saare baba afoju,, e ti mo wipe o lowo onile ninu.. Bee ni oro awon Fulani se ri ni ile Yooba.. Ko yo Aare Tinubu gan funra alara won nibe.. Nitoripe won gba opolopo nkan laaye lEko ti awon ajeji n we ile je fun omo onile ni Eko.
Ara ohun ti emi o faramo ni isinmi ayajo ojo isese ti ijoba ya soto yii.abosi lasan ni mo ri sii.
Idi ni pe,
Musulumi n se asepo odun,beeni kiriyo naa n se ase papo odun bee naa.
Sugbon n je ti,awon onisese ri bee bii?
Sugbon ti ijoba ba fe fun wa ni ayajo ojo ise tooto,a je wipe ise si ku fun won lati se,ise nla si ni pelu.
Ti gbogbo wa ni isese
Talking drum naa lo pelu e fa.
"Ilu tii s'oro".ko si ilu kan ti n soro ni gbogbo aiye ju ilu wa lo
Òpìtàn gidi n'iyin, Ààrẹ Laji Abass, ṣugbọn báwo ní IFÁ se máa sọ wípé, ki ọmọ Yorùbá o ṣe imọle, ti quran o si sọ pe ki ọmọ lárùbáwá o di ònífá. Irọ nlá gbà ni ko si imọlẹ ninu IFA
That's what any African spirituality, religions or esin ibile supreme to all other imported religions. Olodumare is not a jealous god, there's no there's no other Olodumare before me, or thou shal not worship other deity before me.
Odu Ifa on Islam never advised Omo Yoruba to practice Islam. But the archival aspect it recognized Islam as a system of belief and which still nullifies Ogbomosho Imam’s proposition that Islam is isese more than Yoruba isese. Why? It is earlier belief that can talk about the later one, particularly at its arrival. Besides, Islam practitioners only need to tone down wanting to validate their beliefs by downplaying the beliefs of others. I think this is what brought about the controversy sparked by the Imam.
Baba emenu kuro loro ifa, oro ifa koja itan, emamu ifa mo islam, emu enu kuro nibe.
Aare Opitan, the amalgamation of Yoruba Nation with other nations in Nigeria is the problem that is taking away our culture and traditions from us. The problem cannot be solved as long as we are still in the contraption of Nigeria.
Eku ise ooooo l
O n se firifiri diedie.. E ku ise opolo
Aaaree, agbe fun yin lori itan
Sugbon e mu enu kuro lori ifa….if ifa should talk about Imole truly that means awon omo babalawo to di musulumi ni won mu ese yen wo inu ifa….
My question for you is that…who started the story that Oduduwa is from Mecca?
Awon musulumi ko ni?
When was Islam born ??? And when was IFA ??? Awon omo ale eru larubawa -Awon Oloriburuku ti wan fe je ogunkogun
Se a ma bere.
Ti a ba taa,ki a ma a too o
Ti won ba kii ifa islam etutu wo lon se si.