Shame on Nigeria government has they withdrawn history from Nigeria education… All thanks to almighty Allah that raised someone like Aare Opitan tile Yoruba who opened our eyes 👀 by giving us back to back history "Warafa'anaahu makaanan Aliyya" to Aare Laji Abbas. Watching from Dubai
Thank you for the message.its an eye opener.for us and our next generation never to allow Fulani or any foreigners to take over Yorubaland. God bless Yorubaland and God bless you all.
Olóyè Ààrẹ Òpìtàn, ẹ ó pe fún wa o... Olódùmarè a jẹ ki ẹ jèrè ilẹ̀ Yorùbá àti èmi náà. Ìtàn yí tiẹ̀ jẹki ń mọ pe bàbá mi ẸLẸ́RÌN náà kópa nínú ogun Otefon.
Laji Abass, àrẹ òpìtàn ilẹ̀ Yorùbá, ẹ kú oriire ọjọ́ ìbí yín. Ẹ ṣeun, ẹ kú akitiyan yín láti máa fi ìtàn gbé àṣà àwa ọmọ Yorùbá káàkiri àgbáyé ní arugẹ.. Olódùmarè á máa bùkún fún yín ní gbogbo ọ̀nà. Lágbára Ọlọ́run alààyè, ÀTÈMI, ÀTẸ̀YIN àti gbogbo olólùfẹ́ àṣà àti ìṣe orílẹ̀ èdè wa laó wà ní àlàáfíà ara pẹ̀lú ÌDÁNILÓJÚ ÀṢẸ ÌRỌ̀RÙN OLÓDÙMARÈ ẸLẸ́DÀÁ WA. A Ó lè máa gbé ìgbé ayé tó dára pẹ̀lú àṣẹ Èdùmàrè jù báyìí lọ láìpẹ́ láìjìnà lórílẹ̀ èdè Olómìnira wa Yorùbá nation. ÀṢÈYÍṢÀMỌDÚN, ÀṢÀMỌDÚN ṢẸ̀Ẹ̀MÍÌN fún yín o láṣẹ Èdùmàrè Ẹlẹ́dàá wa ÀMÍN.
Alhaji Agba Orun rere, won ni Eda yiowu to nse rere laye , ti won nse epe fun.Ise owo lo ma se Adhua fun.Beni eda yiowu to nse ika ti aye nse Adhua fun,ise owo Oluwo lo ma se epe fun titi aye.
Mufti Iwo fe fulfil agenda awon Fulani ijosi ni, to ni ki awon Emirs wa replace awon Oba ile Yoruba !!! Murfti Iwo shild be terminated before it is too late ! 😊
He need to come out and apologize for saying what he said if he's a true Muslim leader. Fanatical Islam is a problem everywhere, and they get so noisy to the point they overwhelmed the moderate. And you are right Aare Opitan, even the majority moderate Northern Muslims are afraid nowadays. Recently they even kidnapped a leaders near Sokoto and killed him.
Emi ko mo ohun ti o n da amu awon olori i wa, se ka wa wi pe ijo eleya ni kan ni o ye ki won ma a jo kiri ni? Gbogbo won fi ina si ori orule won wa n han oorun. Sio!
I enjoyed every bit of OGUN OTEFON God bless u sir
God restore the Glory of Yoruba land 🙏
Abass the legend in Yoruba heritage
Bi Mufty Iwo se bati Imam Ogbomoso je niyen
😂
Shame on Nigeria government has they withdrawn history from Nigeria education… All thanks to almighty Allah that raised someone like Aare Opitan tile Yoruba who opened our eyes 👀 by giving us back to back history "Warafa'anaahu makaanan Aliyya" to Aare Laji Abbas. Watching from Dubai
Thank you for the message.its an eye opener.for us and our next generation never to allow Fulani or any foreigners to take over Yorubaland. God bless Yorubaland and God bless you all.
Olóyè Ààrẹ Òpìtàn, ẹ ó pe fún wa o... Olódùmarè a jẹ ki ẹ jèrè ilẹ̀ Yorùbá àti èmi náà. Ìtàn yí tiẹ̀ jẹki ń mọ pe bàbá mi ẸLẸ́RÌN náà kópa nínú ogun Otefon.
Itan baba itan, thank you for the concluding part of Ogun Otefon.
Laji Abass, àrẹ òpìtàn ilẹ̀ Yorùbá, ẹ kú oriire ọjọ́ ìbí yín. Ẹ ṣeun, ẹ kú akitiyan yín láti máa fi ìtàn gbé àṣà àwa ọmọ Yorùbá káàkiri àgbáyé ní arugẹ.. Olódùmarè á máa bùkún fún yín ní gbogbo ọ̀nà. Lágbára Ọlọ́run alààyè, ÀTÈMI, ÀTẸ̀YIN àti gbogbo olólùfẹ́ àṣà àti ìṣe orílẹ̀ èdè wa laó wà ní àlàáfíà ara pẹ̀lú ÌDÁNILÓJÚ ÀṢẸ ÌRỌ̀RÙN OLÓDÙMARÈ ẸLẸ́DÀÁ WA. A Ó lè máa gbé ìgbé ayé tó dára pẹ̀lú àṣẹ Èdùmàrè jù báyìí lọ láìpẹ́ láìjìnà lórílẹ̀ èdè Olómìnira wa Yorùbá nation. ÀṢÈYÍṢÀMỌDÚN, ÀṢÀMỌDÚN ṢẸ̀Ẹ̀MÍÌN fún yín o láṣẹ Èdùmàrè Ẹlẹ́dàá wa ÀMÍN.
Mansa allah ❤
Aare, ejowo e ma gbagbe lati pari ogun Ilorin ti Alaafin Oluewu ati Eleduwa ti ku si oju ogun.
He has finished it already
Amugbo bi Oluwo ni ogbeni mufti iwo yen. Oro e ko jomi loju rara. Adeleke gbodo caution oun ati Rashidi oluwo.
A petition should be written against the Mufti of Iwo to the DSS and the police HQ in Abuja.
Onibode of our time
Alhaji Agba Orun rere, won ni Eda yiowu to nse rere laye , ti won nse epe fun.Ise owo lo ma se Adhua fun.Beni eda yiowu to nse ika ti aye nse Adhua fun,ise owo Oluwo lo ma se epe fun titi aye.
Excellent research and good job 👏👏👏👏👏
More strength 🙏
Alhaji e ku ise
Edakun se Ogun ati Sango pelu Orunmila jo lo igba ni ?
Mufti Iwo fe fulfil agenda awon Fulani ijosi ni, to ni ki awon Emirs wa replace awon Oba ile Yoruba !!!
Murfti Iwo shild be terminated before it is too late !
😊
Oba kiipe meji lafin
Aare opitan gbogbo agbaye kaafata
Eku eto sir
He need to come out and apologize for saying what he said if he's a true Muslim leader. Fanatical Islam is a problem everywhere, and they get so noisy to the point they overwhelmed the moderate. And you are right Aare Opitan, even the majority moderate Northern Muslims are afraid nowadays. Recently they even kidnapped a leaders near Sokoto and killed him.
Aare opitan
Olorun yoso agbara dotun Amin kunfayakun
Emi ko mo ohun ti o n da amu awon olori i wa, se ka wa wi pe ijo eleya ni kan ni o ye ki won ma a jo kiri ni? Gbogbo won fi ina si ori orule won wa n han oorun. Sio!
❤❤❤
Esé o
Dancing Jackson, please arrest mufti taliban of iwo