L'óòótọ́, Iragbiji l'èmi àti Tinubu ti mọ'ra sùgbọ́n...- Sen. Kola Ogunwale

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 19 ต.ค. 2024
  • Apá kinni ọ̀rọ̀ tí Sen. Kola Ogunwale sọ nípa ìbẹ̀rẹ̀ ìgbé ayé rẹ̀, bó ṣe mọ Olóyè Obafemi Awolowo àti Bola Ahmed Tinubu rèé…

ความคิดเห็น • 1

  • @lolasobande8663
    @lolasobande8663 ปีที่แล้ว

    Huuuuuuuuun, Senator ti s'oro s'agbon.
    Senator ta bi ni 1949, to je bi omo odun 74 npe Asiwaju to je omo odun 71 ni buroda. "Buroda Lamidi"! Ijinle oro ni eleyi, o.
    Ati pelu, eni akoko to jewo wipe ohun mo igba ewe Asiwaju re.
    E jowo, onirohin, ibi ti e pari foran yi si l'ewu, o. E ti fi to wa l'enu wo; afi ki e pari e sibi to l'apere. ILU wo gan ni Senator ati Asiwaju ti jo se ewe?
    Baba Senator, ke pe, o. Mo s'akiyesi owo Olorun l'ara yin. Eyi lo nmu yin se konge awon eni oke ti won nfa yin goke. Awon ti a npe ni OLURANLOWO AYANMO. Itan yin kun arikogbon ati koko adura.
    Oluwa yoo l'ora emi yin, o. Ki e ri ILERA lo igba yin to ku l'oke erupe.
    Onirohin, you're a first class interviewer. You're so unobtrusive; allowing d subject to stay in d limelight. You're invisible and hardly audible. Asabe needs a tutorial from you. GBOSAS to you!