What about South and North Sudan did separation help them? Until we are able to get rid of the evil in our hearts and teach our children to love themselves, no progress can happen in any black nation
@empresskofoworola You can't compare Sudan with Nigeria, Nigeria is a union of bondage and none of the regions have the same culture and tradition identity,that is why the there's no progress.
Iwa Keni mo ni lon da wa lamun, ani lo itusile lowo awon ajogun ibi to n gbe inu wa. Ti eniyan ba ti wa ti kofe ki ara ile re ose orire, ara ita yio fi orire ara ile se ifaa je
1930 ni bàbá Adesoji Aderemi jẹ Ọni, tí wọ́n waja ni 1980.. Mo mọ̀ wípé ẹ ṣihùn ni Ààrẹ Òpìtàn. Ẹ̀yin gan tí sọ rí.. Àwòrán kan wà tí Ọba Adesoji Aderemi (nigbati ọ́ wá ní Ọọ̀ni Ifẹ̀) bọ Siir Winston Churchill Prime Minister Britain lọwọ́.. Winston Churchill so ni olori ijoba, Prime Minister ni igba ogun World War 2 - 1937 sí 1945.
Oto le so Aare, won fun fun pelu imu gogoro. Exactly bi iya mi se ma so itan awon ebi won ni niyen, they migrated to Oyo-ile from North Africa long time ago. 1:16:59
Babaláwo kan tiẹ̀ jáde ó ní Egypt ni Ọ̀runmila tí wá. Ibeere mi ni pé, ṣe gbogbo odù ifá yẹn náà wá láti Egypt?? Ṣé èdè àwọn ará Egypt ni "Ọ̀runmìlà". Ó tun wípé inú omi ni Orunmila tí jáde.. Èèyàn jáde láti inú omi .. Kí ló wa ń wá kiri?? Ọ́ wá nínú BBC Yorùbá.
It is a pity that self interest of some individuals want to override the interest of a people, race or tribe, the way they speak on national matters, and issues that concern the lives of average Nigerian.
OMG
I too much respect this Man
You're a yoruba heritage that needs to be preserved
Keep it up Sir
Egbetokun was my cousin yet we can't reach him, hnmmmm yoruba shaaaaaa
I WILL PARTICIPATE IN BUILDING HISTORY SCOOL IN. YORUBA LAND...LAJI ABASS..YOU ARE JUST WONDERFUL THANK YOU SIR
Gbé fún Ààrẹ̀ òpintán
Ẹ kú ètò ìlànìlọ̀yẹ̀ òòò
Ẹ̀kọ́ pọ̀ọ́ nínú ìtàn ayé
Yoruba nation ni onan abayo baba tinubu ni owa lori oye
What about South and North Sudan did separation help them? Until we are able to get rid of the evil in our hearts and teach our children to love themselves, no progress can happen in any black nation
@empresskofoworola You can't compare Sudan with Nigeria, Nigeria is a union of bondage and none of the regions have the same culture and tradition identity,that is why the there's no progress.
@@empresskofoworolatvtill when o jare?
ONIBODE YORUBA NATION HOW DO YOU KNOW ALL THIS CLUMSY HISTORY....THAT IS YOU ARE ONE OF RECANATION PEOPLE..THANK YOU FOR COMING BACK.
You nailed it Sir
Just my thought too
Iwa Keni mo ni lon da wa lamun, ani lo itusile lowo awon ajogun ibi to n gbe inu wa. Ti eniyan ba ti wa ti kofe ki ara ile re ose orire, ara ita yio fi orire ara ile se ifaa je
Great job Aare opitan👏👏👏👏
1930 ni bàbá Adesoji Aderemi jẹ Ọni, tí wọ́n waja ni 1980.. Mo mọ̀ wípé ẹ ṣihùn ni Ààrẹ Òpìtàn. Ẹ̀yin gan tí sọ rí.. Àwòrán kan wà tí Ọba Adesoji Aderemi (nigbati ọ́ wá ní Ọọ̀ni Ifẹ̀) bọ Siir Winston Churchill Prime Minister Britain lọwọ́.. Winston Churchill so ni olori ijoba, Prime Minister ni igba ogun World War 2 - 1937 sí 1945.
Oto le so Aare, won fun fun pelu imu gogoro. Exactly bi iya mi se ma so itan awon ebi won ni niyen, they migrated to Oyo-ile from North Africa long time ago. 1:16:59
You are right,Ile eko ni itan Yoruba looto.Onibode, carry go.You are highly explanatory indeed.More power to your elbows.Kudos.
Eseun pupọ, Aare opitan ❤❤❤
AREE OPITAN ILE YORUBA NILE LOKO ATI LEYIN ODI KAAFATAA EKUISE OPOLO MAY GOD CONTINUE TO PROTECT YOU AND YOUR FAMILY AMEN
Nko mo pe Ojutole lo n korin yen sha...o kare lae
Se asa yi kole sese mon pada ni asayi lori oni oore monba ati ri ransesi oba oyo alafin ati oba binni se ko le se tomon pada ni
Bíbélì gan sọ pé Abraham moved from "Ur of the Chaldeans".
Keep telling them so they will yield and do the right thing.
Babaláwo kan tiẹ̀ jáde ó ní Egypt ni Ọ̀runmila tí wá. Ibeere mi ni pé, ṣe gbogbo odù ifá yẹn náà wá láti Egypt?? Ṣé èdè àwọn ará Egypt ni "Ọ̀runmìlà". Ó tun wípé inú omi ni Orunmila tí jáde.. Èèyàn jáde láti inú omi
.. Kí ló wa ń wá kiri?? Ọ́ wá nínú BBC Yorùbá.
ode ma ni yen
Aare opintan,Gbefun!
Gbefun ❤❤❤
It is a pity that self interest of some individuals want to override the interest of a people, race or tribe, the way they speak on national matters, and issues that concern the lives of average Nigerian.
Gbefun !!!
Sir, I think you are mixing Assyria, Persia with Pharisee. I think you mean to say Assyria, Persia, not Pharisee
Farisi, not Pharisee, is/was an Iranian language. He is using this to describe the people
@@Topdigitc noted sir, thanks sir
sir but you talk sense
Gbé fún Ààrẹ̀ òpintán
Ẹ kú ètò ìlànìlọ̀yẹ̀ òòò
Ẹ̀kọ́ pọ̀ọ́ nínú ìtàn ayé