Aare Ona kakanfo Samuel Ladoke Akintola demonstrated wipe akin ni oun loju ogun. Nijo ti awon army koju re ni January 15th 1966. Beeni Aare Ona kakanfo Moshood Kashimawo Abiola ko sa loju ogun nigbati oro election sele ti awon army Nigeria da oju ija ko.
Òtító ni òrò Ààre Láájí Àbàss. Nítorípe Iran Onpetu ni Ijeru l’Ogbomoso ní Benjamin Adekunle ni o fi ko oye Ààre-Onakakanfo lati je, nitoripe, omo-oba kii ja’gun bí eru.
Great historian with proof, evidence, facts and figures about the title holders in Yoruba history.Sir,forge ahead with what God has endowed you with.See something,say and speak out something.
Are,o ye nwon, sugbon nwon Fe da nkan ru ni,nitori nkan ti nwon nri gba lowo ijoba. Personal ambition Gani Adams ati awon ole ti o ntelee. As a matter of fact,o ye ki Baba wa,eni nla laarin awon Oba, Alaafin Adeyemi so gbogbo nkan ti o ro mo oye Kakanfo fun Gani Adams,his jurisdiction and boundaries. I think it was the old rift between Alaafin ati Ooni that brought about the return of Kakanfo,who now believe through hear-says that he is so important and powerful to insult awon Oba wa. The space of Kakanfo should and will be thrown into oblivion,we don't need any Kakanfo in Yoruba land. What has he done to call himself higher than some Obas. He is just the head of the Federal Guard for the Alaafin. Ti man naa ti poju,kilode. We must not forget that S.L Akintola was conferred with the title of Kakanfo due to the rift between Alaafin Adeyemi 1 and Awolowo, history repeated itself again. We don't want unrest and problem in Yorubaland again o.
Too arrogant and pompous. There's nothing wrong for a human being to be ambitious but you have to live and measure up to the standard. In his own case, the reverse is the case.
Onisokusọ gbaa ni Gbọ̀nka yẹn.. Kó máa fi Gani Adams wé MKO Abíọ́lá.. Abiola ti gbogbo aiyé.. To ṣe f'onílé to ṣe f'àlejò.. Tó gbounje f'ẹgbẹ́ gbà àwo ẹ̀ bọ̀.. Àbí SL Akintpọ́la, olórí ijoba (Premier) Akintọ́la baba lámilámi... Gani Adams kẹ̀.. Rárá o
Aare laaji abbas ododo Oro ni gbogbo ohunti eso yen wan tiko mokan lomanso isokuso orun ara wan ni wanfe gbo anu olohun koni fiyin sile ni oruko jesu oluwa wa
I’m very sorry to say this man only wants the merriment attached to this tittle but he has forgotten that it’s a call to service he should just stop destroying our history
Laji Abbas! Mo gbe fun ẹ jọ. You too much my brother. Gani Adams should be forced to drop the “Ibaa” title. That guy is disrupting Yoruba history for self elevation. Alafin made a big mistake in making him Kakanfo.
E seun Aare Opitan, baba adejumo is a disappointment for saying all the rubbish, we know Aare Gani Adams doesn't know anything and very arrogant but baba Adejumo really surprised me with all the rubbish that came out of his mouth.
Aree lajiabass otito oro pelu eeri to daju sakaa oju oni tiyin lagbara eledumare
Aare Ona kakanfo Samuel Ladoke Akintola demonstrated wipe akin ni oun loju ogun. Nijo ti awon army koju re ni January 15th 1966. Beeni Aare Ona kakanfo Moshood Kashimawo Abiola ko sa loju ogun nigbati oro election sele ti awon army Nigeria da oju ija ko.
What we have now is arealagbada
Òtító ni òrò Ààre Láájí Àbàss.
Nítorípe Iran Onpetu ni Ijeru l’Ogbomoso ní Benjamin Adekunle ni o fi ko oye Ààre-Onakakanfo lati je, nitoripe, omo-oba kii ja’gun bí eru.
Great historian with proof, evidence, facts and figures about the title holders in Yoruba history.Sir,forge ahead with what God has endowed you with.See something,say and speak out something.
Are,o ye nwon, sugbon nwon Fe da nkan ru ni,nitori nkan ti nwon nri gba lowo ijoba. Personal ambition Gani Adams ati awon ole ti o ntelee.
As a matter of fact,o ye ki Baba wa,eni nla laarin awon Oba, Alaafin Adeyemi so gbogbo nkan ti o ro mo oye Kakanfo fun Gani Adams,his jurisdiction and boundaries. I think it was the old rift between Alaafin ati Ooni that brought about the return of Kakanfo,who now believe through hear-says that he is so important and powerful to insult awon Oba wa.
The space of Kakanfo should and will be thrown into oblivion,we don't need any Kakanfo in Yoruba land.
What has he done to call himself higher than some Obas. He is just the head of the Federal Guard for the Alaafin. Ti man naa ti poju,kilode.
We must not forget that S.L Akintola was conferred with the title of Kakanfo due to the rift between Alaafin Adeyemi 1 and Awolowo, history repeated itself again. We don't want unrest and problem in Yorubaland again o.
Too arrogant and pompous. There's nothing wrong for a human being to be ambitious but you have to live and measure up to the standard. In his own case, the reverse is the case.
Aare Laji Abass, eku ise sir. Opolo yin koni doba lashe Edumare.
Are Opitan e ku ise o.
This is more of history of old Oyo empire.
Onisokusọ gbaa ni Gbọ̀nka yẹn.. Kó máa fi Gani Adams wé MKO Abíọ́lá.. Abiola ti gbogbo aiyé.. To ṣe f'onílé to ṣe f'àlejò.. Tó gbounje f'ẹgbẹ́ gbà àwo ẹ̀ bọ̀.. Àbí SL Akintpọ́la, olórí ijoba (Premier) Akintọ́la baba lámilámi... Gani Adams kẹ̀.. Rárá o
Aare opitan. Good job
Aare o! Itan baba itan. E ku'se Sir. Gbefun!
Aare, e ma play clip e mo jare.
Aare laaji abbas ododo Oro ni gbogbo ohunti eso yen wan tiko mokan lomanso isokuso orun ara wan ni wanfe gbo anu olohun koni fiyin sile ni oruko jesu oluwa wa
Ojuòrọlárí ni wọ́n.. Èyí tó ń pè ara rẹ̀ ni Ọlaniyọnu... Bí ọ̀rọ̀ wọn ṣe rí nìyẹn..
👏 a da fun yin. Be gan lori.
❤❤❤❤❤
I’m very sorry to say this man only wants the merriment attached to this tittle but he has forgotten that it’s a call to service he should just stop destroying our history
Anything I hear from you is final because no one has ever come out to challenge him since
AWON FULANI NYEYEWA LOJUJUMO KOLE SORO ODAKE MINIMINI BI OMI AMUN
KOYALO BO BATA KAKANFO KALE KOMA LOSI ODE ARIYA
Ko tun ku ti o so, eni ta be lori to tun jenu wuye, kilo tun ku ti o so.😂😂🎺🎷 Ki ni oko olori ayinba fe se si. Itan lo je logun.
Atiku PDP, logbe owo fún Gani Adams to fi ra oye Kakanfo lọwọ Alafin. Awọn fulani mọ game won play daada.