ONA ABAYO - YORUBA REFERENDUM PATHWAY

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 17 ก.ย. 2024
  • ''AJORO YORUBA'' ni akole eto l'oni pelu Alagba Femi Odedeyi ni ikale. Awon rogbodiyan to nlo l'owo ni a o ma s'oro re l'oni ati ONA ABAYO.
    Alaale Sunday ni deedee aago mejo l'eto l'ori Impact Radio/TV,. E o gbodo gbagbe

ความคิดเห็น • 2

  • @tyade7969
    @tyade7969 หลายเดือนก่อน +1

    Oloselu niyin e ye tan Awon eniyan wa je pelu ona abayo lori iro .
    Ki e ranti pe Olorun mbe loke lati se idajo gbogbo yin .

    • @oymediascotland2853
      @oymediascotland2853  หลายเดือนก่อน

      @@tyade7969 Alagba, oro oselu ni oro yi eyi ti awon eleyinbo n pe ni political matters. Ara awon asise ti Yoruba n se ni wipe imo wa ko to nipa ohun ti a n pe ni oselu beeni awon Ful*ni ati awon Ig*o mo eyi ju wa lo. Dida ilu sile, oro oselu ni. Titu ilu ka, oro oselu ni. Titun ilu to oro oselu ni. E dakun, e se alaye fun wa bi oro igbe inu Naijiria tiyin tabi gbigbe agbaiye ko se la oro oselu lo.