@@OYEOLOHUN_TV amin ase edumare, e maa mo se lase edumare. A ngbadun eto yin gidigidi. Ejowo e ma gbagbe ipinle ekiti naa o fun iforowanilenuwo yin o. Paapaa ipao ekiti ni abe ikole local government.
You ask a lot of uneccesarry questions. Your viewers are not learning how to be a hunter. Your viewers are interested in mysterious experiences and mysterious acts.
What did you know about the viewers? You just joined this channel? As a hunter we learned different things you don’t need to say it’s unnecessary questions if you don’t learn I do you can start yours thank you 🙏
Iwin is Yoruba word for spirit. They are everywhere. Some live in the forests, some underground, some in the air, some in the sea, some inside rocks. They are dimunitive creatures. They exist outside our human dimension and are invisible to us.
Hummm
Olohun koni pada leyin yin sir eku igbiyanju sir
Weldone my brother Oyeolohun
I trust you sir
Ekuse takun takun ooo Ọlọ́run ọba asanyin lesan rere
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ Ẹ̀gbọ́n mi, ọ̀dá itọ́ kìí dá ahọ́n, ọ̀dá ohun rere kòní da yín ✌️
@@OYEOLOHUN_TV àṣẹ wa
Hummm moma ngbadun yoruba enu yin ni gbogbo igba ni, olorun koni pada leyin yin sir
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ
Eku eto sir olorun ama funyin se
Thank God you give us today hope there's no problem sir
No problem, Thanks for the love
E ku eto. A ma juse fun yin o
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ ✌️
Weldone brother may God bless you for us
Amen and you too
Well done more blessing
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun
Long time my lovely brother hope there's no problem sir weldone o
Thanks there's no problem at all
Akú Ètò o" Ìtànná ògo gbogbo waa kòní wòòkùn Láse ÈDÙMÀRÈ .
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun Bàbá Arifọkanbalẹ
Eku eto sir olorun ama pa alo atabo yin mo
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ ✌️
Thanks God You are back !! We have missed you Oyeolohun. Welcome back sir.🖐️
Thanks sir, I really missed all of you too
Moki ku ojo meta o oye olohun tv
Ẹ seun ìyá mi daadaa ✌️
Eku eto sir olorun ama funyin se otojo meta sir ooo
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ ✌️
Ekaabo pada olotu, otojo meta . Se ko sinkan.
Kò sí laburu kí ó ba leè dára náà ni, Ẹ seun ẹ kú ìfẹ́ Olódùmarè lára wa, ẹran ìfẹ́ ara ti yín náà kòní di ẹran ikorinra
@@OYEOLOHUN_TV amin ase edumare, e maa mo se lase edumare. A ngbadun eto yin gidigidi. Ejowo e ma gbagbe ipinle ekiti naa o fun iforowanilenuwo yin o. Paapaa ipao ekiti ni abe ikole local government.
Eku eto sir olorun ama funyin se otojo meta o
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun kò sí irọ́ níbẹ̀ ✌️ọjọ́ kan pẹ̀lú
Oyeolohun Eku eto sekosi tope yin keto post sir ejeki a soro lori WhatsApp
Kò sí laburu sir, Ẹ seun ✌️
But the man is not talking like Yoruba.
His Yoruba is like igbira Yoruba
Dats dialect of Ibarapa side
You ask a lot of uneccesarry questions. Your viewers are not learning how to be a hunter. Your viewers are interested in mysterious experiences and mysterious acts.
What did you know about the viewers? You just joined this channel? As a hunter we learned different things you don’t need to say it’s unnecessary questions if you don’t learn I do you can start yours thank you 🙏
@@officialsimple3078Ẹ ma seun
Iwin?? There’s no such thing baba… just stop!
Iwin is Yoruba word for spirit. They are everywhere. Some live in the forests, some underground, some in the air, some in the sea, some inside rocks. They are dimunitive creatures. They exist outside our human dimension and are invisible to us.
@@olurotimiadepitan5087 Wow… they are invisible to us but yet, you’ve seen them under the sea. Anyway, I need to meet one of those guys. I need money
Thank God I'm able to watch this program again. It take awhile before you post again please sir i need your number
08069316812 thanks for the love sir