Another powerful session... I love the question Oogun Inu riro Abere seed + Akogun + Dry gin is good for Ulcer. I Well done Oyeolohuntv and crew. Eledumare yoo ma pa alo ati abo yin mo. Amin❤
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, I trust you Ẹ̀gbọ́n Bastims, aramide lórúkọ ti a npe orita, akotagiri lórúkọ tí a npe ọna, tí afẹ́fẹ́ bá fẹ́ tigbo tiju ni fẹrinrin, ẹrin lọmọrunla nrin pade olóko, ẹrin logodo nrin pàdé alasẹri, gbogbo ibiti ẹ ba ti ńdé bayii, wọn a ma gba ti yin ni ooo, ọmọde a yọnu si yin, agbalagba a yọnu si yin, obinrin a yọnu si yin, ọkùnrin a yọnu si yin, ó rí bẹ́ẹ̀, ó ṣẹ bẹẹ ✌️
Ẹ seun ọ̀gá mi, mọ́tí letí nma mọ́rí, ọmú kò ní sin lọ láyà obìnrin láyé láyé, gbogbo adua yín ni yóò gbà lágbára lọ́wọ́ Olódùmarè, Ọba Asekanmaku. Ẹ seun ✌️
Yoruba kare.
Thanks ✌️
Please keep up this good work.Thank you
Ẹ seun
Omo agoro weldone my friend, Oni se lasan lagbara Olohun
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun ✌️
Very interesting program, keep it up sir
Thanks ✌️
First to gboriwole
Wow! Time is comming, just keep it up,your name has been wrote down, thanks ✌️
Nice program, I love your program sir, May God bless you and your generation 🙏
Amen
Hummm! Nice program
Thanks ✌️
Wish you success at the end sir, as you they promote our culture
Amen, Thanks ✌️
Wow! What a intelligent program 👌
Thanks sir ✌️
Well done sir !! What a nice program… May God continue to protect you and your crews as you go from one place to another. Love ur program so much.
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun sir, iwájú iwájú lọ̀pá ẹ̀bìtì ńré sí, iwájú iwájú lẹ yin naa yo ma lọ ✌️
Another powerful session... I love the question Oogun Inu riro Abere seed + Akogun + Dry gin is good for Ulcer. I Well done Oyeolohuntv and crew. Eledumare yoo ma pa alo ati abo yin mo. Amin❤
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, I trust you Ẹ̀gbọ́n Bastims, aramide lórúkọ ti a npe orita, akotagiri lórúkọ tí a npe ọna, tí afẹ́fẹ́ bá fẹ́ tigbo tiju ni fẹrinrin, ẹrin lọmọrunla nrin pade olóko, ẹrin logodo nrin pàdé alasẹri, gbogbo ibiti ẹ ba ti ńdé bayii, wọn a ma gba ti yin ni ooo, ọmọde a yọnu si yin, agbalagba a yọnu si yin, obinrin a yọnu si yin, ọkùnrin a yọnu si yin, ó rí bẹ́ẹ̀, ó ṣẹ bẹẹ ✌️
@@OYEOLOHUN_TV Ase Edumare... Ese modupe pupo 🙏🙏💕
A ngbadun yin olorun a fi ire fun yin sir, thank you for the medicine sir
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun ✌️
Agbo ato o....
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ ✌️
Thanks for the medicine, may God continue to be moving you forward sir
Amen, Thanks ✌️
Job well done olotu, I like the way you always show the pictures of the animal. May God continue to supportu you
Àṣẹ wàá báyìí niti Ìrèké, Ẹ seun, ẹnikan kìí fi gọgọ ká Ìgbá èsí, gbogbo èrò aburu ọ̀tá kò ní ṣẹ leyin lórí ✌️
@@OYEOLOHUN_TV ase edumare
Thanks sir, May God continue to be moving you forward sir
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Odò toba ti ń ṣàn lọ kìí bojú wẹ̀hìn mọ́, gbogbo ìbànújẹ́ ayé yín yo ba omi san lọ, Ẹ seun ✌️
Respect baba mi
Ẹ seun ọ̀gá mi, mọ́tí letí nma mọ́rí, ọmú kò ní sin lọ láyà obìnrin láyé láyé, gbogbo adua yín ni yóò gbà lágbára lọ́wọ́ Olódùmarè, Ọba Asekanmaku. Ẹ seun ✌️
Eku ise opolo oo
Ẹ seun sir ✌️
Eku eto sir olorun ama funyin se o
I enjoyed this program, please give us more, thank you
Thanks ✌️
I trust you sir, you never disappoint us, nice interview may God bless your hustle ❤️
Amen, I really appreciate it ma, àsetì kìí bá ọjọ́ ki ọjọ ko ma yọ, aseti koni ba yin, thanks ✌️
Thanks so much .God will bless you 🙏❤
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun sir, Àbùdí ni tomi òkun, àbùdí ni tomi ọ̀sà, a kìí sá omi lọ́gbẹ́ kí a ri ipa rẹ, ẹ koni ranre owo ✌️
o ṣeun lọpọlọpọ
A dupẹ ✌️
Wow! You are improved every day sir, keep it up, this is an educative program 👌
Thanks my darling sister ✌️
Oye ọlọhun tv,ẹku isẹ . Ẹjọ ibere ka ni mo ni fún yín. Nje eran kan wà ti wọn pe ní amotekun? Nitori pe iwadi je ki n mọ pe, afi we ni.
Ẹ seun, ṣe ẹ ri amọtẹkun ti awọn eniyan npe ni amọtẹkun tẹlẹ hun? Ohun gangan ni ẹkùn tiwa nilẹ adulawọ.
@@OYEOLOHUN_TV kini ẹranko " cheetah" ni ede Yoruba?
Always in my heart ❤️ 💙 💜 💖 💗 💘 ❤️
Thanks sir ✌️💯❤️
Etun fi eto yi koniyan lede yoruba gidi adupe o
Ẹ seun sir ✌️
A gbadun eto yin yi o. Yo ma juse fun yin
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, àsetì kìí bá ọjọ́ ki ọjọ ko ma yọ, aseti koni ba ẹyin naa, Ẹ seun ✌️
A dupe sir olorun yo ma te yin siwaju
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, iwájú iwájú lọ̀pá ẹ̀bìtì ńré sí, iwájú iwájú lẹ yin naa yo ma lọ, Ẹ seun ✌️
Hummm! E seun fun ogun tie jeki won fisita yen, aisan koni fagoara gbogbo wa se ibugbe o
Aseoo
G😊😊😊
Ẹ seun ✌️
Olotu, when you mentioned egbin, I was expecting to see zebra picture. What is the yoruba name of Zebra
Zebra cannot be found in Africa no name for it same as tiger
@@charlesnoble9824 Thanks for Follow us back to back. Mr Idowu that's right answer sir. Thanks ✌️
Eku eto sir angbadun yin o Olodumare A jeki ema lo re kema bo re
Àṣẹ ooo, ẹyin naa ẹ kò ní rin lọjọ ti ebi ńpọ̀nà ooo. Ẹ seun ✌️
You did not show the telephone number of this man is not good
Bẹẹni ṣùgbọ́n oni reason, contact us on WhatsApp 08069316812
Please stop interrupting the people it's making your programs not interesting
Okay Noted. Thanks ✌️
Babas number
Contact us on WhatsApp 08069316812 to collect his number, thanks madam ✌️