Oloriburuku,, wèèrè ìnàkí ni wọ́n. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olóṣèlú àti Ọba wa.. Ṣebi àwọn oun tí Olóyè Sunday Ìgbòho nfẹ́ ṣe nígbà yẹn nìyẹn. Sugbon bàbá wa Ọ̀nirìṣà sọ ara wọn di errand boy fún Buhari pé kí Olóyè Ìgbòho dákẹ́...
A ò tiẹ̀ mọ oun tí baba wa Ọ̀nirìṣà ńṣe? Ṣùgbọ́n wọ́n mọ̀ bí wọ́n ṣe máa wá jiṣẹ́ Buhari fún Olóyè Sunday Ìgbòho pé kọ́ dákẹ́ lórí ọ̀rọ̀ Yorùbá Nation,,,. Ẹ wo Ààrẹ Gani Adams.. Ńṣe ni wọ́n dákẹ́..
In as yoruba still with nigeria n emir of ilorin still emir in yoruba land then aburu will continue to happened the only solutions is for yoruba to go their way security or obas or governor cant do anything the whole nigeria is in fulanis hand tinubu is jus figure head there
É jé bara wa sọ ootọ ọrọ , Aare Oke o lágbára lori ohun to nsele nile Yoruba
Kare Aarẹ, ọmọ ọkọ ilẹ Yoruba.
Laji abasi eo pe fun wa o
Oloriburuku,, wèèrè ìnàkí ni wọ́n. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olóṣèlú àti Ọba wa.. Ṣebi àwọn oun tí Olóyè Sunday Ìgbòho nfẹ́ ṣe nígbà yẹn nìyẹn. Sugbon bàbá wa Ọ̀nirìṣà sọ ara wọn di errand boy fún Buhari pé kí Olóyè Ìgbòho dákẹ́...
I agreed with you Aree.
AREE ONI BODE YOU ARE WELL COME SIR ❤❤❤🎉🎉🎉.
Nigeria kise ilu kosofin kan beni kinni fulani wa ninu igbo wa governor yi oye ki won soyin lokopa ni eyin oloribuku yi
AARE EKU ISE OLUWA ATUNBO MAA ROYIN LAGBARA OMASEO ERAN TIKU SILU AILOBE ORO YORUBA TOOTO
A ò tiẹ̀ mọ oun tí baba wa Ọ̀nirìṣà ńṣe? Ṣùgbọ́n wọ́n mọ̀ bí wọ́n ṣe máa wá jiṣẹ́ Buhari fún Olóyè Sunday Ìgbòho pé kọ́ dákẹ́ lórí ọ̀rọ̀ Yorùbá Nation,,,. Ẹ wo Ààrẹ Gani Adams.. Ńṣe ni wọ́n dákẹ́..
Ẹ ò gbọ́ bí, orí Ààrẹ Laji Abass pé ó kọjá bẹ́ẹ̀.
This is too bad, very painful 😢 what is wrong with our leaders?
Bi ko si ejo, bawo ni barrister lawyer she ma jeun
Its from ilorin they share n send them to diff yoruba lands with diff misions to bring yoruba down
In as yoruba still with nigeria n emir of ilorin still emir in yoruba land then aburu will continue to happened the only solutions is for yoruba to go their way security or obas or governor cant do anything the whole nigeria is in fulanis hand tinubu is jus figure head there
Another Yoruba Obs just got killed in kwara state by terrorists, wife and children abducted. Wahala ti sele o