ṢE NI WỌ́N DÁ OBA SEMIU OLÓRÍLÉ IFỌ̀ PADÀ S'Ọ́GBÀ Ẹ̀WỌ̀N LẸ́YÌN WÁKÀTÍ KAN TÓ GBA BÉÈLÌ

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 11 ก.พ. 2025

ความคิดเห็น • 37

  • @bosederachealomole3356
    @bosederachealomole3356 4 วันที่ผ่านมา +4

    E jowo e je ki Oba onigberaga yi se itoju baba yi daada o. Bi ogo ti n je ti Olorun, ko ye ki Oba yi pada si ori alefa mo rara.

  • @haynehifanny8006
    @haynehifanny8006 4 วันที่ผ่านมา +7

    Ki wọn le kúrò lorí itẹ, ki won si fi sì ẹwọn 73years.

    • @goldsilver545
      @goldsilver545 4 วันที่ผ่านมา

      O kare jare ejo gidi loda kan gbagbe e sewon

    • @ibro2306
      @ibro2306 3 วันที่ผ่านมา

      😂😂

  • @Mummytiobad55
    @Mummytiobad55 5 วันที่ผ่านมา +8

    I quite agree that the 73 year old man should be compensated!!!

  • @peterfernandez7511
    @peterfernandez7511 5 วันที่ผ่านมา +5

    Well done sir ,continue sir we're enjoying you ....

  • @sundayemmanuel703
    @sundayemmanuel703 3 วันที่ผ่านมา

    Lord is ur strenght

  • @abigaelshinkaiyw3182
    @abigaelshinkaiyw3182 3 วันที่ผ่านมา

    Is good to be good, whatever you do in life, is a matter of time it will come back like waves.

  • @adedoyinmojiogunba5654
    @adedoyinmojiogunba5654 5 วันที่ผ่านมา +4

    Always, My Favorite Person with Integrity, Decency and Honor. Thank you for your Human Services. God Bless you and the hands of your work. Amen ❤🎉

  • @olajumokeaworeni5882
    @olajumokeaworeni5882 5 วันที่ผ่านมา +12

    Se awon eeyan riipe Ooni of Ife seeyan rere. Aimoye eeyan lo nde iwaju Ooni ti won kii dobale. Kode nii soro sii rara. Kaabiyesi Oonirisa, k'ade pe l'ori o. Ase.

  • @abigaelshinkaiyw3182
    @abigaelshinkaiyw3182 3 วันที่ผ่านมา

    A ha se Dan Dan ni idobale ni

  • @adedapoadedokun1922
    @adedapoadedokun1922 4 วันที่ผ่านมา

    Baba Awikonko Ôlôrun Oba yio wa pelu yin o, awon alalê yio ma tubo fun yin se paapa July fun gbogbo awiyannu yin lori õrõ Yoruba...

  • @bosederachealomole3356
    @bosederachealomole3356 4 วันที่ผ่านมา +2

    IFA NI OUN FI PASAN AISODO NA GBOGBO AWON OBA TI WON FI OWO, AGBARA, POLITICS ATI. RITUALS EJE OMO ALAISE SE OGUN KI WON LEE JE OBA. Ki gbogbo eyin alagbara aye fi eyi se ari kogbon. O pe , o ya ewu ete naa ni alaseju yio gbe wo gbeyin.

  • @akintundekuye1840
    @akintundekuye1840 4 วันที่ผ่านมา +4

    Hello sir, why is only Kabiesi arrested? They should arrest others

  • @olabisiayodele3322
    @olabisiayodele3322 4 วันที่ผ่านมา +2

    Aye gba awon Oba ile yi opolopo won ni Ko ye nipo oba gbogbo eyin ti e gba baba yen leti ofo le ma se

  • @OmowonuolaHassan
    @OmowonuolaHassan 4 วันที่ผ่านมา

    Ifa ki mu oba mo nisinyi, politics ni won fin mu oba tabi ki oni toun ni owo lowo,ifa ki je obi,oti ati you ohun ibile mo sugbon owo bi dollars,Naira, pounce Starlin ni ifa nje laye isinyin, that's the reason ti awon oba fin wu iwa kiwa, sugbon olorun a ko wa yo o Amin

  • @AdenikeAdekanbi
    @AdenikeAdekanbi 4 วันที่ผ่านมา

    Eekabo Amin❤ it.

  • @abigaelshinkaiyw3182
    @abigaelshinkaiyw3182 3 วันที่ผ่านมา

    Hmmmmmmm ododo oro

  • @ayoolaolaniran9318
    @ayoolaolaniran9318 4 วันที่ผ่านมา +3

    He is now ogbeni and not oba or Kabiyesi because he is being suspended, no one should call him Kabiyesi for the next 6 month

    • @Bjcrypto545
      @Bjcrypto545 4 วันที่ผ่านมา +2

      No one should call him kabiyesi forever. He is not a king material
      .

    • @goldsilver545
      @goldsilver545 4 วันที่ผ่านมา +2

      He is extremely dangerous

  • @DareAgbaje
    @DareAgbaje 4 วันที่ผ่านมา +2

    Ni igba ti e ba ti fi amugbo Jo oba bi ti oluwo amu oba

  • @GABRIELADEPOJU-n8r
    @GABRIELADEPOJU-n8r 3 วันที่ผ่านมา

    Koye kobaye panda sipo MO lero temi koye loba

  • @nuridinadams9219
    @nuridinadams9219 4 วันที่ผ่านมา +2

    The baba, victim should demand compensation from the oba and Ifo royal families. Nothing more, nothing less. Again, the oba should be dethroned.

    • @biodunayinde9711
      @biodunayinde9711 2 วันที่ผ่านมา

      Public apology is better. No amount of compensation will be enough. The Oba should be dethroned. Compensation from a man with that kind of attitude.

  • @7Sinmi
    @7Sinmi 5 วันที่ผ่านมา +1

    Akandaaaaaa, seeing your show yesterday, with a grown man, naked on the ground was a shameful thing to our race, going viral on social media was very degrading, disgraceful and annoying. After all the Are Ola Abraham definitely has a Wife, Children, Families and Loved ones. Ki lo de, se Ogun laiye ni?, In fact, if he has power to give the World, rain and sun, this man will make the World tough. Well good luck to him.

  • @akanniadekunle3533
    @akanniadekunle3533 4 วันที่ผ่านมา

    i pity that town, the town cannot develop at all

  • @bosederachealomole3356
    @bosederachealomole3356 4 วันที่ผ่านมา

    Baba ti won fi iya je yi ni o ye ki won fi je oye ti o dara ni ilu yo, ki won si se itoju ati aponle re

  • @salamahsalamah9471
    @salamahsalamah9471 4 วันที่ผ่านมา +1

    This kabiyesi should be dealt with in accordance with the law of the land and must be expelled from the throne, because he is so dangerous to humanity,

  • @aremukehinde5400
    @aremukehinde5400 4 วันที่ผ่านมา

    Pls Sir can u go back to that how u use to do it in the past.Its more better sir.Just my take

  • @TheShakirat
    @TheShakirat 5 วันที่ผ่านมา +10

    Hmmmm his a bale not kabiyesi. He need to be sentence to prison with the man that slap the old man also to compensate the old man . Very silly, stupid arrogant bale.