O ṢẸLẸ! IJA TINUBU PẸLU OBI GBA ỌNA MI-IN YỌ

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 16 ต.ค. 2024
  • We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

ความคิดเห็น • 35

  • @bosejuliana7731
    @bosejuliana7731 3 หลายเดือนก่อน +12

    Abi oloriburuku ni gbogbo awon government wa yi ni, Olorun a ma mu yin, igbeyin yin ma buru ju ti Babangida lo ni oruko Oluwa.

    • @binaryworld4000
      @binaryworld4000 3 หลายเดือนก่อน

      Dey play, curse no go catch them😂

  • @oriyomiokunoye7772
    @oriyomiokunoye7772 3 หลายเดือนก่อน +4

    Huuum ijoba Nigeria eti baye je gaaan ooooooo

  • @olamilekanfabunmi1676
    @olamilekanfabunmi1676 3 หลายเดือนก่อน +4

    Iya njewa ni Nigeria 🇳🇬 😢 😢😢😂😂😂
    Olori buruku ni ijoba Nigeria 🇳🇬 😢 😑 😅

  • @OladejiIsmail-sk3hi
    @OladejiIsmail-sk3hi 3 หลายเดือนก่อน +3

    Eku ibaje ooooo eyin oloriwa

  • @godwinjames4477
    @godwinjames4477 3 หลายเดือนก่อน +6

    Awon oloriburuku president

  • @olamilekanfabunmi1676
    @olamilekanfabunmi1676 3 หลายเดือนก่อน +5

    Ododo oro ni obi so
    Olori buruku ni ijoba Nigeria 🇳🇬 😂😂😂😂😢😢😢😢

    • @meritnoah4013
      @meritnoah4013 3 หลายเดือนก่อน

      The parents true true brother love you bro obi is parent

  • @kayodeakanbi1188
    @kayodeakanbi1188 3 หลายเดือนก่อน +2

    Wankise Eni-Olohun Ija Olohun nbo loriwan oju lopesi Idajo Olohun detan,Eloma amodaju pe ni ojo Idajo gbogbo omo Nigeria konidarijiyin fire to fire ni Ile gbogbo wan yiodarisi IDAJI deetan

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 3 หลายเดือนก่อน +1

    🤓 Erin awon eniyan ijoba emi lokan pami.... Olorun ema Ku suru o

  • @aladjimoustaphaiguewassiou9576
    @aladjimoustaphaiguewassiou9576 3 หลายเดือนก่อน +2

    Ododo ọrọ kò le tán ni ẹnu OBI ọlọrun ọba ni kan ni yóò gbé dé ipò tí wọ́n jaa lole,peter obì kò sí nínu awọn obilẹjẹ,, oriburuku bẹrẹ lati ọdọ Tinubu titi lọ dori gbogbo awọn tí won wa nínú ìjọba rẹ,,kò sí ní rágbá fún gbogbo àwọn ti o n gbija Tinubu,,

    • @meritnoah4013
      @meritnoah4013 3 หลายเดือนก่อน

      Amin asee brother miii one love

  • @sussanahogunbo6681
    @sussanahogunbo6681 3 หลายเดือนก่อน +4

    SE AWON OKO BALU NA KO SE TUNSE NI ABI DANDAN NI KU WON RA OMIRAN PELU EBI TO NPA WA YI ISE OWO OLUKALUKU NI YIO JERE YIO SI SESE FUN GBOGBO WA AMIN

  • @sekinatsalami487
    @sekinatsalami487 3 หลายเดือนก่อน +4

    Gbogbo yin ni Olorun ma San lesan toba yeyin adabi toba jepe ajo ni Nigeria ko loku.

  • @kemoblunsky3794
    @kemoblunsky3794 3 หลายเดือนก่อน +2

    Ati Obi o, ati Tinubu o, ati gbogbo eyin oloselu Nigeria, ka kool fun gbogbo yin, aye gbogbo yin ko ni ni itumon ko da be lowo ju karuna lo, eyin eleribu gbogbo, okan gbogbo eyin obayeje oloselu Nigeria ko ni ba le, aisan lo ma kpai yin.

    • @reusamanda9758
      @reusamanda9758 3 หลายเดือนก่อน +1

      What bad did Obi do to you?

    • @meritnoah4013
      @meritnoah4013 3 หลายเดือนก่อน

      Obi is not president yet so brother jee karooo daadaaa

  • @olabisiayodele3322
    @olabisiayodele3322 3 หลายเดือนก่อน +1

    Ofo le ma se pelu ori buruku oro ti Ona nuga so yi ole ni gbogbo won

  • @ismailabidemi1184
    @ismailabidemi1184 3 หลายเดือนก่อน +2

    Oloribu ni gbogbo se dandan ni awon na jade ni ilu nani se won kole dura sile kini won waka kiri

  • @lukmanagbagbe631
    @lukmanagbagbe631 3 หลายเดือนก่อน

    Hmmmmmmm Nigeria

  • @olabisiayodele3322
    @olabisiayodele3322 3 หลายเดือนก่อน +1

    Oju Tinubu yi gan o da rara ti gbogbo e ti we sita yi

    • @meritnoah4013
      @meritnoah4013 3 หลายเดือนก่อน

      😮😮😮😅😅 brother miii kiletun so yiii ooo nibo latun jasii bayii oo

  • @RazeedAyinki
    @RazeedAyinki 3 หลายเดือนก่อน +1

    Olorun osaun wa Amin oooooooooo

  • @ogunrindeadebisi
    @ogunrindeadebisi 3 หลายเดือนก่อน +3

    Oro GIDI ni PETER OBI SO OOO, IJOBAA TINUBU BOLA HAMEED IJOBAA OFOO NI , AWON OLORIBURUKU NI GBOGBO WAN , NIORUKO JESU ATI YIJOBA BUHARI ATI IJOBAA TINUBU BOLA HAMEED, GBOGBO YIN LEMAASOFO TOMOTOMO NIOOO HAAÀ, GBOGBO YI NA LEMATOJU ORUN DOJU IKU TELETELE , AFI TIE BARITI MEKUNNU RO OOO , BENI OOO.

  • @ArisekolaOtesuku
    @ArisekolaOtesuku 3 หลายเดือนก่อน

    Ogaoo

  • @OyeyemiSalau
    @OyeyemiSalau 3 หลายเดือนก่อน +1

    Owo olorun ato Gbogbo won
    Gbogbo won ni olorun ma kolu

  • @heleno1327
    @heleno1327 3 หลายเดือนก่อน +1

    Ki ni won nwa kakiri ole ni gbogbo won olorun amu gbogbo won Ishallau

  • @sussanahogunbo6681
    @sussanahogunbo6681 3 หลายเดือนก่อน +2

    ALAROYE E SE E KU OHUN YIO MA JU YIN SE FUN OLOPOLO PIPE ENIA SE KI I SE ORO GIDI NI OBI SO YI NI ABI BI EBI SE NPA ARALU YI KO KAN IJOBA YI NI O MASE O OLORUN A GBA ISAKOSO ORO MEKUNNU NI NIGERIA YI O YIO SI DARA FUN WA LASE COLORUN

  • @mariamasie9329
    @mariamasie9329 3 หลายเดือนก่อน

    Olorun esan lo fi Tinubu se pasan fun won, Sebi Sowore ni ema ma bu,ki Olorun wa pelu Omoyele Sowore.

  • @AderomosesundayAdeseje
    @AderomosesundayAdeseje 3 หลายเดือนก่อน

    Ko ye irandiran Onanuga o n pe ki gbogbo yin to ja ku Igba ti e ja ku kini e se

  • @moshooduthman1243
    @moshooduthman1243 3 หลายเดือนก่อน

    Okay 😒

  • @Oodua-ii
    @Oodua-ii 3 หลายเดือนก่อน

    You where voted to fix your nation, not to be galavanting all over the place.

  • @OladejiIsmail-sk3hi
    @OladejiIsmail-sk3hi 3 หลายเดือนก่อน +1

    Eku ibaje ooooo eyin oloriwa