IDI T'IJỌBA UK KO ṢE GBA ẸBẸ SUNDAY IGBOHO LATI NI YORUBA NATION NIYI O

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 17 ต.ค. 2024

ความคิดเห็น • 20

  • @ArabinrinOyindamola
    @ArabinrinOyindamola 7 ชั่วโมงที่ผ่านมา +4

    Wonti ge asake awa omo oko yoruba leti lo nitoripe Sunday igboho koni oran rare nise 😮,, awa omoko yoruba ni aran nise fun idi eyi yoruba nation no going back
    We love yorubas 😍😍😍
    We love chief Sunday adeniyi adeyemo igboho osaaaa ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️

  • @omoyelesamson2150
    @omoyelesamson2150 5 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    Iro ni ijoba Nigeria n pa. Won gbà iwr náà wole, sugbon won o tii fesi.

  • @adedejitaofeeq2472
    @adedejitaofeeq2472 4 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Nkanla, ibi to yee ki aaba ogbon ti ababa ago, ikan yan. Yoruba ti amo si ologbon. Oha o

  • @tripleadrs127
    @tripleadrs127 5 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Ha alaroye. Mo se bi ile ise olotito ni bayi eti je ko ya wa wipe ile ise ko yato si awon to ku miiichhluuuuu

  • @akandeopeyemiolayimika7841
    @akandeopeyemiolayimika7841 3 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Olorun maba ti awon ijoba geshi ye, awon na ni wonba Nigeria je, won mo wipe Inkan tobamu ki Nigeria pinya agbara awon tipin niye biwon fe biwon ko, Nigeria si mapin ya lojo kan na ni, Tori aole mabalo bayi

  • @atinukeserifat793
    @atinukeserifat793 3 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Owo Nigeria Government lo wa nbe. Aeon lo sare lo lubby lodo awon UK Government.

  • @OyeyemiSalau
    @OyeyemiSalau 2 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Se bi awon oyinbo yi lo so wapo
    Se Awon oyinbo yi feda ogun sile ni

  • @BasiratOrire
    @BasiratOrire 4 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Alaroye she gbadun? Oju yin lo se abi, radarada

  • @durojaiyesamuel371
    @durojaiyesamuel371 8 ชั่วโมงที่ผ่านมา +2

    iro patapapa ni, iro to jina ooto ni

  • @adekunlefodilullahmfa7700
    @adekunlefodilullahmfa7700 8 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    Iro nla 😂😂😂

  • @Fiona-ql2le
    @Fiona-ql2le 8 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Ironi Igboho ko ni ok letter si UK Baba Akintoye ni

  • @AdesolaKilanse
    @AdesolaKilanse 6 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Alaroye e nparo pupo

  • @solabolaji5364
    @solabolaji5364 9 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Ijoba Geesi je orile-ede alabosi ti ko ni daadaa kan to fe se fun orile ede kankan! Awon ni odada to da rugudu sílè. Bi ko ba je abosi tino gbaye kan, nise lo ye ki awon eya ti won fi tipatipa ko po lo fi ejo UK sun ni ajo agbaye. Ijoba alayojuran ni ijoba geesi.

  • @OniyideAbidemi-z7u
    @OniyideAbidemi-z7u 6 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Iro fun fun pata ni

  • @alabaadejumo535
    @alabaadejumo535 7 ชั่วโมงที่ผ่านมา +2

    alaroyẹẹ, kinnio dẹ ti ẹ fi ọwọ ti o dun yin si abẹ aṣọ, nigbatí ẹ mọ wípẹ Aré Bọ́lá Amedi ni sunday nṣẹ isẹ fùn nitorí awon fulani. o ma ṣẹ o, ALABOSI KO NI JẸ ÉRÉ. ẸYIN NGBÉ IRAN YIN TÁ . AWON ALALẸ́ YORÙBÁ TI DÍDÉ SI YIN NI AṢẸ ẸDÙMARÉ. AṢẸ.

  • @funmilayoodularu5244
    @funmilayoodularu5244 8 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    IRO PO FUN ALAROYE

  • @oe6526
    @oe6526 7 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    Yoruba nation is not going to happen in this century; the rancour of yoruba muslims, the aborisa and baba taku ti Jesu may last the rest of this century!
    Igi 🌴 ti wo lugi 🌴
    Before they went and presented the letter to the property owner, did they consult with IBB a key player among their caretakers?
    Because IBB had said if the noise of war woke him up from sleep, and he looked out the window and found that it was yoruba people beating the 🪘🪘🪘 of war, he would go back to 🛏
    He may have told the property owners to pay them no mind.
    Yorubas are not ready now; not even what we are hearing now that
    "Anobi ji patapupa, anobi do Ayisat ni omodun mesan, oni ju anobi lo, imam ife ju oni lo";
    "Jesu jale";
    "Osumare lo do iya orunmila, the mother transfered the paternity to orisaoko therefore omo ale ni orunmila"
    It will take a century to fix the damage.

  • @idrisalooma5120
    @idrisalooma5120 7 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Sunday igboho fe se idasile orile-ede isese nation not Yoruba nation elemesho atirie kasesile

    • @oe6526
      @oe6526 6 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

      Mufti called the logo of yoruba nation's flag oriolokun🤓