Very Interesting and scary explaination, for the man to fight ghost huun , and I LOVE him for LOVING his CHILDREN, he didn't want them to step in the shoes of all his hard experiences of being a HUNTER , This man is ABIYAMO Tooto 👍👍
I think this is one of the most interesting programmes i have ever watched. Very interesting and educative. The Baba himself is smart and active. He is funny somehow also 😅 May he live long... Mr Nurudeen, May you walk and never stumble.
E jowo omo Agoro, e ba wa Se iwadi fere ibile Yoruba. Kin ni won Fi n ṣe e! Oloode Baba Ode so ikan ti wo n le ni àbèrè.. Kin ni won Fi n ṣe e, Kinni won n loo fun? E ṣe un o Alagba
This man is very nice ❤
Kòní bàjẹ́ fún yín jàre ✌️
Well done sir
I like the way you display the picture of each of the animal. Well done
Thanks ✌️
This man is a mysterious hunter. He is exceptional
Very Interesting and scary explaination, for the man to fight ghost huun , and I LOVE him for LOVING his CHILDREN, he didn't want them to step in the shoes of all his hard experiences of being a HUNTER , This man is ABIYAMO Tooto 👍👍
Your program is top notch . The best out there. Kudos
Thanks sir✌️
Well done,
Thanks ✌️
This is oustanding. I love this man's style and clear understanding. Can someone talk to this man directly?
Yes you talk to him directly. Contact us on WhatsApp 08069316812 to collect his phone number. Thanks ✌️
Ejowo ebawa gba number baba
@@ModupeSalami-nf6qt Contact us on WhatsApp 08069316812 to collect his phone number. Thanks
You are doing a great work.
Thanks ✌️
Very good of you , you are d a great work.
Thanks ✌️
Lati Americans a n gbo yinno
Ẹ seun sir ✌️
Wow 😮 badman
Thanks ✌️
My program is here now.. Let me sit back and adjust my belt...
Thanks sir, much love ✌️✌️
E jowo e fun mi phone baba wa yo
Ẹ bá wa sọ̀rọ̀ lórí WhatsApp 08069316812 láti gba òùnkà ẹ̀rọ ìbáni sọ̀rọ̀ wọn. Ẹ seun
A o gbọ nkan tí bàbá yí nsọ
Okay, Ẹ seun pupọ ✌️
Sorry I can’t hear it clearly.Eso ila or what
Eso ila nibo nìyẹn? Tell me the charm. Thanks ✌️
This man is very very original.
Thanks ✌️
This baba he is so powerful man
Thanks ✌️
I think this is one of the most interesting programmes i have ever watched.
Very interesting and educative.
The Baba himself is smart and active. He is funny somehow also 😅
May he live long...
Mr Nurudeen, May you walk and never stumble.
Amen o, Thanks Mr Opeyemi Oluseye, ọ̀dá itọ́ kìí dá ahọ́n, ọ̀dá ohun rere kòní da yín ✌️
Please l need the baba number, oluwa yio mapa alo ati aboyinmo amin
Oluwa ama ran yin lowo ooo Oyeolohun 🙏🏾
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun ✌️
Bro u a doing great job
Fun gbigbe asa wa,ede wa laruge Elédùà yíò wá pẹlu yin
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, àti ẹ̀yin náà lágbára Olódùmarè. Ẹ seun ✌️
Weldone sir, I always enjoy your program may God continue to be moving you forward
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun ẹ̀yin náà ẹ kò ní bàjẹ́ láyé láyé ✌️
I love this guy program
So interesting program keep it up sir
Thanks ✌️
Eku ise takuntakun olorun koni pada leyin yin sir
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun ✌️
You are the best sir, May God bless your hustle
Àmín àṣẹ Èdùmàrè., àwa náà kọ, Olódùmarè lo ni kí ó rí bẹ̀✌️
Thank you for this
My pleasure! ✌️
Keep it up my brother
E jowo omo Agoro, e ba wa Se iwadi fere ibile Yoruba. Kin ni won Fi n ṣe e! Oloode Baba Ode so ikan ti wo n le ni àbèrè.. Kin ni won Fi n ṣe e, Kinni won n loo fun? E ṣe un o Alagba
Fèrè tí àwọn ọlọ́dẹ ńfọn hun, tí Wọ́n pè ní àbèrè, igi ọparun ni Wọ́n má fí ń gbẹ́ ẹ
I have done it and it confirmed thanks you sir agba ko no tan ni orilede Yoruba
Thanks you for all your effort Mr oyeolorun
💞💞💞💞
@@kasumudavidaunoluwapo-jl4yn Àmín àṣẹ Èdùmàrè
Ganiu Muraina ibaa. Mogbadun iforowero pelu Baba Ode yi pupo. Oolotu eseun. Amajuyinse lola Edumare.
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun, ẹ̀yin náà ẹ kò ní ṣe àsetì ✌️
Ogun amadowo fun gbogbo wa lola Eledumare 🙏.
Eku ise takun takun mo gbadun eto yi mosi gbadun Baba oloode yi
Ẹ seun, Ayé á gbádùn ẹ̀yin náà, Olódùmarè Á sì jẹ́kí ẹ̀yin náà gbádùn ara yín ✌️
Weldone sir
Thanks ✌️
Olorun Ama bayin se eo ni sinse angbadun yin o
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, ibanujẹ koni wọle tọ yín ✌️
Eba ebere oro lowo baba nipa itu ti won fi egbere pa, ki won fi eni han wa to siwa lowo won
Well done for the great and wonderful program always 😊.
Thanks ✌️
Respect baba mi
I trust you King, ìdọ̀bálẹ̀ mi re ooo❤️✌️
Good work brother
Kudos good job 👏
Thanks ✌️
God bless u bro n baba...I really enjoyed this master piece..this is an hero when it comes to hunter😊
Amen, Thanks ✌️
lovely ,i love the programme well done mr nurudeen.
Ẹ seun A dúpẹ́ sir ✌️
We need to see the mat o
Ẹrin músẹ́, o dara ✌️
Bàbá yi duro tan àwọn Yorùbá gidi nìyẹn won duro tán
Bẹẹni, ọkùnrin ogun ni wọ́n✌️
E ku ise o
Ẹ seun sir✌️
Kudos to u all
Thanks Otunba, long time sir ✌️
Ejowo se ele ko gbo oun Ti won ni ka se yi jade fun mi
Yes, Ẹ kàn sí wa lórí WhatsApp 08069316812
Àṣẹ Àṣẹ Àṣẹ
Ẹ seun Ẹ̀gbọ́n mi ✌️
Ekuse opolo sir olorun ama funyin se o
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ ✌️
Eseun pupo olootu omo Agoro
Ẹ seun mo dúpẹ́ sir✌️
Se enikan lo le lo ise Ogede Agbagba yi tabi Iyawo ati Omo le lo ninu e?
Let him talk more about lions he killed
Okay next time
Eku ise opolo
Ejowo olootu, bawo ni mo se leri phone number baba ??
Ẹ kan sí wa lórí WhatsApp 08069316812
What can all these our fathers do to stop fulani attacks on YORUBA land.
They can't do anything lójú táyé but under ground bcos Government didn't allow them to tackle bororo
This guy interrupted the baba too much. He believes he knows too much. He is not a good presenter
Thank you sir
Eku igbasa laruge olorun koni pada leyin yin sir
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ ✌️
Weldone sir
Thanks ✌️