ITAN ILU OJOOWO NI IJEBU-IGBO LATI ENU OLOKINE TI OJOWO

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 15 ก.ย. 2024
  • Èyí jẹ́ ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò tí Bùkọ́lá R. Adélékè ṣe pẹ̀lú Aláyélúwà, Ọba AbdulRasheed Àbáyọ̀mí Bánjọ (Orilonise 1) tí wọ́n jẹ́ Olokine ti Ọ̀jọ́wọ̀ ní ìlú Ìjẹ̀bú Igbó nípa ÌTÀN ÌLÚ Ọ̀JỌ́WỌ̀, ÌJẸ̀BÚ IGBÓ ṣáájú ètò ayẹyẹ Ọjọ́ Olokine fún ti ọdún 2022.
    GBogbo wa ní ilé iṣẹ́ Ìṣẹ̀dálẹ̀ Media Concept mọyì ọwọ́ ìfẹ́ tí Kábíyèsí fi gbà wá lálejò lásìkò tí a lọ ṣiṣẹ́ yìí, ìlú Ọ̀jọ́wọ̀ ò nìí bàjẹ́ o, yóò máa tẹ̀síwájú ni láṣẹ Èdùmàrè.
    Ẹ má gbàgbé láti darapọ̀ mọ́ wa lójú òpó TH-cam yìí láti máa gbádùn àwọn ohun Ìṣẹ̀dálẹ̀ wa gẹ́gẹ́ bí ọmọ Yorùbá àtàtà. Ẹ ṣeun púpọ̀ 👍

ความคิดเห็น • 3