Je ka lo si Timbuktu! : Bino ati Fino Yoruba . Bino and Fino Yoruba

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 25 ส.ค. 2022
  • Ninu episodu Bino ati Fino yi, won lo si Mali pelu iranlowo Zeena lati ko nipa iwe-akosile atijo Timbuktu ti o yani lenu.
    Bino ati Fino je ere-onipele apanilerin nipa tegbon-taburo okunrin ati obinrin ti oruko won n je Bino ati Fino ti won n gbe pelu awon idile won ni Nigeria. Bino ati Fino se orisirisi awon oun amaraya nibiti, pelu iranlowo ore won Zeena Labalaba Onidan nni, won se awari beeni won si ko nipa Afrika ati iyoku agbaye.
    Afojusun pataki isafihan ere naa ni gbogbo igba ni lati pese eto idaraya ati ikonileko fun awon idile. Gbogbo iwonyi pelu iriri ohun Afrika tooto, ati eyi ti o yato.

ความคิดเห็น •