LOHUN TI TINUBU SE YI, MO FOWO SI KA PIN ORILEEDE YI

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 15 ก.ย. 2024
  • LEYIN TI NIGERIA BA PIN TAN BOLA TINUBU OGBODO SEWON GBERE
  • บันเทิง

ความคิดเห็น • 20

  • @wellsfargo2759
    @wellsfargo2759 9 วันที่ผ่านมา

    Amin ase Edumare made ile ileri eku ise takuntaun

  • @PrinceAdebowaleAdewunmi-gm3nj
    @PrinceAdebowaleAdewunmi-gm3nj 10 วันที่ผ่านมา +1

    ỌLỌRUN OLÙGBÀLÀ BÙKÚN YORÙBÁ NATION ÈMI ÀTI ÌDÍLÉ MÍ PRINCE 1 ASE ÈDÙMÀRÈ ❤

  • @TaiyeSanni
    @TaiyeSanni 8 วันที่ผ่านมา

    oluwa ma jeki ase aseyori Amin

  • @zbest109
    @zbest109 10 วันที่ผ่านมา +2

    E ma so ohun te ma se fun Tinumbu ti Nigeria ba pin. E se Ari logbon Lara Pa Awolowo, nigbati o so pe ohun a probe awon oselu eyi lo bi Obasanjo ninu ti o fi gbe ijoba fun Shagari. So e je ki a fi ohun ti a ma se fun Tinumbu pamo.

  • @BamideleMathew-tg6pe
    @BamideleMathew-tg6pe 10 วันที่ผ่านมา +2

    Sorry! Iya o ti jeyin gbogbo yin sese bere ni. Nigba to ba ya e ronu lati se nkan to kan.
    When the affliction overwelme you people you will rise up and fightvfor your freedom which is yoruba nation.

  • @adejokechristiana1386
    @adejokechristiana1386 10 วันที่ผ่านมา +1

    Is a pity. Oga ooo

  • @gbemisolaolokodana1116
    @gbemisolaolokodana1116 10 วันที่ผ่านมา +1

    Oga gan ni Yoruba wahala eyan kilode ninu aiye Ankara ayetoto oga

  • @OmolaraEstherOsunniyi
    @OmolaraEstherOsunniyi 9 วันที่ผ่านมา

    Well done sir

  • @OmolaraEstherOsunniyi
    @OmolaraEstherOsunniyi 9 วันที่ผ่านมา

    God will be with you sir

  • @abiodunawonowo1157
    @abiodunawonowo1157 9 วันที่ผ่านมา

    God bless YORUBA NATION. YORUBA NATION is the only solution.

  • @gbemisolaolokodana1116
    @gbemisolaolokodana1116 10 วันที่ผ่านมา +1

    ASE tedunmare 🙏🙏

  • @gbemisolaolokodana1116
    @gbemisolaolokodana1116 10 วันที่ผ่านมา +1

    Amin loruko 🙏 EMI

  • @user-vw9hv5ie9o
    @user-vw9hv5ie9o 10 วันที่ผ่านมา +1

    Nibo lade gan bayi?

  • @olufunmilayoidowu837
    @olufunmilayoidowu837 10 วันที่ผ่านมา +1

    Yoruba Nation lafe ni kiakia to di wipe awon okunrin a sun lale to baa di owuro ki horopon re ma di awati lowuro awon ole a ti yo lo Yoruba Nation no going back

  • @abimbolasimiloluwa1194
    @abimbolasimiloluwa1194 9 วันที่ผ่านมา

    Kini tinubu fi yato si emefiele amoye eniyan ti o ku nigbati ti emefiele ko owo pamo ewa wo bayi aimoye eniyan ti o ti ku

  • @henryidonije
    @henryidonije 9 วันที่ผ่านมา

    Yoru banation no going back,

  • @tinaparker5248
    @tinaparker5248 10 วันที่ผ่านมา +1

    Yoruba Nation is must. We must achieve it. We are a unique people, we must stand on our own and not depend on others. We must hold onto our culture and not let it perish. God bless us all.🙏🏾

  • @iretiebiesuwa9071
    @iretiebiesuwa9071 9 วันที่ผ่านมา

    E ku ise takuntakun Olorun a kuku saanu wa

  • @FolasadeFagbola
    @FolasadeFagbola 10 วันที่ผ่านมา

    Arole 10 10 e je ki gbogbo wa ni number yon lowo nitoripe opolopo wa la ni ife si ise takuntakun ti e nse fin ile yoruba awa na fe ki ama dasi oro yoruba nation amonsa opolopo wa o ni number yon lowo depo ti a fi ma fi owo ranse lati fi owo ranse oye ki e ma fi numer yo. Si ori screen yin ki a le ma riyin pe yoruba nation no going back from texas