Iroyin Asale 8th Sept 2024: Dangote refinery ko ta epo sí nigeria | Gov le special adviser re danu
ฝัง
- เผยแพร่เมื่อ 16 ก.ย. 2024
- Dangote refinery le ma ta epo rẹ sí nigeria | Gov Adeleke le special adviser re danu | NAFDAC #ogbenibobby #tinubu #sundayighoho #obasolomoni #arisetv #yorubanation #oriyomihamzat #esabod #channelstv #trendingnews
Àwọn olè gbé olè gbá 😊
Indirect 419. Yahooo big time. Awon olee olaa shaa.
Èmi ṣẹ̀ṣẹ̀ ń wò ní ó!
Ogbeni Bobby you're doing well, keep it up.
Ogbeni gbewon debe.
Ẹ kú isẹ takuntakun ó Ọ́gbẹ̀ni Bọbi mí!
Abacha spirit enter Tinubu Body
Ekaro sir ooo baba mi ogbeni bobby EKU ISE takun takun sir ooo emiyin yio gun ni agbara gbogbo awon ALA Len Ile Yoruba patapata ooo Yoruba nation no going back
Tinubu deserves what Atiku is telling him, Senators, ministers ,governor's, house of rep and national Assembly will all bears 4rm what God will judge them all in Jesus name Amen. 🙏
Ekaabo ogbeni bobby,e ku eto naa,e bami ki aaya wipe o ku ise oo
More ngbadun iroyin hiny oooo, e ku ise takun takun sir
OGBENI BOBBY EKU ISE TAKUNTAKUN SIR
Eleyi gba Enutan oh!!!!!! Woto woto for Baba Adeboye😅
Ìyá Patience tí sọ pé òun àti ọkọ òun ó ṣe ìjọba mọ ó 😅
Iba gbewa debe ride on your head dey there e fi haters sile their mind no go touch ground
Speakmy my men. Say it loud and clear.
Pastor abrakadabra kún ilé ó 😮
Olooodo ooo. Malika Jubilee ewoo. Owoo inaa pelu iroo paa fun awon eyaan.
God bless you, Ogbeni Bobby
Amen
Yoruba nation is the best solution
Yoruba nation lafe .
Kudos ogbeni bobby
Subuhanalai. They have been called out that's why. Thanks to Black Man who is calling them out for their oversight.
Yes ijekuje o je ki enu agba tole awon ota mekunu
Ogbeni Bobby ekueto Edumare ASHA nuwa lowo àwon omo ale Nigeria oo lashe tedumare Yoruba Nason lafeoo Àwon Onile Àgba ilewa Funwaoo
Iba gbogbogbo ❤😂😅
Yoruba nation no goin back.
Well-done sir bobby, may GOD grant your efforts 🙏 . Our former president when he was on throwned said parents should limit child bearing, most parents said, will president help in feeding of their children. What was his concern. But this situation of nigeria, even if some parents are in need of a child, if the baby in the heaven can see what nigerian are passing through, infact the baby will hold on. Nigeria is too Hot. When will this worst situationl end. Ho! GOD almighty come to our aid. 😢. We want our FREEDOM.
Ameeeena yarobi
Iba iroyin yoruba ododo, e seun o
Se anfani ti U.K. ati America ni Nigeria nje.
Mr.Bobby ma da won lohun ooo.otoni tolu otoni toluwo,.
Iba debe, Omo Yoruba atata, Aya Oku irin ❤️❤️❤️you
Ebeeruuuu olorun .
Yoruba nation nikan lona abayo.
Baba yii o mo oun ti o nse
Kí olúwa rẹ lọ bẹ̀rẹ̀ ilé iṣẹ́ ìròhìn tí ẹ ó! Gbogbo bí ẹ tì ńṣe ló ń dùn mọ àwa olólùfẹ́ yín ó ❤❤❤❤
Àṣẹ Edumare. Eseun iya wa daadaa ❤️❤️❤️
Ha O ga ooo Daddy G O of a church is one of the cabals destroying Nigeria this very shameful well done Omo Yoruba gidi God bless you
Bobby GOD BLESS YOU YOU ARE GENIUS
🙏🙏🙏🙏 AMEN ❤️❤️
Yoruba nation ni ona Abayo
Yoruba nation no going back
Ṣágo ń bùgó ní Atiku ó 🥺
Ogbeni Bobby. I can not stop laughing.. oyin oriburuku wo lati Apata?? Nigerians do not want any honey from the Apata. Oro buruku ati erin
🤣🤣🤣
EKU ISE,TAKUTAKU OOOO, OGBENI BOBBY.
TINUBU KO RAN ENIKENI NISE, ENI AIMORI KO BA KU , HMM , TINUBU BERU OLORUN OO
PLEASE WE CONTINUE TO PLEAD HAVE MERCY MERCY MERCY
WE PLEAD TO U IN D NAME OF GOD
KINDLY RELEASE ALL TIS CHILDREN OOO
GOD HELP WE 😪 D HARDSHIP SUFFERING PLEASE PLEASE PLEASE
Àwọn olórí burúkú 😮, ṣe wọ́n fẹ́ kí ọmọ Nigeria lowo lọ́wọ́ ní? Àwọn Ọlọpa ibú 😢
Ogbeni Bobby, bawo ni nkan.
E fi Tinubu sile.E maa wo igbehin awon Oloselu; ati gbogbo won.
Iba petrol owon gogo😂
Amin Amin Amin
Baba alawada Jesu lagbara yin sapala lawa manpe nilu wa Ogbomoso Seri awan ijoba wa Jesu yo yo fiya jewan yosi Fi ara jewan ori opo Okunrin lobinrin omo orukan omo wewe tiolese lorun yosedajo fun wan
Ibukun nifun orile ede yoruba.
E ku ise Abo olorun yio daju lori yin
"Postponed ibinu" 😂😂😂😂. Gbe won debe 1!!!
🤣🤣🤣
O better is about time. Better. Why muted for so long!!!. Beeni
Ki olorun fun wa ni ore one Latino to omo wa ki won Yan ki won yanju
Seeing the elderly man addressing his junior colleague is very encouraging we should all remember tomorrow ..
Awon mekunnu lo ni osuka lati ru eru oo Sugbon Oluwa a gba ija wa ja A ni ku sinue
But how do these people think they can get away with this criminal act of shame? How would they try to carry women's pads to Britain when they sell them in all the pharmacies in the UK? So, you don't need to take many with you and if you do, that's where suspicion sets in. Won sa fe d'olowo tipatipa.
Gbogbo awon ijoba anini Lara
Ori gbogbo awon mekunnu loma dawon lejo
Good evening sir
Good evening ma'am
God bless you
Huuuunnnn orisirisi ni nigeria
Atiku go explain tire he worst pass Tinubu
Baa gbewon debe e ma da won lohun oloto Oluwaseun ohun ni osika I’ll ise Godiva ni VDM Mae ooo ojo ko ni ti yin a ngbadun yin e si ngbe wa debe
Layo o we wish u well ki eyin na gbadun ose to nbo yi o ire o
Kaka ki ewe agbon de lile lo n le si.
OGBENI BOBBY, E SE PUPO FUN IROYI TO NLO..(OLORUN MA DAJO JEJERE NI GBOBGO WON)
Ogbeni Bobby bawo lase mabo ninu gbogbo eyito nsele Nigeria lojojumo yi afi yoruba nation loku ni ireti awa omoko ypruba
IBA IROYIN TO MUNA DOKO SEYIN NA NGBORO BURUKU LENU OMO EYE TINUBU NA NI OMO EYE NA YORUBA NATION NIKAN NI ONA ABAYO KI OLORUN OBA FUN WA SE AMIN
Se o daabe ki etun se iroyin yi leyin mi loni? Koburu Eku ise takuntakun o
🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣❤️❤️❤️❤️❤️
Ikilo rere ni.Lodo Oba
Mo ki yin olotu e ku ise takuntakun, Nkan ti okunrin kan so ninu Programme kan laro yi , O ni eyin ilu e lo ba awon Governors yin o ni Federal ti fun gbogbo won ni Billions of Naira ti won le fi se nkan fun ara ilu o ni e ma pariwo President yi mo o ni kan lo protest si Governors won, nitori Ijoba ti ko owo fun won
Bẹẹni ooo, o dìgbà t'awon eyan ba sinu sí awọn Gómìnà lara ki won to ri ẹtọ won gba
Ki awon Ara ilu lo ba gomina won, alocation won ki ni won fi se.All governors should embark on farming in large scale
Yes ooo
UP YORUBA NATIONS NO GO BACK
Eeyan Ashake ni Tinubu won ti ge leti lo
Ekale o Ogbeni Bobby. Kise ipinle Edo nikan ni o sun iwole awon omo ile iwe siwaju o, Delta ati Kano paapaa ti sun tiwon naa siwaju o.
Gbogbo won lo sí ma sun Siwaju, o di next year Kan to wo'le 🤣🤣🤣
@@ogbenibobby
Oro buruku t'oun t'erin!
Amin thinks good week
Ogbeni Bobby, ẹ kú iṣẹ́ o, Olóyè Àáyá ńkọ́? Ẹ bá wa kí Olóyè Àáyá. Ọ̀rọ̀ Naijiria yí má tó jásí ibi tí a fẹ́ kó jásí láìpẹ́ ní agbára Jésù Kristi. Mo gbádùn ètò yín laaro yí lórí ọ̀rọ̀ Tinubu àti yacht tí Naijiria ṣẹ̀ṣẹ̀ ra tí wọ́n gbé pamọ sí France.
Ẹ kú iṣẹ́, ẹ kàn ngbe wá dé bẹ ni sá. Olúwa Aa ma wà pẹ̀lú yín.
Ẹ jọ̀wọ́, time wo ni ẹ máa ka ìròyìn yín, mo fẹ́ gbọ́ yín live? Wákàtí kan ni aago orile-ede Yorùbá fi ju tí Ìlú tí mo wà lọ. Bakanna, tí ó bá ṣeé ṣe mo fẹ́ number aago ìbáni sọ̀rọ̀ yín fún ìdí pàtàkì.
Iba Sanawole
Oga agbaye my foot. We are the owner of our crude oil and we should enjoy it at cheaper rate. Nigeria should sell at global rate to other country. NNPC should stop this nonsense they are doing.
❤️❤️
Mo ti pin in
🙏👌❤️❤️❤️
If dangote refused to sell in petrol to Nigeria or allow NNPC to manipulate him. He should go and source his crude oil outside Nigeria then. Give your petrol to another marketers instead of playing games with Nigerian.
Exactly 💯👌
Governor Ademola ifeanyi Adeleke Ole, be fun won ni ten Kobo won maa ponla nibe, awon eni ibi ti Pon Omo rele iwe, chup nockle Aya 😂
🤛🤛🤛
Owu jija ni onyo yo pastor to nsoro yi lenu esu ti nlo pasito naa lenu nitori ise oluwa to baba pasito Enoch adejare Adeboye nse fun olorun oba bibeli so ninu Mathew ori keje ese kini wipe mase dani lejo kia ma ba da e lejo gba oluwa laiye lati se idajo funrae
Baba oo,Iba gbewon debe of Yoruba nation...... lo'ogun ofe o.u r too much bro
Elo ni owo ti won San fun osise ni Nigeria ti won fi owo le epo,Ika ni ijoba Nigeria,Olorun nikan lo le ko wa yo. Yoruba la fe,eyi ti o po ni ibe president bola tinubu lo ko wa si wahala,se bi oun lo gbe muhammodu Buhari wole,Ika,amunisin ni gbogbo won.
Won ti scam NLC. Won bere lowo NLC pe se k'awọn san 615,000 sugbon k'awọn fowo kún owo epo, tàbí k'awọn ma f'owo kun owo epo sugbon k'awọn san 70k fún oṣiṣẹ
Ọgbẹni Bọbbi, dakun ṣe Atiku lẹnu ọrọ ni. Ijẹrin ode yi ni Atiku ati ọga rẹ fi iya jẹ ọmọ Naijiria. Erongba Atiku tori 2027 ni. Ti Naijiria o ba pin, otun fẹ gbe apoti ni. Ṣugbọn laṣẹ Eledua, ọkọ Yoruba Nation to ti lọ ni ọmọ Fulani Atiku n ju ọwọ si. Gbogbo olori ati ẹlẹmu to ti gbin ebu ika lorilẹ ede Naijiria nipa fifi iya jẹ mẹkunnu, iranderan wọn yio jẹ dọjọ alẹ wọn ni lagbara Eledumare.
The guy like 2 tribalism
GodBless 😂😢😮😅
Amen
Se ti dagote ba ta epo SIta se Ori e Ile ede bomi ni won ti gbe epo robi wa ni ki awon ara ilu dawon duro lati ma gbe epo robi ni Ori ede nageria.papa ki awon Bayer da won duro .ni tori ko SI afa ni pe won ko epo coold oil ni nageria ba yii
Sapala ni won nfi agbado Se.
Oh really
Odaju.ni Babayi.kilode teyin Babayi.fepa.gbogbo aralu.nitori ikan.bere komo.lopin emimope odaju.ota olorun enibi.niawon.oloselu.olorun lolemuwon nitori enitalemu.olorun lafalelowo atifawon.lolorun lowoo
Lodo Oba,e jo omo ILE OLOTA ni iwo
Mi o mo eni to paro ju ninu asetani ati awon oloselu wa bi won ba ki yin ku aajin osan gangan ni a wa
🤣🤣🤣🤣🤣
Too much Baami Aku eto
LODO OBA;IBA KANJU ABE NIKO
Yoruba Nation no Going back.