MAKEUP AND GELE TUTORIAL IN MY NATIVE LANGUAGE

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 4 ม.ค. 2025

ความคิดเห็น •

  • @jumoke3630
    @jumoke3630 6 ปีที่แล้ว

    loveeee it!!!

  • @geniaa.5065
    @geniaa.5065 6 ปีที่แล้ว +1

    Omg what was that song intro at the beginning that caught my attention. Nice makeup ✌🏿✌🏿✌🏿✌🏿

  • @Anyaa
    @Anyaa 7 ปีที่แล้ว

    This was fascinating! I love how detailed this was. I just subscribed and can't wait to see more!

    • @Facequizite
      @Facequizite 6 ปีที่แล้ว

      Anya 👏🏽👏🏽👏🏽👏🏽👏🏽👍🏽 you did great. I just recorded mine today. I haven’t even edited it yet. I consider myself as someone who is fluent in Yoruba, but oh my goodness! No be small thing o. I was shocked at how difficult I found it. It was good fun though. Once again, well done 👍🏽👍🏽

  • @vivicavivian3049
    @vivicavivian3049 6 ปีที่แล้ว

    New subscriber 😘😘

  • @thethinkinglady2957
    @thethinkinglady2957 6 ปีที่แล้ว +1

    O seun ti o fi ede abinibi Yoruba se apejuwe itunojuse yi. Eeyan pupo ni ko gbo ede geesi sugbon ti o wu won lati ko eko itunojuse. Nisiyi, ti o ti ko won ni eko yi ni ede Yoruba gbogbo awon eniyan ni yio kan saara fun o, nitoripe o see alaye yi fun won daadaa. Oluwa yio tubo maa ran e l'owo o. Amin. Faari by Sisi Ope (Lagos) and Facequizite (England) naa ti se itosona itunojuse ni ede Yoruba. Mo Kan saara fun gbogbo yin o. O Dara lati gbe nkan ti a ni laruge. Lati tubo se eko miran daada ni Yoruba, maa gba e ni imoran lati koko ko (place) gbogbo oun elo (makeup items) itunojuse gbogbo ti o fee lo sile, ki o waa see alaye nkan ti won wa fun si ori awe iwe (paper) bayen, o maa rorun fun e l'ati mu won ni ikonkan (each) ki o de se alaye lilo won bi o ba se e nmu won lo. Mo ti je olufe channel e l'ati odun bii meji si eyin. O seun, a dupe o, Misty A. Your dance move to the Wasiu beat at the end of the talk through is nice. Good job!