Ni oruko Jeeesu, loni mo bori ogun, mo bori olote, awon omo mi bori ogun aye, won bori awon olote, won bori awon abinueni, loruko a bori gbogbo ogun alabagbele, ogun ota ile ati ti ode, a bori won, Oluwa mu wa bori won loruko Jesu
Gbogbo ti won fowosowopo mo lati da aye mi duro, lati da aye awon omo mi duro ni oruko Jesu, ki gbogbo igi won maa ya lule, ki won wu tiditidi, ki won wo lule loruko Jesu
Ni oruko Jeeesu, gbogbo eni ti mo fa dani, ti awon omo mi fa dani ti won ni awa ni won maa te mole koja, Oluwa ba mi ja won danu lowo mi ati lowo awon omo mi
Aamin loruko jesu
Thank you Jesus for everything
More anointing in Jesus name 🙏 🙌 ❤ ✨ 💖 💕 🙏 🙌 ❤ Amen 🙏.
I connect myself, my children, my in-law and my sick sister to this powerful evening program Ijn 🙏 amen
Amin Amin Amin Amin Amin Amin jesu
Greater unctions sir.
We love u more
Amin Jeeesu
Ni oruko Jeeesu, loni mo bori ogun, mo bori olote, awon omo mi bori ogun aye, won bori awon olote, won bori awon abinueni, loruko a bori gbogbo ogun alabagbele, ogun ota ile ati ti ode, a bori won, Oluwa mu wa bori won loruko Jesu
More anointing in Jesus name sir
Gbogbo eni to fowosowopo lati da aye mi duro, lati da aye awon omo mi duro, Oluwa fi iku tu won kan loruko Jesu
Gbogbo ti won fowosowopo mo lati da aye mi duro, lati da aye awon omo mi duro ni oruko Jesu, ki gbogbo igi won maa ya lule, ki won wu tiditidi, ki won wo lule loruko Jesu
Oluwa gbe egun mi ni nu ayemi oo loruko jesu oo amni
Thank you Jesus
Ni oruko Jeeesu, gbogbo eni ti mo fa dani, ti awon omo mi fa dani ti won ni awa ni won maa te mole koja, Oluwa ba mi ja won danu lowo mi ati lowo awon omo mi
Gbogbo eni to fowosowopo lati di ona mo mi ati awon omo mi, ati oun ati igbimo won, Oluwa fi iku tu won ka loruko Jesu
Amin loruko Jesu
Daddy eonijabo ĺ felomiran dide loruko jesu krist oluwa wa amin 🙏
Amin olorun
Ohun ti won gbero lati ja mi bo, lati ja awon omo mi bo, ni oruko Jesu, iku tu won, Oluwa fi iku tu won ka
Amen jesu 🙌🙏🙏🙏
Daddy e ku ise oluwa akotun agbara loruku Jesu krist
Amen
day
Amin loruko Jesu
Amin loruko Jesu
Amin loruko jesu