Ninu yara agbara kaka ayeraye gbe mi jade tomotomo, ninu yara tipa tikuuku, Emi Mimo gbe mi jade, Oluwa gbe mi jade tomotomo, ninu yara inira ati abuku, Oluwa fi aanu gbe mi jade tomtomo loruko Jesu
Ni oruko Jeeesu, Oluwa ninu osu yi, fi ase gbe mi dide, fi ase nla re gbe awon omo mi dide sinu ogo, Oluwa fi aanu gbe aye mi dide, fi aanu gba aye awon omo mi didu wonu iserere, oore-ofe ati ibukun nla lo losu yi loruko Jesu
Ni oruko Jeeesu, Emi Mimo ooo, ori mi jade laarin awon ori to n jiya, ori awon omo mi jade laarin awon ori to n jiya laye, laarin ori to n jise jiya, ori mi ati awon omo mi jade sinu ola ati iserere, ori awon omo mi jade sinu ogo tuntun loruko Jesu
Amin Jeeesu, gbogbo irawo to ti doku ninu aye mi ati awon omo mi, ni oruko Jesu, ki won gba imisi iye, aye mi, aye awon omo mi gba imisi iye, ise awon omo mi gba imisi iye loruko Jesu
i oruko Jeeesu, Emi Mimo ooo, nibi ti aye so mi si togotogo, mo jade loruko Jesu, ibi ti aye so awon omo mi ninu yara imule, ni oruko Jesu won jade togotogo nibi ti aye so ipin mi ati ti awon omo mi, agbara Olorun gbe wa jade si gbanga, a jade wonu ola ati iserere otun lo loruko Jesu
Nibi ti aye toju awon omo mi si, lale oni ni ko gbodo di ola, won jade nibe wonu iserere won lo, won jade nibe wonu ogo tuntun lo, won jade nibe wonu ola ati ibukun won lo loruko Jesu

Alleluyah Alleluyah Alleluyah Alleluyah Alleluyah Alleluyah Alleluyaaaaaaaaaaaaaaaaah - Ogooooooooooooooooooooo
Thank you Jesus for everything
Thank you Lord Jesus Christ
😅od😅 am grateful for your annointin😅ginour li😅ves

Amin Amin Amin Amin Amin Amin Amin loruko Jesu Kristi
Ni oruko Jeeesu, Emi Mimo ooo, ori mi jade laarin awon ori to n jiya, ori awon omo mi jade laarin awon ori to n jiya laye, laarin ori to n jise jiya, ori mi ati awon omo mi jade sinu ola ati iserere, ori awon omo mi jade sinu ogo tuntun loruko Jesu
Amin Jeeesu, gbogbo irawo to ti doku ninu aye mi ati awon omo mi, ni oruko Jesu, ki won gba imisi iye, aye mi, aye awon omo mi gba imisi iye, ise awon omo mi gba imisi iye loruko Jesu
Laarin awon ori ti kii se rere, ori awon omo mi jade kuro ninu, laarin awon ori onise, ati oniya, ori mi ati ti awon omo mi jade kuro nibe loruko Jesu
Amen Amen Amen Amen 🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏
i oruko Jeeesu, Emi Mimo ooo, nibi ti aye so mi si togotogo, mo jade loruko Jesu, ibi ti aye so awon omo mi ninu yara imule, ni oruko Jesu won jade togotogo nibi ti aye so ipin mi ati ti awon omo mi, agbara Olorun gbe wa jade si gbanga, a jade wonu ola ati iserere otun lo loruko Jesu
Nibi ti aye toju awon omo mi si, lale oni ni ko gbodo di ola, won jade nibe wonu iserere won lo, won jade nibe wonu ogo tuntun lo, won jade nibe wonu ola ati ibukun won lo loruko Jesu
Hallelujah hallelujah hallelujah
Daddy e ku ise oluwa akotun agbara loruku Jesu krist
AMEN 🙏🏻 🙏🏻 in Jesus name
Amen in Jesus name
Amin Jeeesu
AminJesu Amen Amin
Amen jesu 🙏🙏🙏
Amennnnnnn
Amin ni oruko Jesu Kristi
Amen
Amen
Amen
Amin Jesu Kristi
Amin, amin, amin, amin, amin, amin, amin, amin, amin, amin, amin, amin, amin, amin Jeeeesu