Hello Sir, good job, however, try and reduce the noisy background, decrease the flute, a bit noisy n not necessary, we need better audio not the flute..also try n let your guest speak louder and stay back to listen. Thank u and keep up wt fantastic job. 🎉
Baba iba yin oooo kepe sir.
Ẹ seun sir
Olorun oma fun yin se broda mi Oyeolohun. Olorun ama fun yin ni okun ati Agbara ooo
Ẹ seun Ẹ̀gbọ́n mi dada, kòní bàjẹ́ fún gbogbo wa✌️
Iba olodu omo are.... may your days belong
Amen ooo, Thanks and yours✌️
I really love your program sir
Thanks we love you too ✌️
This is my home town, from iyalode compound ,....oke iyaala❤
Oh nice
Òkè ìjòmù àbí Ẹsẹ̀ iya-nla? Ẹ seun ọmọ ìlú mi atata✌️
Wow please give us second part you really try keep winning sir
A ma fi léde láìpẹ́ láṣẹ Olódùmarè, Ẹ seun ✌️
Wow please give us second part sir may God crown your efforts
Check our Page sir✌️
May God bless you Oyeolohun tv
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun àti ẹ̀yin naa
E moju to esin dada sir.
Hummm
Kudos guys 👌
Thanks ✌️
Eku eto Oyeolohun koni suyin koni reyin lagbara olorun
Àmín ooo, Ẹ seun ìyá mi ✌️
Hello Sir, good job, however, try and reduce the noisy background, decrease the flute, a bit noisy n not necessary, we need better audio not the flute..also try n let your guest speak louder and stay back to listen. Thank u and keep up wt fantastic job. 🎉
Noted
Thank you sir
So nice of you ✌️
Kudos
Thanks
Olorun koni pada leyin yin sir
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun àti ẹ̀yin náà ✌️
I always enjoy your program sir thanks for bringing this ❤️
Thanks ma
❤ Bóse rí nìyan' Àlékún Èmí gígùn' Àláfhíà tó péye fún Olóòtú Oye-OLOHUN ❤
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun Bàbá wa Arifọkanbalẹ, Olódùmarè Á jẹ́kí a ri yin pẹ, Tede kòní bàjẹ́
Otito ni e so. Bibeli so pe “Onijagidijagan ni yo je. Owo awon eniyan yoo wa lara re, owo re yoo si wa lara eniyan.”
Hummm! Ẹ seun ✌️
Amiiiiii oooo thanks olotu
Thanks God ✌️
It look so beautiful
Ẹ seun púpọ̀ ✌️
Moki yin sir olorun ama funyin se moki baba wa oluwo ooo
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun ìyá mi dada✌️
ASE wa
Niti irke✌️
Good job, your preamble is an excellent one.
Glad you liked it
Thank you very much sir✌️
Kudos to you sir
Thanks ✌️
Thanks for this
My pleasure!
Thanks for thanks us ✌️
Ekuse sir olorun yo mafunyin se
Àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun ✌️
Very interesting program kudos to you Oyeolohun
Ẹ seun Bàbá mi ✌️
May God continue to be with you and your cast and crew sir
Amen o, Thanks ✌️
❤❤❤
Ẹ seun sir
Weldone sir may god crown your efforts
Thanks a lot
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun púpọ̀ ✌️
Kilo wa de ti gbogbo awon alagbara wonyi ni ile yoruba lasiko tiwayi won o le pawopo dide si awon iran fulani tonpa wa lati odun yiooo?
Oyeolorun am not confuse yet.
Okay bàbá call you today. Adua wa a gba sir✌️
Nice job
Thank you! Cheers!
Thanks ✌️
Let the man talk for god sake
Please last part sir
Okay
Weldone sir please don't let it take long before you upload 2nd part
Thanks, okay ✌️
No be this man just come back from oke-kura with Tani Olohun
❤😂
Thanks My body✌️
Oyeolorun well done. I Love the music played background, can I get it play on TH-cam?
Yes you can!
Yes, Baba Oluwo Ńlá Himself is the owner of the music, them do it for him on his egungun festival ✌️
Why Is baba calling anjonu orishas. Are Gjinns orishas?
Please I need this oluwo number thanks sir
No problem chatt us on WhatsApp 08069316812
Olootù eku isè oku oro ilè yorubà e fun wà ni apaa keeji lai pè è lai jinnà😅
Ẹ seun A dúpẹ́ ✌️
Your interruption is too much. You are not making it interesting
Okay, thanks
Ẹ seun, kí a dúpẹ́ lọ́wọ́ ẹni tó máni lójú, ọ̀pọ̀ ènìyàn ni kò wo ibi tí a wà.