Mo fe O n'gbagbogbo, Oluwa Olore Ko s' ohun ti nfun ni L' alafia bi Tire. Refrain: Mo fe O, a! mo fe O, Ni wakati gbogbo; Bukun mi Olugbala, Mo wa s' odo Re. Mo fe O n' gbagbogbo, Duro ti mi, Idanwo ko n' ipa Gbat' O wa nitosi. Mo fe O n' gbagbogbo, L' ayo tab' irora; Yara wa ba mi gbe, K' aiye mi ma j' asan. Mo fe O n'gbagbogbo, Ko mi ni ife Re; K' O je k'ileri Re Se si mi li ara. Mo fe O n'gbagbogbo, Ologo julo; Se mi n' Tire toto, Omo alabukun.
Absolutely! We need you Lord! Thank you for this sir.
We need Lord
We really need God in a time like this. God please quickly come to our aid!
Mo fe O n'gbagbogbo,
Oluwa Olore
Ko s' ohun ti nfun ni
L' alafia bi Tire.
Refrain:
Mo fe O, a! mo fe O,
Ni wakati gbogbo;
Bukun mi Olugbala,
Mo wa s' odo Re.
Mo fe O n' gbagbogbo,
Duro ti mi,
Idanwo ko n' ipa
Gbat' O wa nitosi.
Mo fe O n' gbagbogbo,
L' ayo tab' irora;
Yara wa ba mi gbe,
K' aiye mi ma j' asan.
Mo fe O n'gbagbogbo,
Ko mi ni ife Re;
K' O je k'ileri Re
Se si mi li ara.
Mo fe O n'gbagbogbo,
Ologo julo;
Se mi n' Tire toto,
Omo alabukun.
Thanks