IMONLE Titun, KABIYESI OOOOOO. Action la ma RI Baba WA, talkless says Kaybesi Action and work is a watch word. LONG LIFE OBA AFOLABI , NEW LIGHT AND YOU WILL SHINE
Congratulations to you pastor Olabode Ggandi, the good that put you there shall be with you and direct you and order your steps a right in Jesus Name. God bless you and bless your reign to the glory of His Name.
Congratulations Kabiyesi Oba,Pastor Olaoye Afolabi Ghandi.... Oluwa yio maa ba yin joba nilu Ogbomoso 🙏. Igba yin lori ite awon baba yin yio gbe Oruko Jesu ga ni Oruko Jesu 🙏. Eku yio ke bi Eku, eye yio ke bi eye 🙏.Ara yio tu gbogbo ilu ati gbogbo omo Ogbomoso ni Oruko Jesu 🙏.
Kabiyesi ki ade pe lori, ki bata pe lese ni oruko Jesu Kristi.Kabiyesi the Lord almighty will give you directions and wisdom how to rule the land of Ogbomosho like He gave Solomon in Jesus mighty name. Congratulations Sir!
AKU ORIRE TÍ ỌBA WA NI ILU OGBOMOSHO. ÀSÌKÒ ÀTI ÌGBA WÓN A TÚ WÀ LÁRA. ÀLÀFÍÀ ÀTI IFỌKANBALẸ YÍÒ JỌBA NI ILU WÁ, ÀTI ORILẸ EDE NIGERIA LAPAPỌ. OLORUN A GBÉ ÉMIN OGBON ATÍ ÌMỌ WỌ WỌN LÁTI DÁRÍ WA SI RERE. ÉMIN ÌFẸ YÍÒ JỌBA NINU ỌKAN ẸNÌKỌ̀KAN WA.
KABIYESI OOOOOOOOOOOOOO. ADE A PE LORI. BATA A PE LESE. IRUKERE A SE YENTURU YENTURU. EKU A KE BI EKU. EYE A KE BI EYE. ABOYUN ILE A BI WERE. ILU A TORO NIGBA TIYIN O. AMIN ASE .
IMONLE Titun, KABIYESI OOOOOO. Action la ma RI Baba WA, talkless says Kaybesi Action and work is a watch word. LONG LIFE OBA AFOLABI , NEW LIGHT AND YOU WILL SHINE
A ku oriire oooo, gbogbo awa Omo Ogbomoso atata. Igba Oba wa titun yi, yio tuu wa lara, ni oruko Jesu, Amin, Amin, ati AMIN.
Congratulations to you pastor Olabode Ggandi, the good that put you there shall be with you and direct you and order your steps a right in Jesus Name. God bless you and bless your reign to the glory of His Name.
Congratulations Kabiyesi Oba,Pastor Olaoye Afolabi Ghandi....
Oluwa yio maa ba yin joba nilu Ogbomoso 🙏.
Igba yin lori ite awon baba yin yio gbe Oruko Jesu ga ni Oruko Jesu 🙏.
Eku yio ke bi Eku, eye yio ke bi eye 🙏.Ara yio tu gbogbo ilu ati gbogbo omo Ogbomoso ni Oruko Jesu 🙏.
E ku oriire Oluso Aguntan Ghandi. Congratulations sir. Ijoba yin a tu Ilu Ogbomosho lara.
Pastor Laoye congratulations sir
Kabiyesi ooooooo. Congratulations to all of us, congratulation to the city of the valiants.
Congratulations to you sir
Kabiyesi ki ade pe lori, ki bata pe lese ni oruko Jesu Kristi.Kabiyesi the Lord almighty will give you directions and wisdom how to rule the land of Ogbomosho like He gave Solomon in Jesus mighty name. Congratulations Sir!
Sir. Your wishes, desires, and plans to the development of Ogbomosho township will be granted by almighty.
Congratulations sir
To God be glory, honour and majesty. A ku oriire lOgbomosho, igba yi a san wa loruko Jesu. Big congratulations to us all.
Congratulations kabiyesi
Reverend Laoye gunwa s'ori ite after to moye je👍
❤❤❤❤❤❤
Congratulations to BRO GBILE AKANI
Light has come to ogbomoso land
Am so impressed that he spoke yoruba, and the way he was playing with the irukere tip was very funny. Well, a de inu oko a Simi the land of my birth.
❤❤❤❤❤
Congratulations

💜💙💚💛🧡💯