WỌ́N GANU SÍ I - ÀWỌN ALFA BÍNÚ TÁN SÍ WASIU AYINDE

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 5 ก.พ. 2025

ความคิดเห็น • 40

  • @HolleylekVentures
    @HolleylekVentures 9 วันที่ผ่านมา +1

    Baba wa awikoko akanda oro, won ti soro, won ni soro tan, ilu gangan ni oro yii ologbon lole jo omo ran ni mon 😅

  • @olaayoola99
    @olaayoola99 9 วันที่ผ่านมา

    Good talk Awíkonko!!!!

  • @LewisMuturi-b7u
    @LewisMuturi-b7u 9 วันที่ผ่านมา +2

    Aye àwọn àjèjì ọmọ irankinran Gambari-Fulani yi o ni da ni aṣẹ Edumare

  • @adegokeusman8225
    @adegokeusman8225 9 วันที่ผ่านมา +1

    You have said it all by saying none of the Alfas ganu si.Based on this fact I must subscribe to your chanel ❤❤❤❤❤❤😂😂

  • @adedapoadedokun1922
    @adedapoadedokun1922 9 วันที่ผ่านมา

    Baba Awikonko Ododo ôrô PONBELE, E seun lopolopo sir Baba

  • @Olaolla902
    @Olaolla902 9 วันที่ผ่านมา

    Ko ti e fi shere
    Ee ri oju to ffi welcome won ni
    Oju talo peyin sibi
    Won tun maa lọ
    Let's wait and see
    Igberaga po si wasiu kole to ile ę koda ko to awujo orin
    Waiting for apa toku
    Weldone awikonko❤
    Mtcheew 😊

  • @miconentertaiment2821
    @miconentertaiment2821 6 วันที่ผ่านมา

    Awon alfa ganusi

  • @raymondadex5908
    @raymondadex5908 9 วันที่ผ่านมา +1

    Awikonko is an advanced Olote. Why was he talking like Alfa now? I couldn't stop laughing. 😂😂😂😂 Oga you bad ... Lol

    • @LewisMuturi-b7u
      @LewisMuturi-b7u 9 วันที่ผ่านมา

      He is a stupid Yoruba liberal

  • @papat2233
    @papat2233 9 วันที่ผ่านมา

    I am known by my colleagues of coming to the office with different Nigerians' slangs... haven used "Ganusi" in the over 30 times in a day in the office, everyone wants to know the meaning of "Ganusi."

  • @RolynRolyn
    @RolynRolyn 9 วันที่ผ่านมา +1

    Ganusi season go long ooo

  • @kktv4240
    @kktv4240 9 วันที่ผ่านมา +3

    Omo oko ile yoruba ni mayegun, ki awon alfa nah ye so asa ile yoruba di ti Saudi Arabia, ki won lo wa ise se,ise agbe ni ise ile wa, whala awon asesin mo ni ise ti po ju,ki lo de ti won hun da ile yoruba ru, gbogbo hun kan to ma pa ile yoruba Lara ni won hun gbe wa,ni igba ti won hun bu oni ife, me lo awon alfa lo da won le kun, omo ale ile yoruba ni kan lo ma bu k1,gbogbo awa omo oko ile yoruba hun so pe ki won lo wa ise se ki won fi asa ile yoruba si fun wa.

  • @Last9jadon
    @Last9jadon 9 วันที่ผ่านมา

    They are taking this too seriously. Wasiu has freedom of expression .

  • @JunaidOluyemisi
    @JunaidOluyemisi 9 วันที่ผ่านมา +1

    Won ganusi joor,kini won ba ka?? e ti mo pe ase orisirisi asee lo wa lenu awon omo olorin ibi ti Wasiu ro si ko ni won ba tunmo e si,e je ka ba awon alfa na so otito oro ki won ye toju bo ile olounje kiri bi elebi ki awon ye nse bi alagbe eba kiri ibi inawo oninawo

  • @Bjcrypto545
    @Bjcrypto545 9 วันที่ผ่านมา +1

    Awon Alfa Ganuwiyy😂

  • @olufemiolufemi2465
    @olufemiolufemi2465 8 วันที่ผ่านมา +1

    How did the video come out ?

    • @Awikonkotv
      @Awikonkotv  8 วันที่ผ่านมา

      Very good question which I also asked Sir? Who recorded it and for what purpose? Why posted it?

  • @kehindejosephkashimawo9410
    @kehindejosephkashimawo9410 9 วันที่ผ่านมา

    Gbogbo ọkùnrin ló fẹ́ràn obìnrin.. Ní pàtàkì àwọn olorin.. Gbogbo wọn pátápátá.. Àti àwọn tó ti dàgbà gan.., nigbati wọn wá ní Ṣango òde. Ní mo rí woman kan tó ní òun mọ Alhaji dáadáa, gẹ́gẹ́bí ó ṣe pé Wasiu K1.. O wa bere sii sọ̀rọ̀ nípa àwọn ìyàwó.. Ẹnìkan ló ṣe birthday fún, ẹ ìkànnì kò ṣe fún.. Ẹnìkan bímọ ẹnìkan ó bímọ.. Bo se ri fún àwọn olorin nìyẹn.. Wọ́n o need láti toast kí àwọn obìnrin tó máa wá wọn. Ìyẹn loun wá gbé tó fi ńṣe show.. Mí ò rí ẹ̀kọ́ kankan tí ìyẹn kọ́ wa.. Mo stop ni nigbati mo wò díẹ̀ lórí Árábà Tv. Mo fi comment sì pe ko sẹni tí kò like obìnrin. Ayafi bí a bá kan ń tan ara wa jẹ́ ní.. Olúkúlùkù kan ń kó ra rẹ̀ ni ìjánu nítorí wàhálà àti bukata tí yó tíbẹ̀ jade ni.. Baba Ebenezer Obey gan sọ jáde nínú interview kan pe: "I have children out of wedlock".. Ẹ wo bàbá wa Sunny Ade náà.. Ìyàwó wọn pọ̀.. Ọmọ Ibo kan gan jẹri sii tó gbọ́ Yoòbá gan.. Ẹnu rẹ ni mo ti gbọ́ pe: "Sunny Ade, Sunny Ade!! Ìyàwó pọ̀.. Aaah! Ìyàwó pọ̀.. But he is a nice man,, he is a nice man..". Iyẹn ńkọ́?

  • @adeadeyemi5101
    @adeadeyemi5101 9 วันที่ผ่านมา +2

    K1 is 68 year old. How old are all these alfas? He’s old enough to father many of them. How old are all the Alfas insulting him because he entered Ipebi in compliance with Yoruba tradition when he became olori omo oba?

  • @emmanymatthew2539
    @emmanymatthew2539 9 วันที่ผ่านมา

    Awon eniyan Ganduje, Ganucious, Ganusi…

  • @kktv4240
    @kktv4240 9 วันที่ผ่านมา +1

    Asa yoruba ni awon alfa hun ja gba, ki won lo wa ise se, awikonko stop giving asesin mo ni ise ni power, k1 hun se oju awa omo oko ile yoruba,se igba ti won ba hun fi seria ke yin lowo ati ese le to ma mo pe ale jo oran ni awon fulani to da po mo iran yoruba ti won hun fi enu ba gbogbo asa ati ise yoruba je, won si ye ma je ni Ara yoruba.

  • @WasiuIbrahim-rs6sr
    @WasiuIbrahim-rs6sr 9 วันที่ผ่านมา

    Please help us tell all the Alfas to forgive Wasiu Ayinde, o she mistake Oro ni.

  • @WaleWale-d7y
    @WaleWale-d7y 9 วันที่ผ่านมา +1

    You usually contradict yourself.

    • @Awikonkotv
      @Awikonkotv  9 วันที่ผ่านมา

      @@WaleWale-d7y
      Yeah to some foolish, ignorant and gullible like you.

  • @ytimi5231
    @ytimi5231 9 วันที่ผ่านมา

    Alfa ,ewo ni tepe, ibinu si omolakeji o kan epe ati oro bi ase. K1 was just talking carelessly. Folks, forgive him and stop escalating the "ganusi" slang by K1.

  • @kafilatsaka2992
    @kafilatsaka2992 9 วันที่ผ่านมา

    Honestly,I DONT THINK WASIU MEANS ANY HARM BECAUSE THIS IS THE MAN THAT USES SLANGS EVEN IN HIS MUSIC.SOME OF OUR ALFAS SHOULD BE CAREFUL AND GO BACK TO THE HADITH OF THE HOLY PROFECT MUHAMMAD THAT SAYS THAT OUR ACTION SHALL BE JUDGED ACCORDING TO OUR INTENTIONS. WHO KNOWS INTENTIONS ONLY GOD. MAY ALLAH GUIDE US ALL AND NEVER FORSAKE US INSHALLAH 🙏🙏🙏❤

  • @WaleWale-d7y
    @WaleWale-d7y 9 วันที่ผ่านมา

    But you should realise he said it under his roof in the absence of Alfas For example anyone can say oloriburuku ni Buhari under his roof but can't say it publicly. It was a private discussion btw Wasiu and someone please.

    • @Awikonkotv
      @Awikonkotv  9 วันที่ผ่านมา

      @@WaleWale-d7y
      And didn't I said that?

  • @OlufunkeOyedele-si4vj
    @OlufunkeOyedele-si4vj 9 วันที่ผ่านมา

    Awikonko eku atunse, agba koni tan lorile

  • @kktv4240
    @kktv4240 9 วันที่ผ่านมา +4

    Awikonko please don't disrespect k1 Melo ni nu won ni k1 je egbe re ni nu won

    • @itclass7494
      @itclass7494 9 วันที่ผ่านมา

      Hmmm, what a way of thinking

    • @kehindejosephkashimawo9410
      @kehindejosephkashimawo9410 9 วันที่ผ่านมา

      Oun ti Awíkonko ń wí kọ́ nìyẹn.. Ko disrespect ẹ̀ rárá.. Awíkonko yànàná rẹ̀ dáadáa fún ẹni tó bá ní làákàyè tiwọn fi ngbé ọ̀rọ̀ yẹ̀wò

  • @abibodlogistics
    @abibodlogistics 9 วันที่ผ่านมา +1

    You just hit the nail on the head,Wasiu Ishola's problem is that he is proud,he never thought that he will become who he is today,after God,all thanks to late Dr Sikiru Ayinde Barrister who made him who and what he is today,it is that pride that made him start contesting with his God on earth Sikiru Ayinde Barrister.There is nothing anybody can do about this his problem,like the Yorubas says, Abaku Laso Ewure,Wasiu Ishola can never stop being proud and what makes it so sad is that all these stupid idiots that gathers around him will not tell him the truth and I pray that this is not what will send him to his early grave.

    • @user-iu3dq3ot4k
      @user-iu3dq3ot4k 9 วันที่ผ่านมา

      Who are dey to ask k1 to apologise ftom them? Have dey apologies from all insult they've said to our ancestors, our kings including Onirisa

    • @bigshok247
      @bigshok247 9 วันที่ผ่านมา

      K1 biggest problem are is fans because they will never see anything wrong in is wrong doing, The 2nd problem of every rich man in Nigeria because they never good people around them. Na only yes yes men always around them