OBA YORUBA DA

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 3 ธ.ค. 2024

ความคิดเห็น • 36

  • @adedoyinakanbi5677
    @adedoyinakanbi5677 10 หลายเดือนก่อน +1

    Omo Nupe je Kakanfo Yoruba. Arifin oni yoro. Oba Yoruba nfe omo fulani l’afin. Kakanfo fe omo urobo. Aiye Yoruba re e l’ode o.
    Ire ti d’aiye, asa ti d’a Apomu.
    Olori ti n’aja oko. E ri esin awon Olori Oba l’ori ero aiye lu’jara.
    Olori Onirisa, pelu ewu esin, idaji ara ni ihoho, ijo esin l’ese aya’ba l’oju awon ara ilu. Oba Yoruba we lawani fulani l’ori ite Ododuwa. O ni ko si Orisa, elegun o gbodo jade. Oba n’mu igbo l’afin. Awon agba ilu ni Yibo ni ki won fi se Aare orile ede. Oba fi Fulani je B’obajiro, won fi atoun’rinwa je olori ogun. Our leaders at both national and state levels are the problems facing Yoruba Land. Oluwa a gba wa k’ale l’owo won.
    Aare Laji, awon onile a gbe yin o. E ku ise o.

  • @omolaraayo3405
    @omolaraayo3405 9 หลายเดือนก่อน

    Yoruba Nation is the solution

  • @niniolaolamilekan8275
    @niniolaolamilekan8275 10 หลายเดือนก่อน +2

    YORUBA NATIONA IS THE BEST 👌

  • @comfortadeleye128
    @comfortadeleye128 10 หลายเดือนก่อน

    ESE PUPO AARE OTIROPE OUn MON AWON ALAGBARA TOBAYA AAMA SOPE WONBI OUN NILERE WONTUNKO OUN
    OHANLARAE , RADARADA TOFINKO AWON OMOE

  • @sanitempleprayer472
    @sanitempleprayer472 10 หลายเดือนก่อน

    Awon ti nfi adua da aarin yoruba ru
    Ko sinmi eyin odo egbarajo egbarayin sile lowo ota laiduro de asiwaju kankan

  • @niniolaolamilekan8275
    @niniolaolamilekan8275 10 หลายเดือนก่อน +2

    YORUBA NATIONA NO GOING BACK

  • @emmanuelabiodun9749
    @emmanuelabiodun9749 10 หลายเดือนก่อน

    God bless you sir, as you are hitting them almighty olodumare will be with you sir pls keep it on

  • @MikhailAwolowo-zm7fr
    @MikhailAwolowo-zm7fr 10 หลายเดือนก่อน +5

    Ao ni Oba nile Yoruba mo. Lehin Oba sir Adesoji Aderemi ati Oba Lamidi Adeyemi the 2nd, ko si Oba mo. Awon gbewu dani lo ku. Awon ti won ko le da ijoba aafin won se.

  • @olurotimiadepitan5087
    @olurotimiadepitan5087 9 หลายเดือนก่อน

    Won fun won ni security vote lati pa won lenu mo. O ma se o.

  • @sanitempleprayer472
    @sanitempleprayer472 10 หลายเดือนก่อน

    Ijoba naijiria kise fun tiyin ti eba fe egbaradi ni gbo gbo ona ki egbara orile ede yoruba nation bayi

  • @MikhailAwolowo-zm7fr
    @MikhailAwolowo-zm7fr 10 หลายเดือนก่อน +3

    Aare ona kakaogogoro, oti lord ati schnapps.

  • @MikhailAwolowo-zm7fr
    @MikhailAwolowo-zm7fr 10 หลายเดือนก่อน +8

    Ooni of ife ti lo si Bowen University lati lo deliver speech. Ibi to wa important si Ooni lo ti lo soro yen. Nse lo fi wa gun lagidi. Awa naa si ti mo iru eeyan ti won fi je Oba. Misgovernance of the crown king.

  • @adeosunadebayo7145
    @adeosunadebayo7145 10 หลายเดือนก่อน +2

    Truth is bitter, continue telling them,fear not because God has endowed you with the knowledge of telling Yoruba history, culture and traditions You are unique and thank God you are there for the Yoruba race and cause.

  • @muritalabello8653
    @muritalabello8653 9 หลายเดือนก่อน

    God blessed you

  • @anthonyfresh321
    @anthonyfresh321 10 หลายเดือนก่อน +1

    Mr Laji Kudos to you please tell all our kings we are tired of them now nice one

  • @MikhailAwolowo-zm7fr
    @MikhailAwolowo-zm7fr 10 หลายเดือนก่อน +1

    Aare Ona kakaeba ati ewedu.

  • @chukwuemeka1202
    @chukwuemeka1202 10 หลายเดือนก่อน

    Yoruba Bo, won ni Iku Ti n pa ojugba Eni, Owe nii Pa fun ni, Ki Olorun Eledumare daa Abo Bo Awa Omo kootu Oojire ki Olorun ma se Oro wa bii Folorunso to lee nfi Okun Ogede gun Ope

  • @juliusiyiola1403
    @juliusiyiola1403 10 หลายเดือนก่อน +1

    Olorun olodumare ama wa pelu yin oooo. Oje oun to ba Yan ninu je pupo . YORUBA ROONU

  • @oladimejimichael-w1o
    @oladimejimichael-w1o 10 หลายเดือนก่อน

    Baba baba ooo, eo pe fun wa ❤

  • @SereabramSetlhako-pu2gk
    @SereabramSetlhako-pu2gk 10 หลายเดือนก่อน +1

    Baba yinka TNT doju ti asa yoruba otun dojuti esin nile yoruba haaa ko ya lo toro aforiti lowo awon elesin ati alale yoruba

  • @olayinkanjoku2205
    @olayinkanjoku2205 10 หลายเดือนก่อน +2

    ❤❤❤❤❤

  • @olorunfemifemi3897
    @olorunfemifemi3897 10 หลายเดือนก่อน

    ÁRẸ́ ÒLÙPÌTỌN BÁBÀ MÌ LÁJÌ ÁBÀSÌ MÓ GBÀ FÙNỌ́ ÀGBÁ RẸ̀ YÓ DÀLẸ́ ❤❤❤❤👏👏👏👏👊👌👌🍎👍👍

  • @PeterKolaTaiwo
    @PeterKolaTaiwo 10 หลายเดือนก่อน +1

    Eku Eto....Are

  • @olabisisanusi9601
    @olabisisanusi9601 10 หลายเดือนก่อน +1

    Ekaro gbogbo omo ile yoruba pe ki gbogbo wa parapo kadi okan kamo wipe ani eyon kan kan afi olorun ani president ani governor asi ni government

  • @abdulmajeedabdullahi9406
    @abdulmajeedabdullahi9406 10 หลายเดือนก่อน +1

    God bless you sir

  • @yettiefash7425
    @yettiefash7425 10 หลายเดือนก่อน +2

    The last time the youths came out were they not killed carrying Nigerian flag?!

  • @travelfar2306
    @travelfar2306 10 หลายเดือนก่อน

    Eku eto baba amo ipade lobaloba abi ipade governors o ni nkan kan se pelu ile yoruba abe fulani ni gbogbo won wa nkan to le se yoruba lan fani ni referandom yato si yen yoruba n tan ara won ni baba e ke gbajari referandom ona abayo kan to wa niyen oodua agbe wa o

    • @olurotimiadepitan5087
      @olurotimiadepitan5087 9 หลายเดือนก่อน

      Referendum kankan ko le bosi nitori ko si ilana yen ninu constitution Nigeria. E je ki a dekun ifakoko sofo. A ni eto lati da duro. Ohun kohun to ba gba la maa fun.

  • @oyeyiolaoladipupomutiu4862
    @oyeyiolaoladipupomutiu4862 10 หลายเดือนก่อน +1

    E ku eto oooo

  • @hardesojihardebukola3327
    @hardesojihardebukola3327 10 หลายเดือนก่อน

    All this problem doesn't have anything to do with the kings the speech Ooni made last year asking the government to include the kings and Bale's on governance, no any security under the control of the kings.

  • @yettiefash7425
    @yettiefash7425 10 หลายเดือนก่อน +1

    Una don talk am say na your papa go do am so make he do am now.

    • @Mr_Monicle
      @Mr_Monicle 10 หลายเดือนก่อน

      Bless you, l don't know why Are has so much confidence in Tinubu becos he is not for Yoruba yet he used Yoruba Nation to get APC ticket. Can Aare Opita.n tell us what Tinubu is doing in France. If he cares to know, he is the future of generations to come to France.

  • @Majority33
    @Majority33 10 หลายเดือนก่อน

    I am just laughing watching this "oro isiti" video. Aare, is really ryled up.
    Well, Yoruba traditions have shifted and we are acting worse than our present-day African Americans brothers who are looking up to us for development in unity to save them in America. Our sense of community has become individualistic materially. We want to be more westernized than the West.
    Sh-ame on us. Ask our brothers to do something for you, you have entered their trap.
    For me, I have given up on Nigeria and my Yoruba brethren. They don't mean well.

  • @jessicawilliam5206
    @jessicawilliam5206 10 หลายเดือนก่อน +1

    😂😂

  • @RasheedatAkinloye
    @RasheedatAkinloye 10 หลายเดือนก่อน +1

    E ku eto