LOBATAN: EWAGBO OHUN TI SAIDI SHITTU BA IYAALAJE SO NIPA MUYIDEEN ATI AGBALA GABRIEL ATI ALFA LEGBA

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 10 ก.ค. 2024
  • #yorubanation #oyostate #agbalagabriel
    LOBATAN: EWAGBO OHUN TI SAIDI SHITTU BA IYAALAJE SO NIPA MUYIDEEN ATI AGBALA GABRIEL ATI ALFA LEGBA

ความคิดเห็น • 47

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni9463 28 วันที่ผ่านมา +5

    Iyalaje courtroom, the great Oniwaasi Agbaye 😂🤣😄😂🤣😄

    • @yemisioladapo2011
      @yemisioladapo2011 28 วันที่ผ่านมา

      🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣

  • @taiwomorakinyo1463
    @taiwomorakinyo1463 28 วันที่ผ่านมา +3

    Legba gbogbo epe to se o ma pada je ti ee ati awon omo eeni ase ti Olorun, aimoye oborin to ni iju to de bi omo repete, ti o ba lo loyun , iru omo bi muyideen ti ko mo ore, oloju kokoro lo ma bi, ikunle abiyamo lo yo iyawo ninu wahala ati idamu, ibukun mo ba ee dupo ooo Olorun ma se irin ajo ee ni rere ni oruko Jesu Oluwa wa, Amiin.

  • @KoGoodnews
    @KoGoodnews 28 วันที่ผ่านมา +2

    Ise lo n yo alfa legba lenu.E je ki oto ola wo,a yi ohun pada

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 27 วันที่ผ่านมา

    Legba, Nitoripe o fi Fibroid bu Ibukunoluwa, Afaa Legba o ti jebi Olorun. 😮

  • @monisolalawal4131
    @monisolalawal4131 27 วันที่ผ่านมา

    Muyideen ko sise aje ri now bawo le se fe ko ri kole mo iyi owo now arungun

  • @oluremiabioye7877
    @oluremiabioye7877 28 วันที่ผ่านมา +1

    Iyalaje kudos to you ma for your program.

  • @oluremiabioye7877
    @oluremiabioye7877 28 วันที่ผ่านมา +2

    Oloriburuku ni alfa legba yi. Iwo ati idile na ma rare ku lagbara Olorun.

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 27 วันที่ผ่านมา

    Legba, gbogbo awon omo re obinrin lo ma ni fibroid lagbara Olorun. Legba, oo ni Jere ise e.

  • @abasssalami9252
    @abasssalami9252 28 วันที่ผ่านมา

    I don't why just like your message big sister God bless you more

  • @lawalrashidatanikeanike2477
    @lawalrashidatanikeanike2477 26 วันที่ผ่านมา

    Iyalaje ekueto olorun amafunyin se kolorun sanuwa loroyi

  • @Oluwabukola977
    @Oluwabukola977 28 วันที่ผ่านมา +1

    Human right should arrest ajigini,others and muyideen for faking human right office,it is a big crime ma. The first day I heard the voice the people in the so-call human right office,I swear immediately that it was a set up by ajigini. Why didn’t they show there faces like oriyomi hamzat use to do because it should be an open court for people to see everyone

  • @amuwahelen9880
    @amuwahelen9880 26 วันที่ผ่านมา

    Oode, oponu ni Alfa yii, se Nnamdi Kanu to wa ni Prison, se Prison ni Muyideen wa, ti o n wa freedom,

  • @abosedeade-alarapon8524
    @abosedeade-alarapon8524 26 วันที่ผ่านมา

    😂😂😂😂😂😂 Iyalaje oooo

  • @Oluwabukola977
    @Oluwabukola977 28 วันที่ผ่านมา +1

    The freedom muyideen is trying to say is that he knows that he can not buy smoke and Ogogoro and be smoking inside,outside and beside his house as he taught he will be doing,just because he has freedom under the bridge to smoke any time,anyhow without anybody disturbing him. Muyideen know that he won’t be able to do all those things there.that’s why she’s talking about freedom because all smokers,smoke around there environment

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 27 วันที่ผ่านมา

    Ha! Eyin Afaa ti e gba muyideen sodo, including iwo Legba, gbogbo epe ti o se fun Ibukunoluwa maa pada sie lori tomotomo ati awon family e lagbara Oluwa.

  • @monisolalawal4131
    @monisolalawal4131 27 วันที่ผ่านมา

    Iyalaje Olohun ama fun yin se. Emo pe social media yi ko eran mero de owun ti mo Ola tie ati ti awon omo e o gbodo toro aforiji lowo Ibukun iyawo muyideen gbogbo nkan to nso yen inu Olohun ko dun si kini omo Ibukun yen se fun to fin de epe fun omo ti ko se e omo to ri ri ti ejo soro ri

  • @titilayooyinloye2994
    @titilayooyinloye2994 28 วันที่ผ่านมา

    Iya Laje don't become accuse. Mami you are really funny 😂😂😂😂

  • @olayinkatejumade3232
    @olayinkatejumade3232 28 วันที่ผ่านมา +1

    Iyalaje e ma pami o

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 27 วันที่ผ่านมา

    Legba is a sick man

  • @adeyinka140461
    @adeyinka140461 28 วันที่ผ่านมา

    Great job

  • @AdebisiAina-gz6fp
    @AdebisiAina-gz6fp 27 วันที่ผ่านมา

    They should give muyideen one wife from there side and leave agbala Gabriel Alone oo

  • @OmobamiOlaifa
    @OmobamiOlaifa 27 วันที่ผ่านมา

    Hmmmmm fibroid ko ni ko ma bi Mo. Alfa e ki se Olorun.

  • @JulietAyekulehin
    @JulietAyekulehin 28 วันที่ผ่านมา

    ❤❤❤❤

  • @afolayandavid8179
    @afolayandavid8179 28 วันที่ผ่านมา

    😂😂😂 This woman ehn!!!

  • @sammyjboy1
    @sammyjboy1 26 วันที่ผ่านมา

    Firstly why this Legba is doing this is because he already have an agreement with muyideen not for him to receive his own share the wife have to leave the house so that it will be easy to sell the house but because the lady refuse that why he is angry . Ara owo loun ta Alfa.

  • @olabodeolajuwon4318
    @olabodeolajuwon4318 28 วันที่ผ่านมา

    Legba ma bere ija ninu flight ni abunu eeyan alailori pipe

  • @ahmedadeleke1722
    @ahmedadeleke1722 28 วันที่ผ่านมา

    Iyalaje yi o nyce atallatall aarra ara😂

  • @lawrenceakinadeadesanmi2017
    @lawrenceakinadeadesanmi2017 28 วันที่ผ่านมา

    O ye ki iyawo muideen yen gbe okunrin alfa yen losi ile ejo

  • @WuraAkinbo-ri8sy
    @WuraAkinbo-ri8sy 28 วันที่ผ่านมา

    Ashitani Ni ALFA

  • @user-iu6bs2re6j
    @user-iu6bs2re6j 28 วันที่ผ่านมา

    Alfa legba ko ni alafia rara, ara re ko ya

  • @WuraAkinbo-ri8sy
    @WuraAkinbo-ri8sy 28 วันที่ผ่านมา

    You are so funny, Mummy, Those Alfa they are so terrible

  • @user-og7bq2hc2p
    @user-og7bq2hc2p 28 วันที่ผ่านมา

    😂😂❤❤

  • @joyolofintuyi1336
    @joyolofintuyi1336 28 วันที่ผ่านมา

    I am sure Ibunkun did not sign to marry a Gambler most Christian are not Gambler for that alone Ibunkun should divorce that man. Freedom to smoke weed GOD forbid

  • @DasolaTurayo-gc1tz
    @DasolaTurayo-gc1tz 27 วันที่ผ่านมา

    Legba muyideen legba mimo e si afa rara afa gidi ti awa mo akeu gbagodi afa mudeen ajani bello ati awon afa meta timo moni ori sosa media tiwon so otito afa iwo otito loju awon afa gidi sipo ninu aye awon ti awa moni afa gidi niye legba fosiso arigini woja yawere muyideen eyi kise afa gidi rara esu ni eyi mererin ati gbogbo eyi alatileyi muyideen eti ya were aye koni da eniri batise eni ri ona gbegba gbogbo awon omo ti o tinu yi jade gbogbo won ni won ma ni faburod ti alale bani koda fun eyi mererin ati idile yi ema sofo tiron tiron taya taya ibinu olorun ma so kale le yi lori ema pada toro je gbeyi aye yi ni eyi bun omo eda adamo bitiyi eniti olorun ti eyi olori buruku yi kole da ewa fi enu soro odi si ibunkun oluwa pelu edun okan nimo fi se epe yi ti ale bani koda fun gbogbo yi alaro koni je koda fun gbogbo yi gbogbo owo ti e bagbe laburu lori ibunkun oluwa ati lori pastor ademola amusan ati lori iya laje eyi afa esu yi owo ti eba gbe niti aburu ori yi ori awon omo yi ori aya oun ni aburu yema pada si ti aye bamu eniyon olorun legba kale sungbo ti olorun ba binu si eniyon kosi enikeni afa woli babalawo ti o legba eniye sile torina fosiso arigini woja yawere legba olorun ma fi ara pamo je yiniya ojo ibinu olorun maro le yi lori ema damu ninu aye enise orire eyi alaye baje eyi kada towa ninu iresi eyi oni doti tiba awon afa gidi loju je eniyon gidi kan kole ri iru eyi afa esu yi ki Islam wun eniyon se ara awon afa oni doti bitiyi yi awon na ni won jeki kuro ninu musilim timo figba inu christen Muslim gidi to ki wati marun dede nimi tele timo de se asalatu dede sungbo olorun iwa buruku inu eyi musilim esu bi tiyi yi loje ki din oni sosi di eniyi eyi olori buruku afa esu alaye baje koni ragba fuyi eyi olofo to binu ologo emi mo nkan todun yi ole niyi ile ye lodun yi efeki won ta ile ye tori owo ti e feri ninu e lota yi lara ole niyi anini mufu olosa oko shina rainbow oun ni legba fosiso arigini woja yawere muyideen ole ni gbogbo yi enikure eyi alaye Kaye

  • @user-zt2hq2mq1f
    @user-zt2hq2mq1f 26 วันที่ผ่านมา

    ENU Alfa legba yeleyele bi eni fa aso ya. KO mo nkan tofe so, he is trying to belong, through Muideen's case. He is an idiot.

  • @ditty6828
    @ditty6828 28 วันที่ผ่านมา +2

    😂😂😂😂😂 omokunrin yen ni arun opolo bi ti mufti oluwo. 😂😂😂😂 Se arabic lo nso abi ede ilu wo lo nso lénu sef?. Nigba ti won lopolo. Afi jagidijagan.

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 27 วันที่ผ่านมา

    Alabosi ni Legba 😮

  • @BossaFola
    @BossaFola 28 วันที่ผ่านมา

    Ni agbara Olorun, ti ogo ban je ti Olorun ti yoruba ba da duro tan ani lat reform religion in our yoruba land been you Christian and Muslim, my question is who made this Idiot alfa? Because he lack of wisdom

  • @KoGoodnews
    @KoGoodnews 28 วันที่ผ่านมา

    Ise lo n yo alfa legba lenu.E je ki oto ola wo,a yi ohun pada