Maami ko si aponle kànkàn fun obà ti koni olori Lamidi omoboriowo Sangolere a.k.a Bola Tinubu ti o paro oruko jiję gbogbo ohun ti o nwo ti o ndun mo n'inu o ma di ipanuję ogbę ati ękun 😭😭😭 lailai fun Lamidi Amuda omoboriowo Sangolere a.k.a Bola Ahmed Tinubu lati iran kinni titi de ikęrin o hu iwa ni ayilanu o di dàndàn ki a se idajo Amuda omoboriowo Sangolere a.k.a Bola Ahmed Tinubu ni asi Anu kànkàn t'iran t'iran ni Aşę Olodumare Amiiin Amiiin Amiiin
Kosi igbadun fun ika ęniyan kosi ilera idunu tabi iyi kànkàn fun Lamidi Amuda omoboriowo Sangolere a.k.a Bola Ahmed Tinubu titi opin aye rę nitori ko fun àwà Omo yoruba ni işinmi kànkàn
Lamidi Amuda omoboriowo Sangolere a.k.a Bola Tinubu wa segbe t'omot'omo t'omo'mo t'idile t'idile nitori o fi iyalaya iya ję gbogbo awón iran Yoruba sugbòn wa ko ere işę ikà ibi ati odalę owo 👐🏼 rę ni y'iye ni k'iku ati bi Olorun ti mbę ti Ęmi Rę si ti njobà Aşę Edumare Amin
Gbogbo oro ti e nso yi o ran Tinubu. Ko ni ero lati se daada fun ara ilu rara, e ye fi akoko yin sofo. Yoruba Nation no going back iye ni ke je ka ma so e jowo
Mama good talk, God will protect and bless u.
Amin Ase Edumare
Yoruba Nation no going back oo ooooo
Amin
Maami ko si aponle kànkàn fun obà ti koni olori Lamidi omoboriowo Sangolere a.k.a Bola Tinubu ti o paro oruko jiję gbogbo ohun ti o nwo ti o ndun mo n'inu o ma di ipanuję ogbę ati ękun 😭😭😭 lailai fun Lamidi Amuda omoboriowo Sangolere a.k.a Bola Ahmed Tinubu lati iran kinni titi de ikęrin o hu iwa ni ayilanu o di dàndàn ki a se idajo Amuda omoboriowo Sangolere a.k.a Bola Ahmed Tinubu ni asi Anu kànkàn t'iran t'iran ni Aşę Olodumare Amiiin Amiiin Amiiin
baba please listing what is hapining in this country na we are surfring na abeg baba
Kosi igbadun fun ika ęniyan kosi ilera idunu tabi iyi kànkàn fun Lamidi Amuda omoboriowo Sangolere a.k.a Bola Ahmed Tinubu titi opin aye rę nitori ko fun àwà Omo yoruba ni işinmi kànkàn
Yoruba Nation la wa fe bayi ooooo ni kia kia
Lamidi Amuda omoboriowo Sangolere a.k.a Bola Tinubu wa segbe t'omot'omo t'omo'mo t'idile t'idile nitori o fi iyalaya iya ję gbogbo awón iran Yoruba sugbòn wa ko ere işę ikà ibi ati odalę owo 👐🏼 rę ni y'iye ni k'iku ati bi Olorun ti mbę ti Ęmi Rę si ti njobà Aşę Edumare Amin
Mama wa, Oluwa a je ki e pe fun wa, Yoruba Nation yi asoju emi gbogbo wa
Yoruba Nation la fe lai se afira
Iyen ti di dandan lase Edumare
Adura ki won gbe iyawo ati omo kan ni a gba o ki won le mo bi ose nri fun awon eniyan
Sugbon o ni opolo gidi oo, ti o la bawon, oun ti won mo se ni won se yi oo, ko la fi we e oo
Gbogbo oro ti e nso yi o ran Tinubu. Ko ni ero lati se daada fun ara ilu rara, e ye fi akoko yin sofo. Yoruba Nation no going back iye ni ke je ka ma so e jowo
Bawo le se nfe ki ise iyawo yato si ti oko, nigbati omo paapa nse ribi ribi lati ni gbogbo awon oloja lara, gbogbo ebi won lo nse ijoba yi
Iyawo na ko ni aanu loju rara to n se eniyan rara, o buru ju oko e lo
Otito asiko lati tu asiri iya to bi to ba gbogbo ilu je bayi
E wo eje ka soro nipa ibi ti a nlo, e fi baba yi sile
Inu gbogbo wa a dun ti e ba ri gbe o, ati gbogbo awon a mugba legbe ti won nba won sise
Won lo si china lo tun fi wa si oko eru omiran nipa oro ino mono mono
Ko si baba nile lati da yin loun pipe ti e n pe won mama
Won i ti san n oo
Won ti gbe e wo oo
LadyK
Ti won ba fun ni imoran, ko ni gba, sugbon eni ti o ba ni okan ti Olorun, a kuro ninu iru ijoba be
Ton ba ri he, ki lo na yin?
Won ti ge baba leti lo