Hmmm yoruba movies ti dorikodo kini di. Ibo ni awon ijinle yoruba yii Wa ati awon Agba osere yii Wa ooooo Baba wande Baba ti oro Won ma n pawa leerin. Very soon now to me I will stop to watching yoruba movies bcos there is no lesson in yoruba movies again. Bcos I like my language yoruba yoruba I can never 4geting home ojopagogo welldone sir dat is why i like u 👍❤
Mo kí yín Alàgbà Olayiwola Rasaki Ojopagogo fún ìṣe ńlá yí. Laakaye yín ó ní jooba láéláé lágbára Olódùmarè a àṣẹ. ÌKÒKÒ omi ọgbọ́n Imọ àti òye yín elegbara ayé ó ní fo lórúkọ Jésù Kristi àmín. Mo ní àwọn ìbéèrè méjì sí mẹta. 1. Kin ni wọn máa ń fi Adìẹ Irana ṣe leyin ti wọn ba ti gbé òkú de ìtẹ́ tán, ṣe jíjẹ ni àbí wọn yóò pá sì orí saare òkú??? 2. Ǹjẹ́ o yẹ kii Obìnrin máa bímọ sì ilé ọkọ méjì sí mẹta, gẹgẹ bí Iyawa Ibiyemi ṣe see nínú sinnimo Tagiri??? 3. Ǹjẹ́ bí igbẹyin àwọn Obìnrin tí ó bá bímọ sílè ọkọ méjì sí mẹta gbogbo ṣe máa ń rí ní igbẹyin Ibiyemi ṣe rí yí nínú sinnimo Tagiri yí??? Ẹ jọ̀wọ́ mo fẹ́ ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè mi yí, yóò dára fún yín, ilé isẹ yín ó ní jóná, Olúwa kò ní fí èyí ṣe òpin fún ilé isẹ yín lórúkọ Jésù Kristi Olúwa wa àmín.
Obey Adesoji ,e seun alagba, Idahun si ibeere yin akoko, won ma n pa adie irana yi, nigba ti won ba gbe oku de ite, eje adie yi ni won a ro si ara igi ti won ma fi n bo oku mo koto ki won to da erupe boo, jije si ni adie yi fun gbogbo eni ti o ba ni ife si lati je. Owe kan fidi e mule pe won ma n je e ni "ADIE IRANA KII SOHUN A JE GBE " idahun si ibeere keji Ko ye. Idahun si ibeere keta, kii se bee o, ohun to koju senikan eyin lo ko selomii, iriri ati ona ti kaluku gba fi sile oko ka yato sira won, oun lo si le toka si irepo ti yo wa laarin awon omo ti o ba bi kiri, gbogbo won ko ni igbeyin won le ri bi tibiyemi. E seun a dupe o, e ku ife, Olorun a ma bu kun ile ati ona yin ati gbogbo eni to n darapo mo ikanni yi. E SEE PUPO.
Hmmm yoruba movies ti dorikodo kini di. Ibo ni awon ijinle yoruba yii Wa ati awon Agba osere yii Wa ooooo Baba wande Baba ti oro Won ma n pawa leerin. Very soon now to me I will stop to watching yoruba movies bcos there is no lesson in yoruba movies again. Bcos I like my language yoruba yoruba I can never 4geting home ojopagogo welldone sir dat is why i like u 👍❤
Very interesting movie 🎥🍿🍷🌹👍🤝
Kudos sir. Pls help us upload ranti ile, Timo baje olorun
This is good job, kudos to the writer and all the actors and actress. More wisdom to you guys IJN
This move is really interesting and educating, well done guys 😊
Very interesting, well done ✅
Very interesting and Educative 💯
Hmmmm Enibimo omo nio sin enitio bi gan won ni so oku e fun aja, kosi ountio leere ibiyemi jeere agbeere. Meemah OSF
Gabriel afolayan,well done
To say I knew when this movie came out then,but am just seeing it
This is educative. Kudus to all the crew. Thanks so much
Wow wonderful movie
I never regret watching this movie 🎥, OSF
Wow so interesting
Thanks for uploading this wonderful movie
Wonderful movie and good actors
Hmmm! Very lnteresting and educative movie
❤
Nice movie
OSF
Just watching this❤️
Wow nice One, so interesting, Secam OSF
hmmm
Mo kí yín Alàgbà Olayiwola Rasaki Ojopagogo fún ìṣe ńlá yí. Laakaye yín ó ní jooba láéláé lágbára Olódùmarè a àṣẹ. ÌKÒKÒ omi ọgbọ́n Imọ àti òye yín elegbara ayé ó ní fo lórúkọ Jésù Kristi àmín. Mo ní àwọn ìbéèrè méjì sí mẹta. 1. Kin ni wọn máa ń fi Adìẹ Irana ṣe leyin ti wọn ba ti gbé òkú de ìtẹ́ tán, ṣe jíjẹ ni àbí wọn yóò pá sì orí saare òkú???
2. Ǹjẹ́ o yẹ kii Obìnrin máa bímọ sì ilé ọkọ méjì sí mẹta, gẹgẹ bí Iyawa Ibiyemi ṣe see nínú sinnimo Tagiri???
3. Ǹjẹ́ bí igbẹyin àwọn Obìnrin tí ó bá bímọ sílè ọkọ méjì sí mẹta gbogbo ṣe máa ń rí ní igbẹyin Ibiyemi ṣe rí yí nínú sinnimo Tagiri yí???
Ẹ jọ̀wọ́ mo fẹ́ ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè mi yí, yóò dára fún yín, ilé isẹ yín ó ní jóná, Olúwa kò ní fí èyí ṣe òpin fún ilé isẹ yín lórúkọ Jésù Kristi Olúwa wa àmín.
Obey Adesoji ,e seun alagba,
Idahun si ibeere yin akoko, won ma n pa adie irana yi, nigba ti won ba gbe oku de ite, eje adie yi ni won a ro si ara igi ti won ma fi n bo oku mo koto ki won to da erupe boo, jije si ni adie yi fun gbogbo eni ti o ba ni ife si lati je. Owe kan fidi e mule pe won ma n je e ni "ADIE IRANA KII SOHUN A JE GBE "
idahun si ibeere keji
Ko ye.
Idahun si ibeere keta,
kii se bee o, ohun to koju senikan eyin lo ko selomii, iriri ati ona ti kaluku gba fi sile oko ka yato sira won, oun lo si le toka si irepo ti yo wa laarin awon omo ti o ba bi kiri, gbogbo won ko ni igbeyin won le ri bi tibiyemi.
E seun a dupe o, e ku ife, Olorun a ma bu kun ile ati ona yin ati gbogbo eni to n darapo mo ikanni yi. E SEE PUPO.