Ose, ose rere
ฝัง
- เผยแพร่เมื่อ 9 ก.พ. 2025
- OSE OSE RERE
1. Ose, oso rere,
Iwo ojo simi;
O ye k'a fi ojo kan
Fun Olorun rere;
B'ojo mi ba m'ekun wa,
Iwo n' oju wa nu;
Iwo ti s'ojo ayo,
Emi fe dide re
2. Ose Ose rere,
A k'yo sise loni;
A o f'ise wa gbogbo
Fun aisimi ola,
Didan l'oju re ma dan,
'Wo arewa ojo;
Ojo mi nso ti lala,
Iwo nso ti simi.
3. Ose, Ose rere
Ago tile nwipe,
F'Eleda re l'ojo kan,
T'O fun o n'ijo mefa;
A o fi 'se wa sile,
Lati lo sun nibe
Awa ati ore wa;
Ao lo sile adua
4. Ose, Ose rere,
Wakati re wu mi;
Ojo orun ni 'wo se;
"Wo apere orun;
Oluwa, je ki njogun
'Simi leyin iku;
Ki nle ma sin O titi,
Pelu eniyan Re.
#yorubahymn #singingstyle #singingministry #harmony
❤❤❤ Reminds me of Sunday service in my local church 😊😊😊
🙏🙏🙏🙏