AYE MUYIDEEN TI BAJE O - BO SE KO PETITION TAKO AGBALA GABRIEL
ฝัง
- เผยแพร่เมื่อ 15 ก.ย. 2024
- AYE MUYIDEEN TI BAJE O - BO SE KO PETITION TAKO AGBALA GABRIEL
SUBSCRIBE HERE👉 goo.gl/ypvoyF
Join this channel to get access to perks:
/ @drivetvnews
- Drivetv news
follow us on
FB:- @drivetvnews
IG:- @drivetvnews
TWEETER:- @drivetvnews
Ori buruku lo n tele Muideen Kiri. Oro re ko dunmi rara. God bless you sir. Alfa ise yin yi o ma lo siwaju. 11:56 Oriyomi Hamsat is number One on the list. Oriyomi Hamsat ma sesin gbeyin ni loruko Jesu.
Baba wa ema se o. Eyi ti o buru ju ni wipe Agbala Gabriel wa ninu Convention bayi. Pastor Gabriel. Dakun mase fi okan si jowo Jesu Christi ni kio fi okan sio. Pls don’t ever think about it. They were creating more great ness for you. My darling. My honey. My sweetie. Yu are a lover. I am over 70 yrs lives in USA. Iyalaje I love you too much. You are a darling. Eku ise Abiyamo.
Olododo kan koni ku sipo ika lailai. Ibinu Olorun tiwa lori Muyideen ati gbogbo awon alatilehin e. Judasi ati Hamani niwon. Alfa God bless you sir.
Thank you Alfa.You are truly a man of God.God shall continue to uplift you
This Alfa is a truly man of God, please Sir continue your good job Allah will reward you.
BI Lahi ladhi wa Robili Kaaba. I want to see this alfa and pastor Gabriel life bcos I love them beyond what could be described . May Allah bless Agbala and this alfa. Continue your good job sirs.
E seun o Baba bi e se duro ti Agbala Gabriel.Awon Omo yin a ma ri oju rere Olorun ati ti eeyan ni oruko Olorun Oba.Agbala Gabriel maa bori ogun yi lagbara Olorun Oba.
God bless u, Alhaja. am proud of u Sir, God bless u for speaking the truth, u are man of honour. I will like to know u..
Mr kehinde ati Agbala Gabriel olorun konidoju aduratiyin orunyio gbe yin nija oluwa olorun agbaye yio dide Ogun lori gbogbo enitio dide Ogun siyin Amin ni oruko jesu
Many Pastors and CAN supported Agbala Gabriel and they even went to his church without showing it on social media. Shalom
Muyideen enikeni eniakenia tio ba tun surport re lbanuje ni won ma fi lo ojo aiye won toku.won ko ni ri alanu mo ni oruko Jesu amin....
Alfa mogba adura fun yin ni oruko Jesu Kristi Oluwa wipe ati eyin ati awon omo ati omo omo yin Mari anu ati oju rere Olorun gba ni oruko Jesu Kristi Oluwa Amin 🤲🏻🙏🙌
BRAVO!!!👏🏼
Almighty Allah will be with you sir.
Thank you mr keyinde god bless you sir
Gbogbo enikeni ati eniyankeniyan ti won je alatikeyin Muyideen lo ma Sesin ni oruko Jesu Kristi Oluwa Amin 🤲🏻🙏
God bless you sir more wisdom 🙏🙏
Muyadeeni o leri ojurere Oluwa ati ti omo eyan mor rederede yen loma ba ku.
Alhaji Oriyomi Hamzart mo nipa case yi. I have the point to support it.
Baba it's well with you God will be with you in Jesus name
Oriyomi Hamsat is the foundation of this problems but God will judge everyone
You are mad for mentioning oriyomi in this
God bless you my dear brother 🙏. This is who we were as descendants of Oduduwa,but I believe God will take charge.
Thank you Alfa
Muideen ma sesin aworo gbehin ni, Oloriburuku eyan
Ese Alfa wa dada Olorun a san yin ni esan rere e se pupo Olorun a gbo adura yin Olorun a si duro ti awon ebi yin e ni se a se danu Olorun a gbe pastor bori ogun ti.
The great ingtate.
I like this man
Amin lolatitobi olorun oba
Salam alaekun alfa se ri oro yi osokunkun si gbogbo wa sugbon o han si olohun,emaje kadajo olohun ni yi o se dajo
God bless u sir for saying the true.
Gbogbo eyin oloriburuku pastors tie nbinu pastor Gabriel Ademola Amusan of agbala Gabriel olorun yio pale yin mo kuro loke erupe pelu ibanuje ni oruko Jesu amin adabi ti e ko ba nfi agbara imule se ise iranse nikan loku
Not pastor is the useless Oriyomi is looking for way to pull agbala down
Muideen so pe ohun le ta agbala Gabriel, ha osi Se be aiye le o.
E jowo Alfa, E ma je ki won wo Ile na lule nitori ise owo awon Omo Enia ni, ni Oruko Jesu Kristi esu Enia o ni da ere Owo awon Omo Olorun lule, mo daba pe ki won ma fi Ile rent, ki won si ma fi Owo re se itoju awon alaini. Jesu Kristi yio ran Agbala Gabriel lowo ati gbogbo awon oluranlowo re gbogbo lowo. E ku Eto Sir
Good job sir
Alfa God bless you sir, you're always truthful, oloriburuku ni muyideen were abe bridge soro were lenu se iru e lofe se adura fun eniyan, oloriburuku eleda Gabriel mafi iya je e ati awon Alfa ino to tele e kiri
Receipt wa lori bank App
Agba yi a dale baba
Every supporter of evil plan of Muyideen will be put to shame in Jesus name Amen 🙏
Amen
Thank you baba I love musim because of you baba God bless you
Don't love Muslim because of him because you will soon hate Muslim becos of others.
There are good and bad people everywhere. There are good Muslims and there are bad Muslims. You should naturally love good people and hate bad people. Do not connect love and hate to religion.
There are many good Christians and bad Christians. Once you love the good people, you will love the good Christians and the good Muslims. You will hate the bad Christians and the bad Muslims
Baba Eo ni mo boji Omo yin, gbogbo awon omo yin yio se rere laye pelu ogo Olorun Amin🙏
Thanks sir
Oloriburuku nwi kewu radarada, Omo ale Oloriburuku, Baba alfa e jere awon omo yin loruko Jesu
God bless you sir.
Alhaji Komaadun you need to take a trip to Agbala Gabriel
It shall be well with you sir
Muyideen amugho, onitete ati Iwo ati awon ti won wa leyin Muyideen ona won ti daru Olorun ko ni sanu gbogbo won, won ni ri anu gba ti omo ti omo ati aro mon domon won., won ni ni isinmi ni gbara Olorun.
Alhaji Oriyomi Hamzat mo nipa petition yen,Ki gbogbo awon iya arugbo ti MUYIDEEN naa ni inu shoshi naa jade ati awon ti o dabi ogbon ton ba charger won je ki won le wa ra imi,MUYIDEEN Folorunsho Ajigini Legba Anini Alabaru Bodija wa je segeh iya lodo olorun Oba
Awon alatileyin Muyideen Alabaru fe je ni ibi ti won gbin si 😂😂
Kudos to you ❤❤❤❤❤❤❤
Salam alaikum Alfa, May Almighty Allah bless you for saying the truth, Awon Alfa Ina,won fe lo muyideen ni,awon alfa kidnapper 😂😂😂
Oriyomi Amzat, alaseju, won ni nigbawo loode, oni odigbati ohun ba te.
Oriyomi tobasepe ooto ni gbogbo nkan ta ngbo nipa re niti oro Muyideen. Mofi Oloun be e ko lo jawo nisinyi o.
Omo Oloun soro baja o. Kilefe gba nibiti Agbala ba losi court ? Nje e ranti bi agbala se pade Muyideen . E ronun si kee to tese bo o Alhaji Oriyomi. Aabo Oro .
Muyideen Olori majadiye ,oriburuku logbewasaye ,kolesoriremolaye,iya losekufun muyideen
Adara fun yin sir. Who does that
Olorun a duro ti yin sir
BABA. E SEUN O, AYE YIN, ISE YIN, ORUN ALIKIYAMO ONIDERA YIN KONI BAJE LAGBARA OLOHUN AAMIN ASE.
So Muyideen has now turned a preacher! Wonders never end
EkuroLori Oro muyedeen Tori ni akoko muyedeen to so wipe oun Le ta Agbala Gabriel
Baba yi yoo Dara fun yin tomotomo
Mr. Kehinde please do not give out your plan please keep quiet and plan your strategy with Agbala Gabriel
Oloriburuku ni Muideen ati awon oloriburuku alfa to n gbe kiri. Olosi Muideen joye speaker Lori ayelujara
Ase gun muyideen ole ole omo ofo
O surprise mi wipe awon were alfa kan si wa lehin oloriburuku Muideen yi. George gan ma ran lewon gbere ni.
God bless you 🙏 baba
Gbogbo eni to ba support Muyideen Ko ni jere omo e gbogbo ise to ba se fi owo won se lo ma baje loju aye won pelu iwa we’re ti won nhu yi
Pastors will not come out to fight,Christian’s don’t fight their God.They pray to God and win battles.Most of Pastor will pray for their own and win.Dont be deceived,thousands of Christian’s are praying for Agbala Gabriel.
Ekuise
I love you sir
Epe ti ja muyideen ,lo se n sise
God Will Judge Everyone That Against Agbala Gabriel, Alfa Baba Olorun Ko Ni Pada Layin Yin Ni Oruko Nla Ti Jesu kristi.
Correct Alfa ride on
I mean the great ingrate
May almighty Allah 🙏 continue to be with you sir
Muyideen ko le ri alanu mo. He should go and work.
Baba e ni tan ke to tan lagbara olorun
Alfa,ninu ayé tẹ wà yi,gbogbo nkan tẹ ba dowó lẹ tomotomo,taya taya koni dibajẹ loju yín àti lẹhin yin paapa ni gbogbo igba tẹ ba wa laye àti lẹhin igba tẹ ba dogbo tí ọlọrun bá pé yin sọdọ,Oba Ọlọrun koni f'iyin sile nigba kookan
Amina ko se be
Muidineen iwo were ologoro Ajigin Aringin Ole ole ni e ole ole ole Muidineen Ajigin Aringin ole ole ni e
Olori buruku ni Muyideen alabaru bodija ati awon Alfa re.
Awon alfa Muideen o le fun #10.000 losese.
Danboroba, tani ni omo Ashitani? Aja lo ma je enu e pelu eyin e yoje yen 😂😂😂 Muyideen alabaru ni Bodija ki lo nwa support fun? Lo mu ise abaru e ni okukudun ko fi adua tii😂😂😂 e woju ole afibisu oloore.
Ki Muyiden ma lo oruko Agbala Gabriel mo ko ma je oruko ara re.
Alabosi ni Oriyomi Hamzat! I knew from the get-go that he (Oriyomi Hamzat) was behind all this shenanigan, mischief-making. He, Oriyomi Hamzat had no intention of settling the issue between Muyideen and Agbala Gabriel. He went there purposely to retrieve the house document from Agbala Gabriel and give it to Muyideen. His second and more devilish mission was to humiliate Agbala Gabriel. What an evil sneaky person!
Alfa wa dada e se pupo Olorun a fun yin ni emi gigun Muyiden a jere ese owo re.
Osogbo is for mallam Yusuf adepoju and co , the evil genius.
Oloto kiku sipo ika
Gbogbo eyin oloriburuku alatileyin Muyideen against Agbala Gabriel ofo lomi efo nse ofo ni gbogbo yin ma se danu. Atunbota yin koni dara .e ko ni ri alanu mo tirantiran ni agbara olorun amin ase Edumare
Oloriburuku ni Muheeden Afibisu olore ni koleri Alanu mon YES
HAMSAT ORIYOMI mo NIPAA Gbogbo Oro YIOO , Orogun Owo ni HAMSAT ORIYOMI hunbaa Agbala Gebrel SE ooo , nibo lewaa Fi TI Oluwa SI HAAÀ , IBADAN lo mo o molayipo , Olorun GBON JU Eda lo ooo , HAMSAT oni Subuu KIE Saraa ooo , ESIN MUSLIM ESIN Abosi NIOOOO.
Alfa , please just leave Muyideen alaimore alone. The curse is on him already without even cursing him. What a disappointment!!! If not for Agbala Gabriel, who knows Muyideen
Amin Amin Amin ni oruko jesu
Muyideen ori re ti buru . Olorun yio ba tie je ni agbara olorun amin ase Edumare
Eni fibi solore , iya ni yio je ku😩
EKU ISE LAADA EKU ETO SIR
Seloto ni alhaji e jo se oro muyindeen se oju lasan ni bayi
Aye muideen ti baje already oloriburuku Omo ni
Won ni tori agbala Gabriel na Muyideen ni won se fe ba ise iranse e je Muyideen ti aye e ti baje ole oloriburuku ti aye e ti baje
Alfa awon alabosi ni gbogbo awontowalehin muyideen Bodija ,Alfa konisuyin se lagbara titobi olorun amin
Bobaku ola dada ti Agbala Gabriel nse ore ti Mr kehinde nse.olorun oba ogbeni nija kieruba onija yio gbe Gabriel ati Mr kehinde ninja Amin, baba mi Alfa baba dada niyin se eri oroyi ija ilara kitanboro ni
Oriyomi is a disappointment.
Thank God God bless you sir
OCKRAL MADNESS IS IN MUIDEEN HEAD
Emi yin Alo layo ati Alafia. Abo olorun yio dajo Lori yin tomotomo. AMIN.
Oju Muideen ati awon alfa re maa bo ni, ete ni won maa ba bo ni kootu ti won lo