We have disturbed network whenever you start so I pray at midnight after you have stopped and believed that my prayers are answered everytime, thanks sir 👌🙏🙏🙏
Unbeatable, Undefeatable, Unquestionable, Miracles Working God, Alpha and Omega ,Igileyin Ogba mi, Iranlowo alaileniyan, Ijinle Ife, Baba Ayeraye, Unchanging Changer I worship You 💃💃💃💃💃💃💃
Alagbada ina, alawotele oorun, awuwo ma se gbe, ajagun segun ma fi tibon se, aji pojo iku da, oloore ofe, oni yonu julo, alagbara giga, oba lori aiye ati orun.
😊Arugbo ojo, Alagbara nla, owibe sebe, alawilese, oba awon oba, ijine ninu ijile unquestionable God, fi titobi re han ninu aiye mi, ba mi mu ileri re se laiye mi Loruko Jesu amin
Olorun Olulana, Olorun Oluranlowo fi titobi re rin ninu ile mi ati ninu ise mi,ona ti eni kan ko rin ri,rin ninu ile mi,gba ijoba lowo oba aye to nse ijoba lori aye mi ati lori aye awon omo mi amin
Alagbara nla Oyigiyigi alagbara to ju alagbara lo, Ogbamu gramı Oju orun ko se gba Murrumbidgee keke Oluwa Awon Oluwa Oba awon Oba. Oluwa Jeri ara re ninu aiye mi pe iwo ni Oluwa to lagbara lori Owun gbogbo.
Kabiyesi,Oba Awon oba,Arugbo ojo,Oba ngeli Ob eniyan.Olorun Bami Sam Olu Alo,fi bi oti to han ninu aye mi ati Awon Omo mi ninu osu yi ati eyi to ku ki odun to pari.Amin
For today’s prayer point check time stamp 1:05:00
Thank u ma
We have disturbed network whenever you start so I pray at midnight after you have stopped and believed that my prayers are answered everytime, thanks sir 👌🙏🙏🙏
My testimonies are coming ❤🎉 Congratulations to me
Unbeatable, Undefeatable, Unquestionable, Miracles Working God, Alpha and Omega ,Igileyin Ogba mi, Iranlowo alaileniyan, Ijinle Ife, Baba Ayeraye, Unchanging Changer I worship You 💃💃💃💃💃💃💃
Amen in Jesus Name
Am enjoying your program sir, am praying to have my own testimony very soon.
Lord take charge of my life and take over from the enemy controlling my life.
Olorun ipe Sam Olu Alo fianu yanju oro aiye mi ni Oruko Jesu Kristi. Wo mi ni ase iranru ni gbogbo ona ni Oruko Jesu Kristi
Good evening daddy more anointing sir God bless you for us,olorun cac,afunmi in iwe odunmewami eleketa ni eleyi,mercy of God will answer me
Arugbo ojo, alawilese, erujeje, obanla, ijile ninu ijile, fi tito bire han ninu aiyemi, wa gbati odo mi koja loni loruko Jesu amin
God almighty
Daddy it's true,it happen to me
Thank you Jesus
Thank you God
Amin
Jehovah Jireh, work in that manner in my life
Holy Gost 🔥 thank you Jesus, the owner of my soul ❤❤❤❤❤
Amen Amen and Amen in Jesus name to all the prayers
Love and like
Hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah ogo ogo ogo
AMEN AMEN AMEN IN JESUS NAME
Amin Amin Amin Jesu
Thank you Jesus 🙏❤️
Amin JESU, Hallelujah Hallelujah Hallelujah Amen 🙏 ❤
Thanks you Jesus
Thank you Jesus🙏
Hallelujah Hallelujah Hallelujah
Agbara ti yio gbé mi she kooge Oloore,Oluranlowo,ati ti yoo gbe mi pade eni ta fami kooge.
Merciful God
Amen, Amen, Amen in Jesus name
Arugbo ojo, adagba ma paro oye, gbanigbaniitansaya, ajagunsegun ode orun! Omomo tinmori eda Atori se! Seganogo, Jah, Rohi, El Rohi, Adonai
Arogunmasojo please walk in my life,walk in a way that can comprehend in wahabs life walk in my family
Amin Amin Amin loruko Jesu
Hallelujah hallelujah hallelujah
Ogbenija keru onbani ja. King of kings.
Alagbada ina, alawotele oorun, awuwo ma se gbe, ajagun segun ma fi tibon se, aji pojo iku da, oloore ofe, oni yonu julo, alagbara giga, oba lori aiye ati orun.
The mighty father, I am that iam
Kabiyesi Eledunmare..
Olorun Barbara
Fi titobi agbara re han ninu aye mi ni Oruko Jesu.
Oba awon Oba Emini to nje Emini Atini leyin koju ma to ni gbani gbani a sa ya gba aye wa koja ki iyanu fara han.
😊Arugbo ojo, Alagbara nla, owibe sebe, alawilese, oba awon oba, ijine ninu ijile unquestionable God, fi titobi re han ninu aiye mi, ba mi mu ileri re se laiye mi Loruko Jesu amin
Ajagun segun OLORUN olugbala baba awon alaini baba
Olorun Olulana, Olorun Oluranlowo fi titobi re rin ninu ile mi ati ninu ise mi,ona ti eni kan ko rin ri,rin ninu ile mi,gba ijoba lowo oba aye to nse ijoba lori aye mi ati lori aye awon omo mi amin
Amen and amen
Oluwa wo iya mi san fi ara re han lori aisan iya mi
Olorun a alagbara, oba awon oba , oluwa awon oluwa
Oba loni oba titi aye Kiki Ola Kiki ogo. Wa rin koja Lori aye mi .oko mi ati awon omo mi.wa fi ti to agbara re han olorun olu alo
Atobiju , alagbara nla,Fi ara re han bi atobiju ati alagbara nla Lori Oro ayemi loruko Jesu
Olorun arugbo ojo adagbamaparo oye gbengbeleku obatundanitowu
Amen
❤❤❤❤❤❤ Amen
Olorun alsgbara atofiseogunran,Olorun onise iyanu nla,fi titobi Re yanju isoro aye mi ATI ti ebi mi
AMIN
Great merciful God,
Arugbo ojo, opabidere, olugbaja, alawilese, olorun ibere ati opin, unchangeable God, I'm dat I'm, ijinle ninu ijinle, unquestionable God🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏
Sokale oluwa wa fi agbara re han
Olorun olu Alo je ki n ri rinrin re ninu osu keje yi ju ti ateyin wa lo
❤
Alagbara nla Oyigiyigi alagbara to ju alagbara lo, Ogbamu gramı Oju orun ko se gba Murrumbidgee keke Oluwa Awon Oluwa Oba awon Oba. Oluwa Jeri ara re ninu aiye mi pe iwo ni Oluwa to lagbara lori Owun gbogbo.
Hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah
Olorun and, arugbo ojo, alagbara Lori gbogbo agbara, gbongbo idle Jesse, gbanigbani lojo ogun le.
Oluwosan ni ooo
OLORUN ALEWILESE......FI TITOBI RE HAN NINU AIYEMI....BA MI MU ILERI RE SE NINU AIYEMI
A Ku ewu omo oooooo
Oluwa gba todo mi koja😂
MAY GOD HELP ME TO WIN 🙏
Agbara to ma gbemi se konge olore /alanu taa gbemi jade kuro ninu iyara adaniloro gbe womi
Olorun aiyeraye wa dasi Oro aiye mi aiye awon omo mi ki gbogbo Imo satanic ATI ise okunkun Lori Ile mi di asan loruko jesu Amin ki Le wa dupe ore
Awamaridi