TANI PARIWO IJOBA

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 20 ต.ค. 2024
  • Fún alaye àti ibere nípa Itan Yoruba ẹ kan siwa
    Aare Laji Abbas +2348023687432

ความคิดเห็น • 15

  • @oladimejimichael-w1o
    @oladimejimichael-w1o 5 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    Eku eto baba ❤❤❤

  • @OlusholaAjayi-et1qh
    @OlusholaAjayi-et1qh 8 ชั่วโมงที่ผ่านมา +3

    Aare wa eku eto, oroyin kole ta leti awon alakatakiti, eje Yoruba panbele lowa Lara tiyin, aye yin atoro, Imam Eleweran central mosque l'Abeokuta lefi iwa jora. Awon alale koni fiyin sile.

  • @azeezbabatunde9542
    @azeezbabatunde9542 6 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    Awi fun won to awon ni won o gba o, koro naa to daru o, awon naa o gba o.

  • @waheedibrahim7763
    @waheedibrahim7763 7 ชั่วโมงที่ผ่านมา +3

    Killing was at Oko baba Ebute-Meta Lagos Mainland 1958-1959

  • @monsuruakande164
    @monsuruakande164 4 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Laaaaaji ijoba no the around

  • @davesmith7513
    @davesmith7513 3 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Welldlone.

  • @azeezbabatunde9542
    @azeezbabatunde9542 5 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Eku eto Aare opitan, Olorun ko ni pa lakaye yin. Oju awon Alufa yi ti ja bayi. Odun marun pere ni awon onisese ni awon fe fi se eto tako Islam, e je ko ma lo be, ko ti ye ko re awon Alufa o, eto sese bere ni.

  • @princeayo2002
    @princeayo2002 8 ชั่วโมงที่ผ่านมา +2

    E ku ise takun takun

  • @user-iu3dq3ot4k
    @user-iu3dq3ot4k 7 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    😂😂😂
    Ààrẹ gbogbo ẹnu ni mọ fi sọ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tí wọ́n npe ra wọn lafa yí o mọn nkan kan, olodo ni wọn pátá pátá. Alfa kan ni islam de síwájú ilẹ̀ Yorùbá 😂😂😅

  • @oluseyeojo3726
    @oluseyeojo3726 4 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Baba Itan, kinni itan ile yoruba wi nipa OONi kiise Oba awon Musulumi ile yoruba?

  • @oluwatosinajayi9694
    @oluwatosinajayi9694 7 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    Aaree Opitan , please what is the name of the Heridotus book?

  • @user-iu3dq3ot4k
    @user-iu3dq3ot4k 7 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Abosi àwọn Alfa míì pọ là pọ ju

  • @samorano4me711
    @samorano4me711 6 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Are eku eto o