HAA! O SELE!! FULAN TUN PA AKINROGUN, JAGUN NI IGBAJA KWARA...GBOGBO ARA ILU N SA KIJOKIJO....

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 30 ก.ย. 2024
  • BREAKING!!!
    HAA! O SELE!! FULAN TUN PA AKINROGUN, JAGUN NI KWARA...GBOGBO ARA ILU N SA KIJOKIJO....
    #arabatv #kwara #fulani #fulaniherdsmen #trendingnews #breakingnews #trendingvideo #trending #yorubamovies2023 #yoruba #yorubanation #sundayigbohonews #yorubamovies2023 #latestnewstoday

ความคิดเห็น • 8

  • @adetounolorundami5257
    @adetounolorundami5257 4 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    Kini oba ilu yin na esi
    kini governor naa nse si
    eyin oba ile yoruba , egbo nkan ti awon ara ilu fe , won ni awon ko fee awon ota apayan mo , eso fun won pe kiwon ni suru , suru suru won ti fee pa awon omo ilu tan , kini suru yi nse bayi , awon omo igbo ti le won kuro ninu ilu won , ema da awon oba wonyi loun , egbeja ara yi oooo

  • @adetounolorundami5257
    @adetounolorundami5257 4 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    edide eso fun oba, wipe eko fee awon ota yin mo lori ile yin .

  • @adetounolorundami5257
    @adetounolorundami5257 4 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    won ni awon oba naa ti gba omo ishakole lowo awon ota yin

  • @olusesanajayi7950
    @olusesanajayi7950 6 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    De can hear you loud & clear!

  • @adedunkealabi3965
    @adedunkealabi3965 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    E se suuru titi ti fulani maa fi pa gbogbo yin tan, Eyin Oponu Ayirada gbogbo

  • @olufelabarber7795
    @olufelabarber7795 5 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    Ibo lo fi gbogbo Ogun abenu gongo si ?

  • @IsaacOmolade-l1d
    @IsaacOmolade-l1d 5 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    Ejo se jagun o ni ogun ni abi eran lende ye ode ni

    • @kehindejosephkashimawo9410
      @kehindejosephkashimawo9410 4 ชั่วโมงที่ผ่านมา

      Ṣé ọ̀rọ̀ lọ nsọ yìí, àbí pe Fulani pa 'yàn.?