Rárá o, Irúnmọnlẹ̀ ni Èṣù jẹ́ o. Bàbá ṣe àṣìṣe gidi pẹ̀lú nǹkan tí wọ́n sọ yìí o. Òwe lásán ni Ifá pa nípa wípé Èṣù ni ìyá o. Irúnmọnlẹ̀ kìí ni ìyá àti bàbá o.
Baba gbogbo omo Yoruba Olorun yio wa pelu yin Baba, Olorun yio fun yin lemi gigun ati alafia pipe, mo gbadun eto yin yi yato eko ati imo ijinle po pupo ninu eto toni yi, e seun baba logun ofe Ooo
Bàbá, kílódé tí ẹ fi ń sọ nǹkan tí wọn ò sọ nínú bible àti Quran? Ṣé Èṣù ni wọ́n kọ sínú bible àti Quran tàbí Satan àti Hashatan? Ẹ pèé bí wọ́n ṣe pèé, ẹ má jẹ́ ká ba nǹkan wá jẹ́. Èṣù kìí ṣe Hashatan, Bẹ́ẹ̀ni kìí ṣe Satan, Èṣù ni Èṣù ń jẹ́. Ẹ ṣeun
Bàbá, ẹni tí ó wá ń ṣe Guru, Shintoism, Hinduism, Zoroastism, Buddhism, etc, irú Odù wo ni yóó hù? Kò sí Odù kankan tí ó ní kí ẹnikẹ́ni lọ ṣe Islam tàbí Christianity o. Àjásà lásán ni gbogbo irú Ifá yẹn o, kí n ṣe ògidì Ifá rárá. Àgbélẹ̀rọ tàbí Àjásà ni àwọn Ifá yìí o.
One of the best men living on earth 21 century. It's a privilege to witness and be alive to see Baba wa, Baba mii ❤
Welcome back professor .. big love from Dublin sir ..
Thank you so much sir. May Olodumare continue to prolong your life sir.
Baba God bless you and your family IJN Sir
Baba am happy to see you sir
Asalam alekun baba Allahu we bless u more and more good job sir
well done sir,love your knowledge
Thank you sir
That's very good about the religion
May the Almighty God bless you sir
This is GREAT
God bless you sir
Good blessings sir ❤❤❤❤
God bless you sir
God bless you baba
Thanks you sir ❤❤❤❤❤❤
Very nice my father
Thank you sir god bless your age for Yoruba land
Baba mi,I which to see u one
Ogun apaji wa. Confirmed
Timilehin John Aderemi nki Baba Egbeji Alawoye looogun ooooofe
Because I own u something sir
A n’gbadun eto yin Baba!
Baba otojometa sir
❤❤❤
34:00
I am impressed by this intelligent presentation. Please sir how can I get the contact number of baba. I want to ask questions.
Baba mi emi ola yin yoo guu pelu aseolodumare
I never knew Esu had parents and also gave birth😮
Rárá o, Irúnmọnlẹ̀ ni Èṣù jẹ́ o. Bàbá ṣe àṣìṣe gidi pẹ̀lú nǹkan tí wọ́n sọ yìí o.
Òwe lásán ni Ifá pa nípa wípé Èṣù ni ìyá o. Irúnmọnlẹ̀ kìí ni ìyá àti bàbá o.
@@tosineweje7328 okay sir. Thank you
Esu is not satan please.
Baba gbogbo omo Yoruba Olorun yio wa pelu yin Baba, Olorun yio fun yin lemi gigun ati alafia pipe, mo gbadun eto yin yi yato eko ati imo ijinle po pupo ninu eto toni yi, e seun baba logun ofe Ooo
Baba e seun o
So, Islam ni ọ̀nà tí Ọlọ́run fi ń mọ ènìyàn. Kí Olódùmarè ṣàánú fún àwa ọmọ Káàárọ̀ Oòjíire. Wọ́n ti fi Ẹ̀sìn àjèjì kó wa ni ọpọlọ (57 mins) ....

Baba ❤😘
39:00
❤