Esi ati Alaye yen ko kunju won Rara, Toripe oloye ifagbenga ko fenu ba Awon Egungun Idemo quarters Nile Baba Temi Aduloju toje pe Awa lankehin Oro ni ilu Ado Ekiti,Ogun ati Egungun la nse Nile tiwa to si gbajumo kaakiri gbogbo Ekiti ati Akoko bakana.E seun,Aseyi Samodun lagbara Eledua.
Nice one brother alausa of ado ekiti 1
Am proud of ekiti
This was very informative interview keep up the good work bro may oludumare continue to bless you ese oooo
Àse, thank you.