Àwon omo ilekewu ni àwon omo ogun ti nwon fe lo fun ogun esin ni ile Yoruba. Bi gbogbo àwon omo wonyi ba dagba tan, ewu n la ni ni ile Yoruba . Àwon ti nwon n pe ni alumajiri ni oke Oya, omo ilekewu ni won, àwon omo wonyi ni nwon n lo nigbakigba ti won ba ti da wahala sile. Mo ti ri isesi àwon alumajiri wonyi nigbati wahala sele ni Kaduna ni odun 1987 ati 1990 . Eesin o koku ni àwon omo wonyi. Yoruba gbodo fi ofin de gbogbo àwon ilekewu ki won ri pe gbogbo omo lo kawe ki i se ile kewu lokan. Omo ti ko ba le kawe a lo ko ise owo.
Awon musulumi lo gor ju lagbaye 😂😂
I appreciate you for this enlightenment n this programs t educate the Yoruba Muslims in the south west.
Àwon omo ilekewu ni àwon omo ogun ti nwon fe lo fun ogun esin ni ile Yoruba. Bi gbogbo àwon omo wonyi ba dagba tan, ewu n la ni ni ile Yoruba . Àwon ti nwon n pe ni alumajiri ni oke Oya, omo ilekewu ni won, àwon omo wonyi ni nwon n lo nigbakigba ti won ba ti da wahala sile. Mo ti ri isesi àwon alumajiri wonyi nigbati wahala sele ni Kaduna ni odun 1987 ati 1990 . Eesin o koku ni àwon omo wonyi. Yoruba gbodo fi ofin de gbogbo àwon ilekewu ki won ri pe gbogbo omo lo kawe ki i se ile kewu lokan. Omo ti ko ba le kawe a lo ko ise owo.
Archbishop na miliki, Poopu na enjoyment imaamu na gbaladun.
Isilamu tishirin Ni Ile Yoruba patapata isilamu mafedanu Ni Ile Yoruba laipe lase edumare