O ya ni lenu wipe awon Fulani ko ti le so wipe awon lawon ni Ilorin sugbon awon Yoruba Ilorin fun ra won ni won npin ogun ibi won sita. Awon akotile ta.
Aare Opitan. Sheikh Habeeb Abdullahi Al ilory nse afihan bi won se je ni morkaz. Ko wopo ninu alfa ti o ba jade ni morkaz ti igberaga ko si ninu eje re. Eniti igberaga ba si po fun, iro ati oro asobaje ko ni jina si enu re.
Nnkan toba wu onikaluku ni ki o fi enu e so, ilorin ile yooba ni. Olorun je kari aare opintan onibode ile yooba pe. Omode ni Yahaya Gambari atipe oro'mo adie ko mo awodi, iya e loda asha mo, atipe atari ajanaku ni oro ile yooba kiise eru omode, nnkan towa nile koja Yahaya Gambari.
Yoruba a ma pa lowe pe ojo ti owo eni ba te ikuda ni ao bere iku to pa baba eni.Ti awon Alfa Ilorin ba ti n faga gbaga pelu awon oni mimo ile larubawa ,ilu Ilorin iba ti da ju ile larubawa lo.O se je pe awon oni mimo larubawa tun fi mimo won ko awon Alfa Ilorin leru?
@LajiAbass, Please, focus more on the history of the Yorùbá people and reduce the frequent mentions of Motala, Okeadu, Baba Ile Amí, and similar references. These Islamic stories are gradually disengaging your audience, as we find them repetitive and less interesting.
Aare Laji Abass, may Allah grant you more strength, wisdom and long life to protect the Yoruba history from intruders. Amin!!!
Aare,thank you very much for your persistence on IIorin history and awareness on Yoruba ownership of Ilorin and Kwara state in general,God bless you
O ya ni lenu wipe awon Fulani ko ti le so wipe awon lawon ni Ilorin sugbon awon Yoruba Ilorin fun ra won ni won npin ogun ibi won sita. Awon akotile ta.
Aare Opitan. Sheikh Habeeb Abdullahi Al ilory nse afihan bi won se je ni morkaz. Ko wopo ninu alfa ti o ba jade ni morkaz ti igberaga ko si ninu eje re. Eniti igberaga ba si po fun, iro ati oro asobaje ko ni jina si enu re.
Comment from sierra Leone
Nnkan toba wu onikaluku ni ki o fi enu e so, ilorin ile yooba ni. Olorun je kari aare opintan onibode ile yooba pe. Omode ni Yahaya Gambari atipe oro'mo adie ko mo awodi, iya e loda asha mo, atipe atari ajanaku ni oro ile yooba kiise eru omode, nnkan towa nile koja Yahaya Gambari.
Aree lajii abass, ejeki awon Ilorin o maa tan ara won, won o kife gba pe abe oyo lawon wa, awon alabode ile Yoruba
Lagelu kose gbagbe ninu itan Ibadan. Lagelu ni ipinle.
we have a place called ilugun under ijebu northeast,agoiwoye while some first settlers claim to come ule ife
Ajase-leni-igba .. niyen. Lol 😅
Eeku ise nla.
Gbefun
Yoruba a ma pa lowe pe ojo ti owo eni ba te ikuda ni ao bere iku to pa baba eni.Ti awon Alfa Ilorin ba ti n faga gbaga pelu awon oni mimo ile larubawa ,ilu Ilorin iba ti da ju ile larubawa lo.O se je pe awon oni mimo larubawa tun fi mimo won ko awon Alfa Ilorin leru?
are olayiwola ojokipe pe asefidio yi tipe bayi osidabi anan are lati kuwait ni motigboyin o alfa habib ni baba ounpa iro
aare this your video u do it 2013 not new video bcus this is your old studio background
Baba murkaz kinni ti won, se historians ni won a bi Quranic scholars , mesujamba e wa n pa'alo.😮