Okunrin gidi deni osuolale oooo, iyawo re lo fe ti si ita 😢 eni toliri koni fila, eni toni fila kolori, hmmmm Olorun jo maje kin sife laye mi 🙏 Okunrin olorire alalubarika ni ki n fe ooooo
Hmmm, Osuolale ti se mistake he could have told his wife about oga Seun before that he wanted to have relationship with her so that she can be very careful of him and the type of oga seun may be his wife will be mind her own business, she will not fall into oga Seun hand.
Okunrin gidi deni osuolale oooo, iyawo re lo fe ti si ita 😢 eni toliri koni fila, eni toni fila kolori, hmmmm Olorun jo maje kin sife laye mi 🙏 Okunrin olorire alalubarika ni ki n fe ooooo
Well done sir ❤❤👍👍👍
Iywo Osun olale ki se obirin gidi,nitori obirin gidi gbodo gboran si Oko re lenu
Iyawo osuolale o bowo fun oko re, Thanks for this sir🙏🤲
❤❤❤❤❤ 🎉🎉🎉🎉🎉
Well done sir ❤❤
Ese olotu ❤❤❤
Thank you olotu
Well done sir
More wisdom
Hummm.... Olagbra ooo ... God bless you sir
O ye ki iyawo osuolale tête boju to ile re . Ki o be oko re ki o to bo sori
Ẹ tún kù ìṣe ọpọlọ Olusotan wá, Osuolale tí gba èṣù láàyè nínú ìgbéyàwó wọn ó, nípa èrò ọkàn rẹ.
Thank you sir, may Allah continue to strengthen you.
Eh ku ise olotu, story yi wa interesting ganni, Iyawo Osu ni afojudi si OKO re, oh fe ki OKO re maa niyemeji si Pelu kan to rawole yi.
God bless you sir
Thanks so much God bless you sir thanks so much sir
Thanks ❤
Well done sir
❤❤❤❤❤❤
❤❤❤❤❤❤❤
❤❤❤❤❤
Eku ise opolo
I still reserve my comment.
Hummmm obinrin
Ohun tonro to ro, beni bikose soro sita olehu
Hmmm, Osuolale ti se mistake he could have told his wife about oga Seun before that he wanted to have relationship with her so that she can be very careful of him and the type of oga seun may be his wife will be mind her own business, she will not fall into oga Seun hand.
This story is interesting from the beginning, i know its going to be very tough, eeeeh na serious matter o
Yes, I don't blame Osu for thinking such way, his wife was wrong but he should have a discussion with his wife about it.
Osuolale lo da Ina sinu Ile re lati ibere !!!
Ki o de takute(private investigator) to collaborate his suspicion.
E ku ise oo
Eku,ise,sir
Ati ibere pepe ni
Osuolale ti se Asise pelu
Aimo so fun Iyawo re
Mistake Elekeji
Koto yowo ni Ile
Oye ki iyawo re ma inkan tose
Eku ise takuntakun sir
Ti obirin koba yan ale sugbon toba ni afojudi nkan tomapada sile ni yen
Kosi eyi tiko toro ninu gbogbo e o,awa obinrin agbodo fi ogbon toye koro di idile wa mu
Eku ise opolo o idile tiyin na koni daru
Ìtàn yi se pàtàkì púpọ̀ nítorípé afojudi jù ọkọ dido lọ.
Kii ọ ya tètè se DNA awọn ọmọ rẹ kì otọ pẹ jù.
Ọ̀rọ̀ ti Ọ̀ga Ṣeun sọ yẹn Ni kọnukọhọ nínú.
God bless you sir