Won n pe ki o se nnkan tose pataki ljo lo beresi jo bi okoto. Dr. Omowumi Lawal naa so titi n se lo se bi alaigbo. Boya gominaa ko ni onimoran to yanranti tabi pe ijo ko je ki o ri aaye gbo. We love him and gave him votes of sympathy with prayers yet he forgot too soon
BABA mi ipa ti OBA IFO yen awon ALALE lo fi sesin sir nitori pe oti n se ti pe ti pe sir awin ALALE lodide lati sha gbogbo awon Kanda ninu to wa ninu awon OBA ile YORUBA hunnnnnnn
BABA mi ASA ati Iselu❤ se e ri ni genaletion ti a wa yi gbogbo alagbara ka gbara ni on wnu ko ni gbe agbara sile nwon ma ma shesin ni laseeedumare ♥️ ASE Edunmare ASEWA
The levity with which Osun state governor is handling this Oluwo will definitely have a telling effects in the coming election in Osun state. Since the governor is incapable of handling Oluwo of Iwo, it will be proper for the people themselves to handle Oluwo through the coming state elections.
OLÚWO KORI ỌMỌ BINRIN TO DÁRA NI ILU IWO ÀTI GBOGBO ILẸ YORÙBÁ. O LỌ GBE FÚLÀNÍ WÀ SÍ ILE LÀTI MỌ FÍ YANGAN PÉ KÒSÍ OBÌNRIN TÓ DÁRA TÓ. ÌYÁLÓDE NÀ DAKẸ
Ijo ni governor Adeleke njo kiri Governor Adeleke nwa second time lona aito ti won Ko ba handle rashidi ati mufti iwo Ko ni si second time fun governor ti Ko ba ti le protect awon Ara ilu
GOVERNOR ADELEKE OF OSUN STATE IS A DISAPPOINTMENT CONCERNING OLUWO OF IWO AND MUFTI BOTH OF THEM WILL DESTROY YOUR REGIME. LAGBARA LOWO OLORUN GOVERNOR ADELEKE ALALE ILE YORUBA MA JE YIN NIYA ATI AWON OMO YIN LASE EDUMARE, AMI ASE EDUMARE. GOVERNOR ADELEKE WA SUN OONIJI SAYE MON LASE AWON ALALE ILE YORUBA, ASE WAA NITIREKE
Governor Adeleke PDP ni egbe awon satan of Sokoto KO si Bo SE ma BA wi KO ma ba SE Atiku ,SE governor onijo ma ni oun o ri jatijati radarada ti Oluwo nse, SE KO RI ni, eji gbogbo ona Ile ife road KO da rara Seyi 😊😊Makinde tun gbogbo titi Ibadan SE kinni Adeleke SE?.
eku ise sir Oro oba owo olorun nikan lole gbawa lorie kosi unti gomina osun lesesi Tori aregbesola logbewole aregbesola na lofi oluwo je oba kinlero pe gomina lesesi
Efi gomina onijo yen sile oma to ye eku ohun baba wa onle yo ma se atile yin beni sise to ba oba ifo maba oluwo pelu mufut iwo gbogbo oro te so ase gun
All these is the one Nigeria, how do we know that the person speaking hausa is a native Hausa or native Fulani just to justify what the Fulanis are doing in the whole Nigeria.. Is either Nigeria goes back to regional system or divide Nigeria by regions in her.
Olorun asaaanu gbogbo wa. Epeele sir. Ko ni ni sa la se olorun. Aaaaameen
Good job my Brother, Ofin to m’eleegun lo mu ẹlẹha. Ofin to mu ki Ọba Ifọ s’ẹwọn na lo mu Rasheedi Oluwo.
Ase Ase ooo
Eku de de iwo yii. Sir. Ekaa sir sir. Epele sir. Eku oroo ilu. Adura wa agbaa sir. Aaaaameen
Oto ojo meta ma
Won n pe ki o se nnkan tose pataki ljo lo beresi jo bi okoto. Dr. Omowumi Lawal naa so titi n se lo se bi alaigbo. Boya gominaa ko ni onimoran to yanranti tabi pe ijo ko je ki o ri aaye gbo. We love him and gave him votes of sympathy with prayers yet he forgot too soon
Amin asee
BABA mi ipa ti OBA IFO yen awon ALALE lo fi sesin sir nitori pe oti n se ti pe ti pe sir awin ALALE lodide lati sha gbogbo awon Kanda ninu to wa ninu awon OBA ile YORUBA hunnnnnnn
BABA mi ASA ati Iselu❤ se e ri ni genaletion ti a wa yi gbogbo alagbara ka gbara ni on wnu ko ni gbe agbara sile nwon ma ma shesin ni laseeedumare ♥️ ASE Edunmare ASEWA
Woah very early in the morning.
Osun people should carry out protest on oluwo. I think people shouldn't give Adeleke second term
Ootø oro ko ni ki won ma so owun
If a governor does not listen to the people's demands, why do you want to vote him in for a second term? People don't know how powerful they are. 😅😅😅
Ogun n ja awon judicial systems that gave him the right to operate parallel judicial system
EkAROO SIR BABA WA ❤ Eku ise ILU SIR ❤ OLORUN OBA A ma wa pelu yin sir laseeedumare ♥️
Governor is avoiding dealing with Oluwo’s case because of his 2nd term running.He care less of Yoruba wellbeing
And also the governor is HALF-YORUBA-YIBO, so he does not give a F of whatever that happens in Yoruba land
The levity with which Osun state governor is handling this Oluwo will definitely have a telling effects in the coming election in Osun state. Since the governor is incapable of handling Oluwo of Iwo, it will be proper for the people themselves to handle Oluwo through the coming state elections.
Ase Edumare 😢
Awa yoruba ni dindinrin abi fulani o gbadun yoruba nation no goin back
Forward this matter to the concern departments at the state level.
BABA mi ASA ATI iselu oooo hunnnnm aarin agba OGUN IBO ati awon Foolani Hausa la wa ooooo hunnnnm OGA ooooo
OLÚWO KORI ỌMỌ BINRIN TO DÁRA NI ILU IWO ÀTI GBOGBO ILẸ YORÙBÁ. O LỌ GBE FÚLÀNÍ WÀ SÍ ILE LÀTI MỌ FÍ YANGAN PÉ KÒSÍ OBÌNRIN TÓ DÁRA TÓ. ÌYÁLÓDE NÀ DAKẸ
Awon Fulani je Oba ni gbogbo agbegbe wa, ki i se ilu nikan
@@omolaraayeyemi2853 What kingship over the world? Are you whining us?
Gomina n sa, ko fee se awon Fulani ni
YORUBA NATION NO GOING BACK LASEEEDUMARE IBUKUN NI FUN ORIRE EDE WA YORUBA ODUDUWA AGBE WA Oooooo Koni gbe ODALE LASEEEDUMARE
Baba keepe funwa amin ejowo ema bawa so date ojo OSU ati odun fun wa Lori eto yin ❤❤❤❤❤💚💚💚💚
Good observation
Ijo ni governor Adeleke njo kiri Governor Adeleke nwa second time lona aito ti won Ko ba handle rashidi ati mufti iwo Ko ni si second time fun governor ti Ko ba ti le protect awon Ara ilu
Ara nkan ti oluwo se nsise na niyen.
Àṣẹ o, bẹẹni yóò rí funwon
They can't do anything to us in yoruba land except osun
Gomina Dapo Abiodun,e seun fun igbese yin Lori oba alasete. E ku ise sir.
To me i will said the governor is a weakling. I expect that man to be dethrone by now.
Who is governor. Governor woni .
GOVERNOR ADELEKE OF OSUN STATE IS A DISAPPOINTMENT CONCERNING OLUWO OF IWO AND MUFTI
BOTH OF THEM WILL DESTROY YOUR REGIME.
LAGBARA LOWO OLORUN GOVERNOR ADELEKE ALALE ILE YORUBA MA JE YIN NIYA ATI AWON OMO YIN LASE EDUMARE, AMI ASE EDUMARE.
GOVERNOR ADELEKE WA SUN OONIJI SAYE MON LASE AWON ALALE ILE YORUBA, ASE WAA NITIREKE
Dada wo lose ju ijo were rubbish governor
Baba Asa ati Ise, e kare. Baba tooto ni yin. Otito a jeki emi yin to sir.E ku eto sir.
They are Mediator!!
You're backing him and saying the some yoruba are traitors
Oba Abdul Rasheed Adewale Oluwo of iwo, is doomed already.
Odo oro
Governor Adeleke PDP ni egbe awon satan of Sokoto KO si Bo SE ma BA wi KO ma ba SE Atiku ,SE governor onijo ma ni oun o ri jatijati radarada ti Oluwo nse, SE KO RI ni, eji gbogbo ona Ile ife road KO da rara Seyi 😊😊Makinde tun gbogbo titi Ibadan SE kinni Adeleke SE?.
eku ise sir Oro oba owo olorun nikan lole gbawa lorie kosi unti gomina osun lesesi Tori aregbesola logbewole aregbesola na lofi oluwo je oba kinlero pe gomina lesesi
Boya Gomina Adeleke ti gba owo lowo Arabu tani mo.Gomin nberu Oluwo. Se Oluwo lagbara ju Gomina lo ni ?
Efi gomina onijo yen sile oma to ye eku ohun baba wa onle yo ma se atile yin beni sise to ba oba ifo maba oluwo pelu mufut iwo gbogbo oro te so ase gun
Dudu oluwo lata pupo
AWON ALALE to te ile YORUBA do o ma ma fi nwon shesin laseeedumare
There is no Egbeda boundary between Lagos and Ogun. The only Egbeda is in between iyana ipaja and ikotun
Emaa lo tibile àwọn baba yin sikena
ASEEEEEEE ASEEEEEEEEEE ASEEEEEEEEEE ASEEEEEEEEEE ASEEEEEEEEEE ASEEEEEEEEEE ASEEEEEEEEEE ASEEEEEEEEEE ASEEEEEEEEEE ASEEEEEEEEEE ASEEEEEEEEEE ASEEEEEEEEEE ASEEEEEEEEEE ASEEEEEEEEEE ASEEEEEEEEEE ASE Edunmare ASEWA 👍👍👍👍👍👍👍👍👍👍