Awikonko you wrong , agbala always announce any money that comes in after the show. The problem of muideen is that he wanted the money to come to him directly
Ki Muyideen lo si church miran. Ki fi chuch Agbals Gabriel sile. Ki I se church Agbala Gabriel ni kan lo wa fun iranlowo. Muyideen. Ko lo si ibomiran ko le mo pe. Olorun ju eda lo Of Abo
Se Muideen ko ri opolopo awon ti Agbala Gabriel nse iranlowo, awon bi alaisan, awon opo ati bebe lo. Awikonko eku iro ogbon. Alaimore ko le ni itelorun laye laye.
Erù we left kòloko ñi shop,Sebi Ohuñ peĺùu Awòñ Oĺòpà ti wòñ wa latì Oshògbò,tiko gbògbo eŕu, Won the ko eyi ti Ìyawo fi Owo tiwoñfùn ra Oja, won ko gbogbò re,lo si Oshogbo, Lo Oshogbo kolo gbaà.
Awikonko, kò ní bàjẹ́ fún yín sir. Aláìmoore ẹ̀dá ni Múìdínì, bóyá ni Múìdínì lè pàdé Olóore mọ́ láyé.
Awikonko ọ̀rọ̀ yín kò ní dàrú pẹ̀lú àṣẹ Èdùmàrè...
AGBALA Gabriel is always giving act even after the program
Ingrate. A HOUSE, A BUSINESS., A WEDDING, Haba! Muyideen needs to beg God for mercy and forgiveness..
Muideen tun feki Agbala jeki won d'awo fun aburo oun naa. O wa lara nnkan ti o fi nbinu si pastor . Okanjuwa, ole ni.
Really?.
Muideen je alaimore eda, owe to sope, ENI TA SE LOORE TI KO DUPE, BI OLOSA KONI LERU LO NI.
Muideen gan lowe yi bawi.
Awikonko you wrong , agbala always announce any money that comes in after the show. The problem of muideen is that he wanted the money to come to him directly
Exactly what awinkonko said, he didn't oppose Agbala.
Ki Muyideen lo si church miran. Ki fi chuch Agbals Gabriel sile. Ki I se church Agbala Gabriel ni kan lo wa fun iranlowo. Muyideen. Ko lo si ibomiran ko le mo pe. Olorun ju eda lo Of Abo
E ku eto. Tani o maa fun oloriburuku muideen lowo? Alaimoore.
Se Muideen ko ri opolopo awon ti Agbala Gabriel nse iranlowo, awon bi alaisan, awon opo ati bebe lo.
Awikonko eku iro ogbon. Alaimore ko le ni itelorun laye laye.
AWIKONKO and his proverbs!!!!
Erù we left kòloko ñi shop,Sebi Ohuñ peĺùu Awòñ Oĺòpà ti wòñ wa latì Oshògbò,tiko gbògbo eŕu, Won the ko eyi ti Ìyawo fi Owo tiwoñfùn ra Oja, won ko gbogbò re,lo si Oshogbo, Lo Oshogbo kolo gbaà.
Eni to ori ko ni fila. Ki Muyideen lo sun sile Awon family re o
419 ni Muyideen.
Baba 419