Ę kaaro sir, a maa ju yin se, ko si ni re yin lagbara Olohun. Ę dakun mo ni ki n beere ORUKO EWE ti ę n gbiyanju lati so nibęrę eto yi.. E ko ranti pada so ki ę to pari eto.
Pls baba! kini mi ti le dada, mo dupe sugbon iseju merin or meta ni mo un lo to fi ma lo sile sir, is there any remedy for that sir, i really appreciate you sir
❤haaa Baba oni inu ire eseeee lopolopoooo .Aye ile Yoruba koni baje oooo. I need ur number Sir . Mofe wa yin waaaa. Ejowoooo
Please what can someone use for skin tag
Thanks you sir
Weldone, how much
Eseun, mo nife si ise yi, eelo lo le nan mi.
Ese adupe sir
Mo dupe pupo.eo ni mo koro laiye yin eo pe fun wa sir
Ejowo sir ilu wo ni lewa sir
08061408254
Elo ni ti e ba fe se funyan?
Baba Dada ko ni baje
Please I saw your video, please sir how can I get the medicine for aleko. Ejo sir bami yanjure.
08061408254 whatsap
Ę kaaro sir, a maa ju yin se, ko si ni re yin lagbara Olohun.
Ę dakun mo ni ki n beere ORUKO EWE ti ę n gbiyanju lati so nibęrę eto yi.. E ko ranti pada so ki ę to pari eto.
Egbo kanranjangbon ni sir
Olohun yio gba funyin ju bayi lo ashe tedunmare
Amin sir
Pls baba! kini mi ti le dada, mo dupe sugbon iseju merin or meta ni mo un lo to fi ma lo sile sir, is there any remedy for that sir, i really appreciate you sir
Se e ti ma n tete release tele abi leyin igba ti e lo oogun ti a gbe ranse lo to bere
Ejowo eloni e le se fun mi? aleko to daju ni mo fe,
Please sir how much can it cost me ?
Ise baba won pupo sugbon mo gbadun won, e ba won soro ni whatsap....................
Smile! kii se ebi awa naa o, eroja lo won o, inu mi dun wipe e so wipe o sise daada, olorun seun sir, e se mo dupe sir