TAOFEEQ ADAM ILE EYEBA IJERU OGBOMOSO TI FENU JA WAYA.

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 4 ก.ค. 2024

ความคิดเห็น • 111

  • @abrahamaugustus1619
    @abrahamaugustus1619 4 วันที่ผ่านมา +7

    Baba, you are a true son of Ogbomoso.
    He has gone beyond his apogee.
    He has naked the King in the Market,so he couldn't dress Kabiyesi in the room.

    • @Alwarithuun
      @Alwarithuun 2 วันที่ผ่านมา

      You will definitely support mugun man and old fools because it favours your redeem pastor who bow to adeboye but ur oba refused to bow or respect the Imam of Muslim

  • @WahabYunus-fq1qj
    @WahabYunus-fq1qj 2 วันที่ผ่านมา

    Almighty God will keep imam you like or not inshallah

  • @fataisanni7106
    @fataisanni7106 3 วันที่ผ่านมา +1

    Alaburu ni ìwọ Baba yii.
    Ọlọhun ju ẹ lọ.
    Lọ gba fun Ọlọhun.
    Se Kabiyesi jẹ Ọlọhun.
    Wọ́n nbẹ Ọlọhun oun gbọ́.

  • @sampsonkomolafe832
    @sampsonkomolafe832 4 วันที่ผ่านมา

    Baba you are a good
    Man in Ogbomosho thank you for your peaceful talk

  • @AlomaIbrahim
    @AlomaIbrahim 4 วันที่ผ่านมา +4

    daju daju ekeyi tonsoroyi omo ale ogbomosho ni oro tonbeni ile yi kokan soun ogbomosho ki imam talhat loyan oro arare ninu ile won imam kanfefi da ilu runi ki imam mafi esini boju

  • @akinwaretolu1225
    @akinwaretolu1225 วันที่ผ่านมา

    This matter is very simple having followed the issues for a long time. Imam should go to Ayilara to settle his case so that peace can be in the land. Ogbomoso koni daru.

  • @adisakabiru6737
    @adisakabiru6737 3 วันที่ผ่านมา

    To ba je pe ori otito ni Imam Yunusa duro le lori olohun Oba Allah yoo gbebori yii insha allah

  • @fataisanni7106
    @fataisanni7106 3 วันที่ผ่านมา

    Ọ̀tá Imam Tọlihat ni ìwọ Baba yii.
    Ki lo fẹ́ gan.
    Gba fun ẹniti Ọlọhun gbe Ọlá fun.
    Ìwọ naa bímọ.
    Ọ̀tá Ilu ni ẹ lọ joko jẹ

    • @mubashirabdulaziz7413
      @mubashirabdulaziz7413 2 วันที่ผ่านมา

      He mistakenly gain access to the palace and want to sustain it

  • @bumishaw7094
    @bumishaw7094 4 วันที่ผ่านมา

    You have spoken well sir..

  • @RhamanWasiu
    @RhamanWasiu 4 วันที่ผ่านมา +2

    Dajudaju olori buruku ni omo ile eyebaaa

  • @user-kp1yj8go8o
    @user-kp1yj8go8o 4 วันที่ผ่านมา +1

    Didirin agba, allow the palace media to do these.

  • @ibraheemlawal2012
    @ibraheemlawal2012 3 วันที่ผ่านมา +1

    SUBER, SUBERU SUBERU
    OMARARE LOLODO ATI OLOGUN, MINAFIKI NI E.
    OMA KEWU ASN EJO LASAN LOMO.
    MA MURA EWAN EE

  • @Cute_Holabecee1640
    @Cute_Holabecee1640 4 วันที่ผ่านมา

    So u accepted him as a boss too..Alhamdulilah!!! nothing can forsake him.. Baba Agbalagbi..

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni9463 4 วันที่ผ่านมา +2

    Imam Teliat Yunusa is an Iporo Ake man NOT Ogbomoso indigene. The family said he is not a member of their family and this had been proved beyond reasonable doubt.
    Tell Teliat to mention the name of his father, names of his uncles, tell him to mention the name of his brothers & sisters bcos he said his father had 8 children from 3 Wives or so.
    Above all, he is so rude.

  • @fataisanni7106
    @fataisanni7106 3 วันที่ผ่านมา

    Ọ̀tá Ogbomoso ni ẹ to foju han ìwọ man yii.
    So, ki lo se ẹ lati maa jẹ ki alaafia waye ninu ilu yin.
    Ki lode to gba fun Ọlọhun.
    Ẹ̀sin lo n wa lori ọ̀rọ̀ yii

  • @OWOADENAFISATBOLANLE-nu7ey
    @OWOADENAFISATBOLANLE-nu7ey วันที่ผ่านมา

    Eyi eni bi oloun yoo bi yin InshaAllah to ri efe da oju islam bole

  • @AbdullahiAkanni-uq2er
    @AbdullahiAkanni-uq2er 3 วันที่ผ่านมา +1

    Baba u are not God and u cannot separate what God has joined together. Olohun juyinlo

  • @ditty6828
    @ditty6828 4 วันที่ผ่านมา +1

    Major professional acadip niyen. He can dish out but he cannot receive it.

  • @ditty6828
    @ditty6828 4 วันที่ผ่านมา +2

    Really!, taofeek benu boloku yi ma daft o.

  • @user-jj5vr3fd5z
    @user-jj5vr3fd5z 4 วันที่ผ่านมา +1

    YORUBA MUSLIMS THINK YORUBA FIRST BEFORE RELIGION. IF THERE IS PEACE IN YORUBA LAND RELIGION WILL BE PEACEFUL TO PRACTICE.

  • @MuhammadMuddaththir
    @MuhammadMuddaththir 2 วันที่ผ่านมา

    E rora ma se epe, baba elepe

  • @truthpeace5644
    @truthpeace5644 วันที่ผ่านมา

    Ti Ile tabi ilu kan ba n toro, Omo ale ibe ni ko ti dagba. Omo ale ni o n fi owo osi juwe Ile Baba re. Se e le se bee si Emir Kano, Sokoto, Ilorin abi Saudi? E n ri oba fin nitori orisa Saudi, o ma se o.......

  • @abrahamaugustus1619
    @abrahamaugustus1619 4 วันที่ผ่านมา +1

    Those are dirty words, Imam and his rebels should be axed from that position.
    He should not be allowed to sit with th King

  • @hamzathameedolayiwola3036
    @hamzathameedolayiwola3036 3 วันที่ผ่านมา

    Haaa, Baba yii
    E o sí bẹrù Ọlọrun....

  • @odeyoyinyusuphabiodun8419
    @odeyoyinyusuphabiodun8419 4 วันที่ผ่านมา +1

    Man, you are part of those fueling this problem 🙄. How can you be narrating an outcome of a meeting that you are not part of without even providing a single piece of evidence to back your point. Where is the proof of what you are saying here.

  • @bellomuhammad-lk5ih
    @bellomuhammad-lk5ih 4 วันที่ผ่านมา +1

    Eni subu babalobanika...that taofeek need to be dealt with...I just pity him...al because money been given to him!!!!

  • @basiruazeezadeyemi
    @basiruazeezadeyemi 3 วันที่ผ่านมา

    Baba are you not the supporter of kabiyes, let every one support who who she want

    • @fataisanni7106
      @fataisanni7106 3 วันที่ผ่านมา

      Baba ọna wo ni arákùnrin to sọ̀rọ̀ yii fi bu Kabiyesi.
      O fi oju han wipe ara àwọn ti wọn nti Kabiyesi ni ìwọ Baba yii wa.

  • @olabodeolajuwon4318
    @olabodeolajuwon4318 3 วันที่ผ่านมา

    Saudi ati awon onijekuje ni won nda wa lamu nile Yoruba

  • @basiruazeezadeyemi
    @basiruazeezadeyemi 3 วันที่ผ่านมา

    Are you a God

  • @RidwanullahOyewunmi-kp9yz
    @RidwanullahOyewunmi-kp9yz 4 วันที่ผ่านมา +1

    Wahala ago lomapa ice water

  • @SerahGibson
    @SerahGibson 4 วันที่ผ่านมา +1

    ODODO ORO, GBOGBO AWON AWON TI NWON FE GBOGUN TI OGBOMOSHO, BI OLORUN NSE JE OLORUN, TI O BA JE WIPE NSE NI ORO OGBOMOSHO OKAN NI. SUGBON TI O BA JE WIPE OJO TI MO TI DAIYE, NGO GBO GBOGBO IRU EYI RI, SUGBON OHUN KAN NI MO MODAJUPE PE, GBOGBO ENIKENI TI O BA NI ON FE ILU OGBOMOSHO RU, TORIPE NGO RI IRU EYI RI LATI OJO TIMO TI DAIYE, NGO GBO IRU EYI RI. OLUWA YIO RANWALOWO.AMIN. OLORUN YIO GBE WA JERI GBOGBO AWON ENI IBI, OLUWA YIO GBAWA, TORIPE NGO RI IRU EYI RI, OLUWA YIO JOBA NI OGBOMOSHO, LATI OJO TI MOTI DAIYE.OLORUN NGBO, OMO YI KOLE TO ENIA.

  • @mubashirabdulaziz7413
    @mubashirabdulaziz7413 2 วันที่ผ่านมา

    Aye gbogbo awon omo yin yoo ri bii ero yin fun mewolaka

  • @BiolaBalogun-bd9bh
    @BiolaBalogun-bd9bh 3 วันที่ผ่านมา

    But wat is your problem gan an. Wahala ti yin gan poo. Tshebi the matter is the court. Ni tshe ni e ma n mura si Oro kan an kan😊

  • @user-jj5vr3fd5z
    @user-jj5vr3fd5z 4 วันที่ผ่านมา

    SAUDI PEOPLE THINK ABOUT THEMSELVES FIRST BEFORE ANY RELIGION. BUT YORUBAS THINK OF SAUDI RELIGION BEFORE YORUBAS

  • @merrimentproduction2654
    @merrimentproduction2654 วันที่ผ่านมา

    Olórí burúkú ni bàbá radarada yi

  • @OlaegbeDaud
    @OlaegbeDaud 4 วันที่ผ่านมา

    Imoran tiwa siyin logbomoso nipe, gbogbo eyin tenpe arayin lomo ogbomoso gan-an, ni isoro arayin nitori e tiso oro tonbe nile yi laarin Imam ogbomoso ati oba ilu ogbomoso, di oro oselu, enikookan yin kan nsoro ifenu ni, gbogbo yin e lo sora gan ki e mada ija esin sile, e fi kabiesi ati imam sile kiwon pari oro ara won nitori awon ayilara tiwon nso wipe imam kiise ara awon, kinlode tiwon kogba ile ejo lo kiwon lo yanju re dipo tiwon fi nda wahala sile laarin,ilu kinlode tenti oro si oba lenu wipe oba gbodo yo imam ni, e jowo alatunse niki e je, ki a beru oloun, nitori idajo oloun.

  • @Fattylincorn
    @Fattylincorn 4 วันที่ผ่านมา +1

    Igbo tipoju. 😂

  • @rasaqajibade8501
    @rasaqajibade8501 4 วันที่ผ่านมา +2

    Iwo gan oni sinmi lagbara olohun awon omo e onisinmi loju aye ati eleyin e

    • @ditty6828
      @ditty6828 4 วันที่ผ่านมา

      Ko ri fun e bi ero okan re si omolakeji re.

    • @oluwafemiadewole3580
      @oluwafemiadewole3580 4 วันที่ผ่านมา

      Shey won fi Epe se yin

  • @edunjobiejire1499
    @edunjobiejire1499 2 วันที่ผ่านมา +1

    Hypocrite ni yin baba, if truly you are a Muslim, you will support the Imam, over what, firstly as a Muslim you should know that all mosque belong to Allah not to any individual or group or tribes, you should know that the mosque is the property of all Muslim, so the post of imam should be held by a knowledgeable person and imam Dr Yunus Toliat is qualify for the office and he has been there before the present king of Ogbomosho, what truth and justice are you expecting from this matter other than to let the matter remain as it is, let imam be and the king be in peace.

  • @bellofatai7169
    @bellofatai7169 4 วันที่ผ่านมา

    Soun need to implement his authority on the ogbomosho central mosque,imam need to be step aside by the authority of soun.

    • @tijaninafiu1277
      @tijaninafiu1277 4 วันที่ผ่านมา

      Dey play, note it, Baba wa Soun Ogbomosho don't have power to remove Chief Imam Taliet

    • @tijaninafiu1277
      @tijaninafiu1277 4 วันที่ผ่านมา

      You're pathologist lie , I don't said Ayagbo Ayato in the Mosijeed , just make it as explanation

    • @tijaninafiu1277
      @tijaninafiu1277 4 วันที่ผ่านมา

      You're pathologist lie , I don't said Ayagbo Ayato in the Mosijeed , just make it as explanation

  • @adisakabiru6737
    @adisakabiru6737 3 วันที่ผ่านมา

    Tani lo ni weere ton rojo

  • @rasaqajibade8501
    @rasaqajibade8501 4 วันที่ผ่านมา

    Omo ale nie Konig dafun e walahi awon omo ko Le se ori osimape lewon I sue

  • @bellofatai7169
    @bellofatai7169 4 วันที่ผ่านมา

    This is very bad of ogbomosho son to talk to kabiyesi like this.

  • @adeoluwaoladeji834
    @adeoluwaoladeji834 4 วันที่ผ่านมา

    Hummmm o ma se o se jijeti oba je Christian na ni arifin fipo bayi , awon obayeje korawon Jo lati ba ilu ogbomosho je , se bi o se ye ki oloriburuku omo Ile eyeba ma fi enu abuku Kan oba ogbomosho niyi hummmm agba o si ni igbe igbe baje bale Ile Ku Ile dahoro , sugbon momope gbogbo e ma pada leyin ti o ba ya , ilu alafia won si fe so di ilu Ogun nitori ijekuje , o si ma leyin

  • @AbuAbdillahQuillpen
    @AbuAbdillahQuillpen 3 วันที่ผ่านมา

    Why is the king so low in intelligence?
    Shior!

  • @OmoboriowoteenthinOmotoyosi
    @OmoboriowoteenthinOmotoyosi 3 วันที่ผ่านมา

    Is this man mad?

  • @aadeoyemosun0359
    @aadeoyemosun0359 3 วันที่ผ่านมา

    Hmmm. Islam ni yoo bori

  • @Alwarithuun
    @Alwarithuun 2 วันที่ผ่านมา

    Try and read comment
    Muslim will never support your wicked struggle,
    You are trying to use divide and rule method baba agbaya oní sango.
    I heard you saying you will use all your power to remove Imam and send him to Prison.
    You never fear Allah at all baba agbaya keferi elebo baba

  • @user-jj5vr3fd5z
    @user-jj5vr3fd5z 4 วันที่ผ่านมา

    The way my Yoruba Muslims are going now makes me scared of religion war within our means.

  • @bolaelegbede7843
    @bolaelegbede7843 2 วันที่ผ่านมา

    You are just ranting. The Muslim community is ok with him and that is the most important thing. It is in your own interest that there is peace in Ogbomosho. If crisis breaks out, you and the king will not survive it.

  • @user-yx2bn1xc9w
    @user-yx2bn1xc9w 4 วันที่ผ่านมา +2

    Truly, no maturity for you this man , immam is going no where. Also if you are sad, try and take immam to court and stop irritating stories

  • @oladosutunde
    @oladosutunde 4 วันที่ผ่านมา +2

    Baba onirarun niyi, ALABOSI agbalagba ni o taofiki

    • @RhamanWasiu
      @RhamanWasiu 4 วันที่ผ่านมา +1

      Iwotiii osoroyiii wallahi oonini atubotan

  • @toyindosunmu795
    @toyindosunmu795 4 วันที่ผ่านมา

    Omo oko niyin Baba.

  • @rasaqjelili
    @rasaqjelili 4 วันที่ผ่านมา +2

    Taleyin seyin ni olohun ni

  • @tijaninafiu1277
    @tijaninafiu1277 4 วันที่ผ่านมา

    Baba I don't want to disrespect to you. But you saying purely nonsense, you're not defend Islam at all but you're defend ur family which is very unfortunate for you sir . Imam will not remove case at court and Soun Ogbomosho can never remove him and ur family by the Grace of Almighty Allah 🙏.

  • @Kabisanra1
    @Kabisanra1 4 วันที่ผ่านมา +1

    TAOFEEK ori yin ti daru walai imam kin se ologun bi ti e bee ni won o le ni ibi totin n bo oooo

    • @RhamanWasiu
      @RhamanWasiu 4 วันที่ผ่านมา

      Orii babanla awan babare lodaruuu

    • @Kabisanra1
      @Kabisanra1 4 วันที่ผ่านมา

      @@RhamanWasiu omo were ni o

    • @RhamanWasiu
      @RhamanWasiu 4 วันที่ผ่านมา

      @@Kabisanra1 okay kosiyonu omo rederede ni ooo

  • @Alwarithuun
    @Alwarithuun 2 วันที่ผ่านมา

    Baba you are a deep liar WaLlah.
    I followed him and he is only preaching but I heard you saying sango will destroy any liar and you will use anything to fight including shaytan osun, ebora, and so on

  • @mustaphakayodeissah2264
    @mustaphakayodeissah2264 4 วันที่ผ่านมา +3

    This man is really pain. Kilode ti wahala repo bayi. Agbalagba, oro oloro siwakosi gbogbo agbarire, kilode?

    • @RhamanWasiu
      @RhamanWasiu 4 วันที่ผ่านมา

      Igbatii ehoniran ni ofaaa

  • @doslos
    @doslos 4 วันที่ผ่านมา +6

    In this matter, the only way to restore honour and respect to the throne of Ogbomosho, is for Soun to dismiss and send the imam packing. This will establish Soun's authority and also send a strong warning to anyone like him who will contemplate to disrespect and dishonour the throne of Soun.

    • @Fattylincorn
      @Fattylincorn 4 วันที่ผ่านมา +2

      Lol see jokers. You know oba will not try that.😂😂😂

    • @doslos
      @doslos 4 วันที่ผ่านมา

      @@Fattylincorn Of course it's not going to be done directly. All that needs to be done is for Soun in council and the central mosque islamic committee to make the decision, and the Soun will sign and confirm it.

    • @ShinaAbifarin-xy6eo
      @ShinaAbifarin-xy6eo 3 วันที่ผ่านมา +1

      Nonsense

    • @doslos
      @doslos 3 วันที่ผ่านมา

      @@ShinaAbifarin-xy6eo We know that No body, including Soun, Soun in-council and The Mosque Islamic committee can stop him from practicing his religion or being an imam in any mosque of his choice anywhere in Nigeria, that is his fundamental and constitutional right. But since he has chosen to be insurbodinate and disrespectful to the throne of Ogbomosho, he is not fit and can not be the Chief imam of ogbomosho any longer. He deserved to be sacked and discarded out of that Ogbomosho central mosque.

    • @bolaelegbede7843
      @bolaelegbede7843 2 วันที่ผ่านมา

      ​@@doslosStop the joke. The Muslim community is ok with their Imam and that's the most important thing.

  • @laoyesuleimanabubakar4753
    @laoyesuleimanabubakar4753 3 วันที่ผ่านมา

    Ejo man yo to poju jare. Are the chosen mouthpiece of Ogbomosho or you just want to make yourselve look relevant? You talk too boastful and much . Go to court to remove whoever you want to remove ,stop this nonsensical pronouncem on social media. You are not the authority.

  • @user-ov9mc3iu1i
    @user-ov9mc3iu1i 4 วันที่ผ่านมา

    Baba Taofeek Suberu lobanika, e je ki Ogbomosho nisinmi , gbogbo wahala ti e nfa yi ti poju .olohun lo yan kabiesi ba kana olohun lo yah Baba imam 😅, eda olohun kankan ko si leyo imam kuro

    • @RhamanWasiu
      @RhamanWasiu 4 วันที่ผ่านมา

      Okay kosiyonu lase olorun eni Eleni ni yiojogun awan babare atii awan omo re lapaapo

  • @Fattylincorn
    @Fattylincorn 4 วันที่ผ่านมา

    Who knows the facebook of this werey mπn?

  • @rasaqajibade8501
    @rasaqajibade8501 4 วันที่ผ่านมา +3

    Oniro agbalagba
    Ole ni wona oloribuku agba oponu yunusa gbon ju e lo

    • @ditty6828
      @ditty6828 4 วันที่ผ่านมา +1

      Iru iro nborun. Awon omo ale kii sooro mo.

    • @RhamanWasiu
      @RhamanWasiu 4 วันที่ผ่านมา

      Maa worry omin tifee tan leyin ejaa yinusaa bayii

  • @rasaqajibade8501
    @rasaqajibade8501 4 วันที่ผ่านมา +2

    Kini wala e I hope commissional of police is hearing you now nothing we happen imam aye e mabaje gbeyin ni lagbara olohun

  • @user-ov9mc3iu1i
    @user-ov9mc3iu1i 4 วันที่ผ่านมา +1

    If anyone supports Imam in ogbomoso, they get paid for it. That's all. What is your brain

    • @oladosutunde
      @oladosutunde 4 วันที่ผ่านมา

      your evidence

    • @oladosutunde
      @oladosutunde 4 วันที่ผ่านมา

      WALLAHI, RHIS THAN IS SERIOUSLY PAINED BY THE DAY AS LONG AS THE MAN REMAINS IMAM, WA KAN PARA E LASAN

    • @oladosutunde
      @oladosutunde 4 วันที่ผ่านมา

      it was said that oba said he neva see war before, open your line for debate

    • @oladosutunde
      @oladosutunde 4 วันที่ผ่านมา

      Gbo gbo eniyan lo mahun bu Oba won, na only you they always right , alinikan se

    • @ditty6828
      @ditty6828 4 วันที่ผ่านมา +1

      ​@@oladosutundelo si ogun fun kabiesi to ba omo oko ni e. Olopolo yiyoro.

  • @user-yx2bn1xc9w
    @user-yx2bn1xc9w 4 วันที่ผ่านมา +1

    Olotito ni Mewalaka, ko de unkan ti ema shefun , Olorun a juyin lo , e o le Lee mewalaka ni ile oko reee..
    Then Akara toti wo inu ekoo nii, kotun jade moo, ni oro immam Ogbomoso. Torinaa , egba fun Olorun, and stop to be hypocrites. Majority loves Him. Stop doing abosi pelu Oba .why are you
    irritating.muslims

    • @ditty6828
      @ditty6828 4 วันที่ผ่านมา +1

      Eeh!, talo fe le mewolaka nile oko e?? Amoran ni won nfun ko ye enu sososo si nkan ti o ba ri okodoro lori re koto gbenu si. Lo so fun.

    • @RhamanWasiu
      @RhamanWasiu 4 วันที่ผ่านมา +1

      Eyin ni yee olorun niyee

    • @taofeekbello9629
      @taofeekbello9629 3 วันที่ผ่านมา

      This old man has no shame, imaam Taliat is generally accepted alhamdulilah rabbil alameen. Who knows this man before the imaam saga?