Awon ti Egba ati Awon ti losi Port Novo? Donc Awon Ti OWU ti won wa ni Abeokuta tiwon nko? Kabiyesi Eledumare Laji Abbas Eku Ise opolo Amaju yinse Amin
O dabi enipe e ko ranti pe igba Oyo Empire, awon Oyo dabo bo gbogbo Ekiti, Ife, Igbomina,Ijesa, Ondo ati beebe lo. Nwon si ran awon Ilari lo si ibe lati gba isakole. Gege bi apeere, e o ri awon Omo omo Omo etc awon wonyi ni Ikere Ekiti, Ikoro Ekiti ati beebe lo.
ESE OLOTU IRAN OYO TI WON BAFE KO IWE WON MA KO NI YORUBA GEGE BI EDE WON OLOTU IJEBU IJESA OHUNDO ATI EGBA SE AWON YII NI OHUNKO TIWON YATO SI TITI OYO

wao 😮 you just make mention of Yagba and Egbemekun 🙌 mo ro pe emon ni pa Yagba ati Egbe ni oh
Adupe o Oluko agba laji Abass! Eku ise naa.
E seun oluko agba itan womi Lara gidi gan ni, olorun a maa fun yin se
E ku ise o.
Ire ati anu Olorun yio ma ba e gbe o
Oluko Agba otojo meta moti retireti
Gegebi brasil
È kabo Oluko agba
ESE OLOTU AGBA OTUMO SIPE AROMODOMO NAMURUSU NI YORUBA TISE BABA WA OODUDUWA
O dabi enipe e ko ranti pe igba Oyo Empire, awon Oyo dabo bo gbogbo Ekiti, Ife, Igbomina,Ijesa, Ondo ati beebe lo. Nwon si ran awon Ilari lo si ibe lati gba isakole. Gege bi apeere, e o ri awon Omo omo Omo etc awon wonyi ni Ikere Ekiti, Ikoro Ekiti ati beebe lo.
👍💯
Please can you translate the numbers in Yoruba to English please! Thank you sir
BRAZIL
Eru aye bami
ESE OLOTU IJEBU IJESA OHUNDO ATI EGBA ATI BEBE LO KOSI BI WON SEMASO EDE OYO NI SUGBON OLOO LENU WON YATO SI AWON IBINI NIKAN ADE LODAWAPO