ELEYI GAJU OO!! EWO OHUN TO N SELE SI AWON EBI IGBOHO!!

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 23 ต.ค. 2024

ความคิดเห็น • 62

  • @Joladeallison1351
    @Joladeallison1351 4 หลายเดือนก่อน +9

    It is better to divide Nigeria now to save Lives and Properties. Yoruba Nation, no going back

  • @toyinmuyibat2875
    @toyinmuyibat2875 4 หลายเดือนก่อน

    God bless you baba gbagede imo Am so much impressed with this your program

  • @bisolawe1996
    @bisolawe1996 4 หลายเดือนก่อน +2

    Almighty God will fight our battle he will surely take us to our promise land in Jesus name amen

  • @remiomodele3233
    @remiomodele3233 4 หลายเดือนก่อน +3

    Don't worry about the current expressions of ingratitude.
    Baba Banji and Oloye Igboho have our everlasting gratitude, and their names have entered the annals of African and world history.

  • @kolaomilabu3563
    @kolaomilabu3563 4 หลายเดือนก่อน +4

    The simple answer to the question of our behavior in Yoruba is ,Ole ,Ijekuje,lmotara eni nikan,Tenbelekun .Iwa Tara eni ni kan .Omaseo Omo Yoruba Arotomaso lo poju .Nitori ijekuje .

  • @OmitogunDennis
    @OmitogunDennis 4 หลายเดือนก่อน

    Baawa? E ku ishe o! Up Yoruba Nation! No going back 😮.

  • @bolat.o.9343
    @bolat.o.9343 4 หลายเดือนก่อน +1

    E ku ise, e ku eto BGI TV, Olorun a ma fun yin okun ati agbara. Amin

  • @JideCrown-dk7tt
    @JideCrown-dk7tt 4 หลายเดือนก่อน

    Well done baba gbagede imo.

  • @toyinmuyibat2875
    @toyinmuyibat2875 4 หลายเดือนก่อน +2

    Ayafi ki Olorun bawa dupe fun omo Adeyemo igboho osaa
    We shall be free one day
    Yoruba Nation we stand

  • @toyinmuyibat2875
    @toyinmuyibat2875 4 หลายเดือนก่อน

    Talk and do ni chief Sunday Adeniyi Adeyemo

  • @bettylusi584
    @bettylusi584 4 หลายเดือนก่อน

    Eranko ni gbogbo won, awon agba onijekuje ti tiwon ti baje. Olorun a bawa pale won mo.
    Olorun a gba Yoruba Nation fun wa Amin Ase Olodumare.

  • @adeolaosho3431
    @adeolaosho3431 4 หลายเดือนก่อน +4

    Yoruba nation no going back .

  • @euniceadeleye7400
    @euniceadeleye7400 4 หลายเดือนก่อน

    Haaa! O ga o, listening to this our old men and women with what this evil Fulanis are doing to them, it makes me cry, hhehn! On their own land? Habaa! The governor should do something about it now, and he just overlooked it while the fulanis are maltreating his people. Haaa! O ga o aanu awon iya ati baba wa wọnyi ṣe mi o. The only lasting solution is Yoruba Nation. May Eledumare help us o and deliver us from this violent men. Baba Gbagede e kunise ilu sir. Olorun a f'ere si iṣe yin. Ni agbara olorun ẹ ni ṣe lasan sa. Much-loved sir❤💕💖🙏🏾

  • @leahayodele2526
    @leahayodele2526 4 หลายเดือนก่อน

    YES E DIDE OGUN. IJOBA KO NI RAN YIN LOWO. ERAN YIN LOWO..EKOJU IJA SI FULANI..FROM. MAIDUGURI TO OGUN STATE. THE DISTANT IS DIFFERENCE.

  • @michaelajibola3532
    @michaelajibola3532 4 หลายเดือนก่อน

    God will continue to protect and fight his battle and his family but the rebels will never see the light of the day

  • @AdeoluomoIfabunmi
    @AdeoluomoIfabunmi 4 หลายเดือนก่อน

    koniye o, oloribuku number one olubaje, adaluru, iwogangan Ni, alakoko to nɗarin Yoruba Ru, onijere, agbaya OSI, ole oooole, gbajue

  • @oladimejiadekolu2839
    @oladimejiadekolu2839 4 หลายเดือนก่อน

    Dr Adeyemo the best.
    The master of the fakes.
    All his enemies shall leak the dust in the mighty name of JESUS.
    YORUBA NATION NO GOING BACK

  • @taiyeajiboye3968
    @taiyeajiboye3968 4 หลายเดือนก่อน

    Awa omo yoruba ni ota ara wa nitori ijekuje,ika,alabode ni gbogbo awon agba ,politician ati ninu awon oba yoruba.olorun nikan lo le yo omo yoruba ni oko eru.awon fulani hersmen pa wa ni ipakupa se o ye ko ri bee,omo yoruba e jawo ninu ote.e fi sunday igboho lorun sile,E je ki ogun mii eyin ole,onijekuje.Yoruba nation no going back, we need our freedom.

  • @st4r._yxi
    @st4r._yxi 4 หลายเดือนก่อน

    Sunday Igboho ni oooooo

  • @ezraareo4625
    @ezraareo4625 4 หลายเดือนก่อน

    Olorun ,E jowo E BA wa Segun awon Fulanis adaniloro yi . Ki e bawa le won pads si Ile to won o . Baba Gbagede Imo e KO ni sise o . Olorun yio da abo Bo yin o ni Oruko Jesu . Amin .

  • @KehindeoseniSaliman-ou4jt
    @KehindeoseniSaliman-ou4jt 4 หลายเดือนก่อน

    Ekale sir ooo baba mi GBagedeimo EKU eto sir ooo eku ise takun takun sir ooo abo olorun ama ba Yin GBE tie bi ti ara yin na ooo Yoruba nation no going back

  • @estherewetuga8245
    @estherewetuga8245 4 หลายเดือนก่อน +2

    Nigeria is in big mess
    Nigeria an expired, fake, failed and fraudulent and lawless country end it now for peace and to save lives
    Yoruba Nation no going back
    Yoruba Nation is the only Solution
    We are grateful to Prof Banji Akintoye and Chief Sunday Adeyemo Igboho Oosaaaaa our great hero
    May God blesss them both and their family

  • @Saadu-x1p
    @Saadu-x1p 4 หลายเดือนก่อน

    Olagbara. ooo Yoruba

  • @JideCrown-dk7tt
    @JideCrown-dk7tt 4 หลายเดือนก่อน

    Tuale for Oloye Sunday Igboho Oosa.

  • @comfortadeleye128
    @comfortadeleye128 4 หลายเดือนก่อน

    KUKUNDUKU 😃😃😃😃😃

  • @sunodu8555
    @sunodu8555 4 หลายเดือนก่อน

    HOPE IN NIGERIA IS HOPELESSNESS

  • @adepitandavid1277
    @adepitandavid1277 4 หลายเดือนก่อน

    Those in diaspora that want us to remain in Nigeria should come to the country.
    Travel from Lagos to Maiduguri and see what will happen. All boarder closed, Fulani didn't allow our farmers to access their farms. Where do we go from here?
    Those in diaspora that blamed Chief Sunday Igboho for challenged Fulani should come to Nigeria to see things for themselves.
    They are working overseas, are their jobs and works not in. Nigeria?

  • @AdeoluomoIfabunmi
    @AdeoluomoIfabunmi 4 หลายเดือนก่อน

    Iro lopa,

  • @ditty6828
    @ditty6828 4 หลายเดือนก่อน +1

    Eriti ni Ijoba Ibile Obafemi/Owode ni Ipinle Ogun.

  • @mygodisgreatt.elizabeth2091
    @mygodisgreatt.elizabeth2091 4 หลายเดือนก่อน

    Babagbagede Imo don't mind them agba ofifo to ndun yanmuyanmu ni won, awon oni yeye gbogbo,won ko gelete won mi hin. Yoruba Nation no going back. Yoruba Nation now now now. ORILE EDE YORUBA NI A FE OOOOOOO. Don't mind the one that called himself Kakanfo. Chief Sunday Igboho Oosa God bless you jare.

  • @christianasktoluwase2893
    @christianasktoluwase2893 4 หลายเดือนก่อน

    BABA GBAGEDE KILO SELE SI IGBOHO OOO???
    EKU OJUMO DEAR

  • @Omowunmi0412
    @Omowunmi0412 4 หลายเดือนก่อน

    E ma ko won fun Olopa mo .E ti owo ile bo Bi e ba ti yanju awon bi melo kan won a sa fun yin .E yi owo pada fun won

  • @KoladeSamuel-rg3nd
    @KoladeSamuel-rg3nd 4 หลายเดือนก่อน

    But this Imam self resemble Fulani

  • @YemiOdejobi
    @YemiOdejobi 4 หลายเดือนก่อน

    Aye Dupe Dagboru Onidoti Koledara lagbara Olorun .Eladuwa konijeki gbogbo awon oderinde Songbeto tintele lehin bi’ Ajakalearun deede onishorire debiti won o lalubarika afibi biwon jawo ninu iwa Ibaje ati inubini t’oun oro-alufansha tiwon nsosi awon Babawa Prof Banji Akintoye {PBA} & Oloye Dr Sunday Adeniyi Adeyemo “Igboho Oosa” Eyinju-Olodumare Angelitiwa nile Yoruba {CSI}

  • @bettylusi584
    @bettylusi584 4 หลายเดือนก่อน

    Ki President Tinubu jowo ki won bawa yonda Dr Sunday omo Adeyemo, ki won le raye wa gba wa sile lowo fulani panipani

    • @feyikemioderanti3999
      @feyikemioderanti3999 4 หลายเดือนก่อน

      Please let him stay out of this.Some people’s plan are evil.

  • @florencedairo3888
    @florencedairo3888 4 หลายเดือนก่อน +1

    E lo wan kan se si awon Eranko yi, eye ko won fun Olopa mo, ema pa won iwo n se npa yin ki ma sun won Siri yin ti to, elo ko ra yin ko. Ero Oko yin, igba ti Malu won ba fe ku tan, won kora won ra won lo si ilu. Won. Elo wa nkan si Oko yin, ti ijo o ba dasi, elo wa nkan se si won . E ye ra Malu won mo, eye pari wo mo, Inu awon Adari yin ko ri ti yin ro, elo gbe yin ara yin ki won to gba yin tan tori awon Oba to ko Malu fun won ti won fi npa yin , elo ri si awon Oba ika yi. Ikan ti ema se ni ye. Elo dale ki e ma wo ki ma gba yin etu ja de ki e gbe ja ara yin tori awon adari yin ti ta yin Fulani pe ki e ma seru won ,eyin le ma gba ara yin kale.

  • @SerahGibson
    @SerahGibson 4 หลายเดือนก่อน

    ORO RUNRUN,KINI KATI GBO,OLUWA YIO PA NWON RE KURO NI ILE WA.KOSI YORUBA TI O LO DA NWON LAAMU NI ILU NWON, KO TILE LE ROGBO BIKOSEPE KI FULANI FI AGBEGBE WA SILE FUN WA.KI ENYIN NA MASE TA ILE FUN NWON MO.AMORAN TI MONI LATI SOFUN NYIN NI YEN.

  • @st4r._yxi
    @st4r._yxi 4 หลายเดือนก่อน

    Igboho Oosaa EKUN OKO FULANI

  • @OjoDele-tc8zu
    @OjoDele-tc8zu 4 หลายเดือนก่อน

    Fulani me lo ni e ko fun olopa eyin we re olote edaruko ago olopa melo ni eko fulani si olosi elerun

  • @Omowunmi0412
    @Omowunmi0412 4 หลายเดือนก่อน +5

    Ko si ijoba to ma gba yin .E fi agbara nkan ti e ba ni lowo fo le won danu kuro ni ilu yin .Awon Fulani ko fe oju boro rara .E mu ni like daidain ki e le won danu patapata .

  • @OyeyemiSalau
    @OyeyemiSalau 4 หลายเดือนก่อน

    Ki won ye na Ile fun won mo
    Ki won da owo won pada fun won

  • @iretiebiesuwa9071
    @iretiebiesuwa9071 4 หลายเดือนก่อน

    E ku ise takuntakun Olorun a kuku saanu wa

  • @gracesowunmi4838
    @gracesowunmi4838 4 หลายเดือนก่อน

    OJUBORO KO SE GBO MO LOWO EKURO OGUN NI KE FI PA GBOGBO ERON WON ATI AWON ELERON NITORI E FI IDON HON WON NI WON SE NJE NKON OKO YIN TE BA FI OGUN PA WON ARA WON A BALE

  • @jemilaagbaje6238
    @jemilaagbaje6238 4 หลายเดือนก่อน

    Awon alaimokan niwon baba gbagede, toba dawon loju pe ogun wa lowo won kiwonlo bawa face Awon bandits ninu igbo

  • @lamidiwilliams6095
    @lamidiwilliams6095 4 หลายเดือนก่อน

    Awon boda wa to wa ni joba lo ni Malu. Won fi Fulani bo ju. Otito ni KARMA

  • @OyeyemiSalau
    @OyeyemiSalau 4 หลายเดือนก่อน

    Eku eto baba gbagede imo
    Ki won lewon dani kuro ninu ilu
    Ti won o ba gbo ki won role fun won
    Ti won ba ri idamu wa gbailu won lo

  • @santeebaba
    @santeebaba 4 หลายเดือนก่อน

    Ododo oro.Enu Yoruba o ko.Aje banu la ma nje

  • @daviesoyetunji9994
    @daviesoyetunji9994 4 หลายเดือนก่อน +1

    @babagbagede...'Ebi Igboho'? Ba wa. Sugbon ebi dede eni ni won je, temi, tire , ti gbogbo eni ni won. A dupe fun iranlowo re.

  • @leahayodele2526
    @leahayodele2526 4 หลายเดือนก่อน

    E.JEKO DOGUN...EDA FULANIS LAMU...OLE NIWON O SOCIAL FIGHT NI KI E FUN WON.

  • @imoleadini
    @imoleadini 4 หลายเดือนก่อน

    Oloye lgboho.akukuni.fio sawari.osini kuku kuku.afikoye.tomotomo

  • @GaniatAlakeAlli
    @GaniatAlakeAlli 4 หลายเดือนก่อน

    Oroleso

  • @kolaomilabu3563
    @kolaomilabu3563 4 หลายเดือนก่อน

    The simple answer to the question of our behavior in Yoruba is ,Ole ,Ijekuje,lmotara eni nikan,Tenbelekun .Iwa Tara eni ni kan .Omaseo Omo Yoruba Arotomaso lo poju .Nitori ijekuje .

  • @bosedelameed8441
    @bosedelameed8441 4 หลายเดือนก่อน +5

    Yoruba Nation no going back

    • @adeoyebalogun949
      @adeoyebalogun949 4 หลายเดือนก่อน

      😢Yoruba Nation No going Back. It most nbe Actualised😅

    • @adeoyebalogun949
      @adeoyebalogun949 4 หลายเดือนก่อน

      Yoruba. Nation Is a MUST.

  • @daviesoyetunji9994
    @daviesoyetunji9994 4 หลายเดือนก่อน +1

    @babagbagede...'Ebi Igboho'? Ba wa. Sugbon ebi dede eni ni won je, temi, tire , ti gbogbo eni ni won. A dupe fun iranlowo re.

  • @daviesoyetunji9994
    @daviesoyetunji9994 4 หลายเดือนก่อน +1

    @babagbagede...'Ebi Igboho'? Ba wa. Sugbon ebi dede eni ni won je, temi, tire , ti gbogbo eni ni won. A dupe fun iranlowo re.

  • @daviesoyetunji9994
    @daviesoyetunji9994 4 หลายเดือนก่อน

    @babagbagede...'Ebi Igboho'? Ba wa. Sugbon ebi dede eni ni won je, temi, tire , ti gbogbo eni ni won. A dupe fun iranlowo re.