Lati ojo ti mo ti de aye,,nko ti ri iru alfa eleyi ri oooo. Emi ro wipe gbogbo won ni elesin jagidijagan ni. Ha Olorun jowo bami fun baba yi ni emi gigun ati alaafia.
se pe awon alfa gidi shi wa ninu awon alfa , olorun awa pelu yin , God bless you alfa , adura yin agba fir saying the truth to the remaining alabosi alfa , eseun fun iwa dara dara yi o
Oponu lo po ju ninu awon were alakatakiti esin. Iro ati asan lo gbe esin awon arabo duro. Gbogbo iwe won ati anobi adoku do alaye ajipata pupa, iro ni. Anobi naa ni jubril, ohun naa ni allah olowo otun meji 😂.
Jesakumu llahu kairan jesa ha
Lati ojo ti mo ti de aye,,nko ti ri iru alfa eleyi ri oooo. Emi ro wipe gbogbo won ni elesin jagidijagan ni. Ha Olorun jowo bami fun baba yi ni emi gigun ati alaafia.
God bless you sir Afa mi
Thank you Alfa , you are the only alfa that preach endurance and peace. Thanks
God bless you and your family
You saying the truth baba
Amin olohun ki ni fun won SE
se pe awon alfa gidi shi wa ninu awon alfa , olorun awa pelu yin , God bless you alfa , adura yin agba fir saying the truth to the remaining alabosi alfa , eseun fun iwa dara dara yi o
Oloriburuku ni Mufty Iwo
They want yoruba to be stagnant but they will surely fail God bless you baba.
I.hope they wil listen..but they won't
atide si yin lorun
E seun baba
Oponu lo po ju ninu awon were alakatakiti esin. Iro ati asan lo gbe esin awon arabo duro. Gbogbo iwe won ati anobi adoku do alaye ajipata pupa, iro ni. Anobi naa ni jubril, ohun naa ni allah olowo otun meji 😂.
Original Allah wa ninu kaaba( okuta Quraish), muhamed ni PR allah, jubril ni middleman.
3 in 1😂😂
Ara won o gba o. 😅
Aimokanmokan, Se alfa ni eleyi. Ara won ni iwo na. Iro lasan, yoruba level.
Olopolo dudu leleyi jare
were kan ti yoju ninun won. Omo ale jatijati
Iwo gangan ni olopolo dudu. Were alainironu. Come to Saudi Arabia, they have so many idols, they're celebrating Halloween now in their country.
Dindinrin ni gbogbo yin
Smile
Oroyi tipoju @@ojlinksglobal1616
Oponu afofun gbe mu, amukunmeko
Na today you see am? Na because your islam don cast, all of you are the same
Ibo leleyi ti keu gan nan? This is an example of those that are given us problem in Islam. Alfa Elebo 1. Iwo gangan ni baa laakaye
Laakaye re ti sonu ti pe. Won ti paaro opolo re pelu sawdust, iwo gangan ni won nba wi.