LAST WARNING TO CHIEF IMAM OGBOMOSO FROM THE PALACE OF OBA GHANDI AFOLABI OLAOYE SOUN OF OGBOMOSO

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 27 ม.ค. 2025

ความคิดเห็น • 20

  • @SerahGibson
    @SerahGibson 8 หลายเดือนก่อน +1

    OHUN KAN NI MO FE FI DA NYIN LOJU, EJEKI IMAM YI LO SI IRAN TI O BA TI WA, AROGANT OMO NYEN TI POJU, SE ENYIN NA MO DAJUPE, ENITI YIO BA SONU,BI NWON TONI TOLA FON FERE ODE, KONIGBO ON NA NI YIO SI FORI ARA RE GBE, TORIPE OMO ESU GBAA PATAPATA NI OMO NYEN, SE O GBE ARONI MIN NI,EO WA RI PE ARINFIN, AWON WO NI NKI LAYA, TI OGBOMOSHO BAFI LE FI OMO YI JE LEMOMU,ENYIN ARA OGBOMOSHO LAPAPO,TI EBA JEKI OMOKUNRIN YI JE IMAM,ORO OGBOMOSHO TI DI, ETIFE FOJE BO OLOSA LOWO,A WA KU BABA ENITI YIO BO, ENITI O BA FI OMOALE JOBA,WAHALA TI E MA DA SILE NI ILU OGBOMOSHO,TI O BA DI OJO IWAJU,AGBARA NYIN KONI KA, IRU RE KO SELE RI NI ILU OGBOMOSHO,GBOGBO OHUN TI O WA NIBE NI KI O LO SI,ILE EJO AGBAIYE, KI O LO PEJO,AMORAN TI EMI NI LATI SO FUN NYIN,NITORI OLA, IMAM KISE OMO ILE AYILARA, KINI DE TI KO LOSI INU IRAN TI O BA WA, ENITI O BA GBOWO LOWO OMO AKOJI ONIGBERAGA,OTILE RUN GBOGBO EDA ALAIYE NINU, TODAY IS 25-05-25.TORINA AWON ARA ILE AYILARA TI SOPE KISE OMO AWON. TI OMI NYIN BA TEYIN WO IGBIN NYIN NI ILU OGBOMOSHO.ONBO ONBO,AWON LAMDE DEE NYIN NI OGBOMOSHO. EFI OJU NYIN SILE KI E YA OJU NYIN DADA,KI TALUBO MASE WO, ERANTI ILORIN O,GBOGBO ENITI O BA RI COMMENT YI,KI O LOFIPAMO SORI,ACCAI RE ABI BAWO NI ENSE PE, EMI MOPE TI O BA DI OJO IWAJU,IRANDIRAN ENITI O BA GBOWO LOWO RE, PE AWON OMO TI O BA TI ARA RE JADE NINU ILE AYILARA, YIO JIYA ALAJOBI. EGUN TI KOSI LE TAN LAILAI NI, TORINA MO GBADURA FUN ENYIN OMO ILE AYILARA,PELU ASE TI OLORUN FI DA AIYE ON ORUN, KI ENINA DA OWO RE PADA, KI EJEKI OGUN O MI. GBOGBO AGBAIYE MOPE ISOKAN NIWA. SUGBON BOBO YI KOLE JE IMAM NI ILU OGBOMOSHO,KINIDE TI KO MO DUN MOHURU MOHURU MO SHOUN ANA,MAY HIS SOUL REST IN PEACE,SUGBON KINI KAN NI MOPE, ILE OGBOMOSHO KONI DALE, ENITI O BA GBE OMOKUNRIN YI WA, KI O GBE PADA SIBI TI O BA TI GBEWA LO. OMO ILU OGBOMOSHO WO NI ENYIN RI KI O RI BI O SE RI NYEN. GBOGBO EDA KEDA TI KOBAFEKI ILU OGBOMOSHO O TORO, OHUN TI O BA TO SI NI KI OLUWA SE FUN IRUFE ENI BE, THE WHOLE WORLD HAS KNOWN HE IS NOT BELONGS TO THAT FAMILIES, ENOUGH IS ENOUGH. ATUBA, TUSE, FUN ILU OGBOMOSHO ATI GBOGBO ENYIN OMO OKO GIDI, TIKI SE ATOHUNRINWA NI ASE OSA POPO TI NWON FI TE ILU OGBOMOSHO DO,AMIN ATI ASE OLORUN OBA.

  • @abimbolaojo2761
    @abimbolaojo2761 8 หลายเดือนก่อน +3

    Bi agboole kan ba n toro, omo ale ibe ni ko tii dagba. Bi omaale ba dagba tan te run wa fi omaale je olori esin, gbogbo e daru niyen. Ki Lemoomu lo yanju oro ibi to ti se wa na.

    • @olabodeolajuwon4318
      @olabodeolajuwon4318 6 หลายเดือนก่อน

      Religion of peace my foot very inhuman beings

  • @OgunkunleMoroof
    @OgunkunleMoroof 8 หลายเดือนก่อน +2

    Truth be told,he is not under any control of any traditional authority or leadership.its because he doesn't know or he is not too well endowed with his rights in Islamic beliefs and faiths.Religion stands above anything in any society.be it Islamic and Christian religion beliefs.This people's want someone they can cow or bow under the traditional beliefs or authority.its because those that have been taking up that imamship position have been given in to the traditional institution.and the new imam wants to put things in order and fights for his rights.peoples do believes in old order.the way they have been doing things is wrong.and the young man wants to set the records straight

    • @sadiqtijani9824
      @sadiqtijani9824 8 หลายเดือนก่อน

      Don't mind them they just want one Illiterate they will be pushing up and down and can't even stand and defend his religion and followers

    • @TheOguntola
      @TheOguntola 8 หลายเดือนก่อน

      By insulting the king, is the king from iyilara family? Stop there

    • @sadiqtijani9824
      @sadiqtijani9824 8 หลายเดือนก่อน

      @@TheOguntola Oga can you tell us how he insulted the king let's hear because the king himself never said he insulted him rather he said the problem is within the Imam's family. As a matter of fact, a good Muslim an of course an Imam of his kind will never insulted a leader because our religion forbid us from such attitude.
      So kindly explain to us how he insulted the king?

    • @abimbolaojo2761
      @abimbolaojo2761 8 หลายเดือนก่อน

      Omo ale mii. So because you are Imam, all other religions are old order? E maa ni arojinle. Humanity surpasses religion. Any religion that suppresses humanity and right of others to live is a bad religion and should not be practised among humans

    • @sadiqtijani9824
      @sadiqtijani9824 8 หลายเดือนก่อน

      @@abimbolaojo2761 Epele! who is surpressing who in this matter now? You guys even take the matter upon yourself more than the king himself just because of your hatred and hypocrisy (Awon Abobaku)
      The king himself has said he has no problem with the Imam but the family should solve the problem within themselves.
      So what is you guys headache?

  • @OgunTimothy
    @OgunTimothy 8 หลายเดือนก่อน +3

    Ti idile kan ba ntoro, Omo ale ibe ni koti dagba.

  • @oladosutunde
    @oladosutunde 2 หลายเดือนก่อน

    There is no message here other than wanting Imam under the traditionalist, this you cannot achieve insha'Allah, Yoruba level, iro lasan

  • @olalerelukman9120
    @olalerelukman9120 8 หลายเดือนก่อน

    Q