Update on the meeting outcome among Muslims, Christians and Onisese

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 8 ก.พ. 2025
  • Ababo ipade alaafia laarin #muslim #christian and oni #isese

ความคิดเห็น • 205

  • @MuyiwaDare
    @MuyiwaDare หลายเดือนก่อน +26

    I can't love you guys less Prof. Tani Olohun (PhD) & Janosi 🎉🎉❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤

  • @akoredeogunsola8620
    @akoredeogunsola8620 หลายเดือนก่อน +25

    God almighty will continue to protect you, you're truly a blessing to Yoruba land.

  • @akindelegiwa5874
    @akindelegiwa5874 หลายเดือนก่อน +20

    Omode ni o, sugbon olorun ti pe yin ni pataki fun awa iran Yoruba gidi lati pada si ile,, ki awa omo Yoruba le e bo ni inun ide esin ajeji,, ki a maa ba ma damu kiri maa tani olorun ki olorun olodumare jeki e dagba darugbo lase olorun olodumare❤❤❤

  • @obaola
    @obaola หลายเดือนก่อน +22

    May Olodumare continue to bless and guide you 🙏🏽

    • @akindelegiwa5874
      @akindelegiwa5874 หลายเดือนก่อน +2

      Amin ase,, ati gbogbo wa ooo

  • @elizabetholanrewaju6921
    @elizabetholanrewaju6921 หลายเดือนก่อน +14

    You are blessed Tani Olohun❤

  • @sojibabalola1264
    @sojibabalola1264 หลายเดือนก่อน +15

    Taani olorun, opolo re o ni joba. Kare omo oko Yooba👍

  • @SamsonAdeyanju-w8l
    @SamsonAdeyanju-w8l หลายเดือนก่อน +5

    Muslims will never allow this peace move to succeed, Tani olohun you are right.

  • @seunrahman4828
    @seunrahman4828 หลายเดือนก่อน +12

    God will continue to protect you ❤❤❤

  • @tee4all20000
    @tee4all20000 หลายเดือนก่อน +9

    You are a blessing to Yoruba race

  • @fkay4159
    @fkay4159 หลายเดือนก่อน +16

    God bless Tani olohun, they are trying to islamize yoruba very thoughtful

    • @akinsomoAkin
      @akinsomoAkin หลายเดือนก่อน

      Mumu

    • @MariaCypriano-o3m
      @MariaCypriano-o3m หลายเดือนก่อน +1

      Iyalayae ni mumu odedo

    • @OmoIrunmole29
      @OmoIrunmole29 หลายเดือนก่อน

      Oloriburuku somebody Omo ajagungbale ​@@akinsomoAkin

  • @oluwadaredavid836
    @oluwadaredavid836 หลายเดือนก่อน +1

    Infact, Tani Olohun you are a genius... I love your work. Keep on

  • @therock9027
    @therock9027 หลายเดือนก่อน +14

    Even Akewugbagold is untrustworthy

    • @LewisMuturi-b7u
      @LewisMuturi-b7u หลายเดือนก่อน +4

      Ọmọ irankinran Gambari-Fulani ni

  • @davidapalowo8985
    @davidapalowo8985 หลายเดือนก่อน +8

    I said it Jamba n ta fun jambata iro npa fun ro esin ajeeji ko le sise nile Yoruba isese lo ni ile Yoruba esin ajeji ma wole patapata thanks Tani Olohun god bless you

  • @ayodeleoso8617
    @ayodeleoso8617 หลายเดือนก่อน +9

    Prof Tani Olorun and Dr Ajanasi tani olorun❤

  • @almightyjagaban8939
    @almightyjagaban8939 หลายเดือนก่อน

    You are too brilliant brother. Eledumare will keep blessings you

  • @oluomopeter2936
    @oluomopeter2936 หลายเดือนก่อน +6

    Akewugbagold and his people know that a lot of people are living Islam that's why they are trying bringing sharia law

  • @jomoniwaoronla3873
    @jomoniwaoronla3873 หลายเดือนก่อน +13

    Aboru boye 🎉

  • @akindelegiwa5874
    @akindelegiwa5874 หลายเดือนก่อน +5

    Olorun olodumare ti pa gbogbo egun run lori ile Yoruba,,, olorun olodumare e sehun ooo isese lesin alafia❤❤❤fun iran awa omo Yoruba gidi,,, ifa ni olorun olodumare gbe fun iran omo alade lati maa towa si oju ona ti olorun fi fun wa❤❤❤professor wa, ki o pe pe pe fun wa ooo lase olorun olodumare❤❤❤

  • @tanimowookusaga4856
    @tanimowookusaga4856 หลายเดือนก่อน +19

    Kingship matter is our traditions and culture. It is under the suzreinty of the Isese. Ko kan Musulumi rara. Ifa ni won fi te ile Yoruba do. Gbogbo ile Yoruba ni o ni odu to te do.

  • @seunrahman4828
    @seunrahman4828 หลายเดือนก่อน +5

    God bless you more ❤❤❤

  • @BeatriceAyodeleAyeni
    @BeatriceAyodeleAyeni หลายเดือนก่อน +6

    Isese ni agba, Ema fi esin ajoji ba ile YORUBA je o

  • @jamesoladipupo4759
    @jamesoladipupo4759 หลายเดือนก่อน

    The song always bring me here again and again 😂😂

  • @isholakoladesamuel3477
    @isholakoladesamuel3477 หลายเดือนก่อน +4

    Our Yoruba ancestors will bless you Tani Olohun.

  • @akinwumioluwafikayo3554
    @akinwumioluwafikayo3554 หลายเดือนก่อน +8

    Akewugbagold is a double standard man.
    He's just trying to conquer yorubaland for Muslim.
    Sobe selu eda ni Akewugbagold

    • @okeemmanuel2649
      @okeemmanuel2649 6 ชั่วโมงที่ผ่านมา

      All muslims are birds of the same feather

  • @MariamAtoke-v8h
    @MariamAtoke-v8h หลายเดือนก่อน

    Tani Olorun ka re omo ilu ti olorun fi ogbon ati o ye da nitoriwipe ibadan ki se ilu la San ni ile yoruba ati Nigeria la pa po ❤❤❤

  • @gbengakolade6366
    @gbengakolade6366 หลายเดือนก่อน +8

    I don't know what Baba Takutijesu is doing in that meeting. He has been doing well but they are trying to mark him down, using Akeugbagold, who is the Head of Department of the Teqqeyah Department.
    Awọn Baba ilẹ Yoruba tunti bẹrẹ diẹ diẹ niyen, bi nwọn se maun gba igbakugba nìyẹn. Iwa ọmọluwabi koṣe fi ba awọn ọlọgbọn ẹwẹ ati onijagidijagan lo. Awọn to jẹpe ẹsìn wọn gb'awọn láàyè kiwọn parọ tan eniyan jẹ ni nwọn nṣe pade pẹlu laini ọwọ ijoba ninu.
    Ao ran awọn Baba yẹn n'isẹ o. Ki awọn Baba yẹn lọ sinmi, ki wọn si mafi ọrọ ba àwọn ọdọ ro kiwọn to gbe igbesẹ kan. Igba tiwọn tiun kọja lọ, ki nwon ma ba ija tí àwọn ọdọ nja fitafita ati ọjọ ọla jẹ fun awọn ọmọ toun mbọ lẹhin. Bi wọn se fi aye gba ẹsìn àjèjì buruku yi latibẹrẹ ni nwon tun mba bọ diẹ diẹ nìyẹn.

  • @abdullazizabass4860
    @abdullazizabass4860 หลายเดือนก่อน +1

    Brother, awon alale a gbe e...I like you because you didn't allowed yoruba cultural heritage to be soiled.....keep it up

  • @adegbolaadesola1954
    @adegbolaadesola1954 หลายเดือนก่อน

    Thanks!

    • @taniolohun9915
      @taniolohun9915  หลายเดือนก่อน

      You are welcome sir...thanks for the support my surname shaker

  • @AuntyYinkaRo
    @AuntyYinkaRo หลายเดือนก่อน +38

    Yoruba is under siege!! We all have to watch carefully the process. Ewo lo kan awon aafa ninu oba yiyan? Wahala isese niyen!! Kini tiyin? E shogba yin! Aja kii roro ko sho ojule meji.

    • @binaryworld4000
      @binaryworld4000 หลายเดือนก่อน +13

      They want to install another Rasheedi iwo...,esin ofo ni isilamu

    • @akindelegiwa5874
      @akindelegiwa5874 หลายเดือนก่อน +10

      Olorun olodumare e se adupe fun igbedide iran awa omo Yoruba gidi ati igbedide ile Yoruba gidi lapapo ❤❤❤

    • @mugabezion5763
      @mugabezion5763 หลายเดือนก่อน

      It's muslims who want to sell the whole land to their fulani masters. Oluwo of Iwo has already sold the entire iwo land to fulani hausas.

    • @joyceolusola8549
      @joyceolusola8549 หลายเดือนก่อน

      It is not their fault,it is the fault of the Yoruba afobaje,ijekuje TI ba tiwon je. Bawo ni won SE nfi Christian/ Muslim JE OBA ni Ile Yoruba. Gbogbo AWON asise wonyi NI AWON babanla WA SE TI OMO Fulani so Ara re di OMO Yoruba. Gbogbo AWON AGBAAGBA Yoruba lo la oju kale ti Oluwo Fi LO fe Fulani lai mo wipe Fulani agenda of taking over Yoruba land NI. Tomorrow OMO Fulani YIO je Oluwo. Yoruba land is in TROUBLE

    • @leahayodele2526
      @leahayodele2526 หลายเดือนก่อน +1

      TANI OLORUN..OLUWA TI PE IWO YI. OLORUN YIO MU E DURO DOPIN.. KONI RE E O.❤

  • @FataiAdeshina-j3o
    @FataiAdeshina-j3o หลายเดือนก่อน +5

    The foreign religions be relegated awkward when kingship in yoruba land is involved. This is a traditional abode hence never concerned foreign religions. They should allow the traditional institutions to holdforth to their territory. Any foreign religions be it Christian or Muslim suddenly mingle with the institutions be warned.

  • @KaflatKaflat
    @KaflatKaflat หลายเดือนก่อน +2

    What i like most is that music composed for the alisunna😂😂😂😂😂

  • @engradeola3253
    @engradeola3253 หลายเดือนก่อน +1

    😂😂😂😂
    It's the song for me, this egbon no go kill me, ajanasi, we'll done o😅

  • @WaleWale-d7y
    @WaleWale-d7y หลายเดือนก่อน +6

    Esin ofo lesin musulumi, they can't change, they are same everywhere in the world..

    • @akinsomoAkin
      @akinsomoAkin หลายเดือนก่อน +1

      Oloribu ni o

    • @OmoIrunmole29
      @OmoIrunmole29 หลายเดือนก่อน

      ​@@akinsomoAkinoni ku ree

    • @Kantz1
      @Kantz1 หลายเดือนก่อน

      @@akinsomoAkin Èébú asán àti èpè tí kò lè ṣẹ ni Musulumi máa fi ńṣe èsì ọ̀rọ̀ gidi torípé wọ́n mọ̀ pé àwọn ò l’ọ́rọ̀ kankan lẹ́nu. Gbogbo wáàsí Musulumi ò ní kókó ọ̀rọ̀, òfo ló bá dé!!! That’s why they generally resort to violence pretty quickly. Awọn oni-jàdídí-jàgan!

    • @akinsomoAkin
      @akinsomoAkin หลายเดือนก่อน

      @@OmoIrunmole29 ko ni ye o, iku ofo ni wa ku.

    • @Kantz1
      @Kantz1 หลายเดือนก่อน

      @@akinsomoAkin Oró tí mbẹ ninú Islam ju ti tramadol lọ. Nitoripé Islam a máa pa’ni níyè tán pátápátá.

  • @elizabetholanrewaju6921
    @elizabetholanrewaju6921 หลายเดือนก่อน +7

    Aja mi Bello 😂😂😂

  • @bolajisamsontunde6629
    @bolajisamsontunde6629 หลายเดือนก่อน +4

    Our camera man has very sweet voice

  • @ayodeleoso8617
    @ayodeleoso8617 หลายเดือนก่อน +2

    Prof Tani Olorun you are welcome❤

  • @adebajolanu7755
    @adebajolanu7755 หลายเดือนก่อน +4

    Tani olohun himself ❤

  • @Holly-Starh
    @Holly-Starh หลายเดือนก่อน +1

    I just hope we get a sensible king that loves Yoruba race in Oyo, make we no go get another Rashidi.
    Olohun a ma so wa oo.

  • @WaleWale-d7y
    @WaleWale-d7y หลายเดือนก่อน +8

    Akewugbagold gan ko lenu oro, aimoye igba lo ti tabuku kristiani ati Onisese.

    • @mercyjoy5409
      @mercyjoy5409 หลายเดือนก่อน +4

      believe akeugbagold at your own risk , his the agent AJJ and umura pilgrim and he knows Islam is going to perish finally soon that's why his working tiredness for by force peace

    • @akinsomoAkin
      @akinsomoAkin หลายเดือนก่อน

      ​@@mercyjoy5409dey dream

    • @segunogunwande2978
      @segunogunwande2978 หลายเดือนก่อน

      The religion that is as light as a feather. The Islamic leaders are the problem, they're the trouble makers. Without Islam, peace will reign on earth.

    • @MariaCypriano-o3m
      @MariaCypriano-o3m หลายเดือนก่อน

      Hmmmm❤​@@mercyjoy5409

    • @Kantz1
      @Kantz1 หลายเดือนก่อน +1

      @@WaleWale-d7y Ṣeku-ṣẹyẹ ni akeugbagold. Ta ló tilẹ̀ fun ní gold ọ̀hún gan-an? Irọ́ ni gbogbo ẹ̀ bá dé!! Akeugbasand l’ọkùnrin náà ó sì máa wá jẹ́.

  • @WaleWale-d7y
    @WaleWale-d7y หลายเดือนก่อน +5

    Esin ofo lesin musulumi, they can't change, they are same everywhere in the world..Owo ti won ngba lowo Arabu ti da ori won ru patapata..

    • @akinsomoAkin
      @akinsomoAkin หลายเดือนก่อน +1

      Dindinrin

    • @OmoIrunmole29
      @OmoIrunmole29 หลายเดือนก่อน

      ​@@akinsomoAkinOri e daru Omo eru

  • @tidebe
    @tidebe หลายเดือนก่อน +7

    Iwo town is producing more nonentity people in Yorubaland

    • @Kantz1
      @Kantz1 หลายเดือนก่อน

      @@tidebe Anything Islam produces quantity, not quality. Kò si ojulowo ninu Islam, Taqiyya lo máa ńpa’rọ́ fun Taqiyya.

  • @eniowooladapo4802
    @eniowooladapo4802 หลายเดือนก่อน +3

    Akewugbagold mbo wa gba fun isese. E lo koole

  • @turzzie349
    @turzzie349 หลายเดือนก่อน

    Your wisdom and level of understanding pass those ẹgbẹrun kan dem. I can't love you less✌️💯

  • @oluwasanmisojobi7073
    @oluwasanmisojobi7073 หลายเดือนก่อน

    Respect 💯

  • @ditty6828
    @ditty6828 หลายเดือนก่อน +5

    Bi ti baba muyideen ajani bello se nso isokuso kiri na niyen ki won to ku.

  • @bakarekazeem2368
    @bakarekazeem2368 หลายเดือนก่อน +9

    They are just talkertive. They don't have good things right from their scripture to preach.

  • @oe6526
    @oe6526 หลายเดือนก่อน +5

    Won fe fi ipade won di tanioloun ati Baba takutiJesu lowo 🙋‍♀️ mu fun adepoju ati awon affas alakatakiti🤓
    The meeting is to clear the way for sharia across southwest states.
    You can not conquer southern nigeria without first defeating Southwest.
    The only way to capture Southwest is through Chris-trad-islamic conflicts.
    2044 is the year of total take over, ti e eyin yoruba ko ba mura s'oro yin! Awa ti ri ti pe

  • @ainajonathan14
    @ainajonathan14 หลายเดือนก่อน

    you too wise

  • @Ayanwola1
    @Ayanwola1 หลายเดือนก่อน

    Trully Oro Tani Olohun yi jinle ooo.

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni9463 หลายเดือนก่อน +10

    What is Alfas or Imam concern in installing traditional king 👑. Installation of Oba is absolutely for traditional king makers (Afobajes) NOT for Musulumis.

    • @MandiClement
      @MandiClement หลายเดือนก่อน

      Why wouldn't alfas want to get involved when most Obas are handpicked by politicians and not ifa...?
      Obaship is now a thing of the highest bidder... the reason one Oba had the guts to challenge any Oba in Yoruba land who was chosen by the gods to come out. No Royal father came forward. No Royal father said anything.
      Even most Obas talk from both sides of the mouth, you see most siding with Muslims and Christians against traditionalists, demonising and trivialising the Yoruba culture and tradition.

    • @margaretoludotun2351
      @margaretoludotun2351 หลายเดือนก่อน +1

      True talk my brother but the Muslims and some Christian’s leader has suddenly became emergency king installer

  • @Emiola_1
    @Emiola_1 หลายเดือนก่อน +1

    22:20 though 😂
    Mo ti jo kpa 😂😂😂😂
    I have play like 40 times 🤣

  • @ArowoloAjobiewe
    @ArowoloAjobiewe หลายเดือนก่อน +3

    IFA NGBA AIYE LO GBOGBO ELESIN AJOJI TIMO

  • @omofemy4479
    @omofemy4479 หลายเดือนก่อน +2

    Weerey ni baba yiooo,ito sugar kee

  • @ajefela3539
    @ajefela3539 หลายเดือนก่อน +2

    Musulumi pelu wahala,
    Paripasu😂😂

  • @binaryworld4000
    @binaryworld4000 หลายเดือนก่อน +5

    Any Yoruba king still practising islam by this time na big mumu, all these oponu and omo ale musulumi might rebel against our obas one day oo

  • @Ayanwola1
    @Ayanwola1 หลายเดือนก่อน +1

    Awon eniyan wonyi ko fe ki ile yoruba ni Alaafia rara.

  • @akinolaadebayo4566
    @akinolaadebayo4566 หลายเดือนก่อน +5

    Ina ti njo won li je ki awon MUSULUMI pe ipade...kilode ti won fi bere wahala lati ojo gbondikan....Okete ti boru mo yin lowo ooo

  • @sulaimantunrayo
    @sulaimantunrayo หลายเดือนก่อน

    ❤❤❤❤❤❤❤👍👍👍👍👍👍

  • @loantha2996
    @loantha2996 หลายเดือนก่อน +8

    Why can't musulumi stay out of kingship matter

    • @aladesuraju5372
      @aladesuraju5372 หลายเดือนก่อน

      Kingship belong to everyone ,not for elebo sit only

    • @loantha2996
      @loantha2996 หลายเดือนก่อน +1

      @aladesuraju5372 nothing concerns mohamedans. Jagidijagan

    • @Kantz1
      @Kantz1 หลายเดือนก่อน

      @@aladesuraju5372 Oò ṣe máa lọ du ipò ọba ilẹ̀ lárúbáwá where you belong? Àwọn onílùú ló ni seat Ọba, kìí ṣe àwọn ẹlẹ́sìn. Ọba ti ńjẹ k’áwọn àjòjì tóó k’ẹ́sìn wọn wọ ìlúu wa. Wọ́n dé tán, wọ́n fẹ́ẹ́ j’ọba. Eléyìí ò níí yẹ yín lọ́kọ̀ọ̀kan o. Ẹ̀yin ẹrúu Fúlàní.

    • @OmoIrunmole29
      @OmoIrunmole29 หลายเดือนก่อน

      ​@@aladesuraju5372u dey crazy una Muslim get the throne

  • @OmidijiOdunayo
    @OmidijiOdunayo หลายเดือนก่อน

    Ope Ni Fun Eleda Ohungbogbo, Gbogbo Awon To Gbe OFIN Sharia Lowo, E Wo Oju Won Dada, Omo Fulani Ni Won, Ewo Oju Akewugbagold Se O Jo Ti Yoruba Ni, Se Oju Mufty Ati Ti Oluwo Jo Oju Yoruba Nii, Afaemo Ni Ki Won Ma Yan Fulani Ni Oba Oyo... Kosi Eyi To De Ti Awa Beru O.... Enikeni To Ba Gbe Owokowo Ma Ba Esekese And Vice Versa...

  • @AkinropoOlasoji
    @AkinropoOlasoji หลายเดือนก่อน

    O ku oye, omo yeye mi.
    Wa dagba.

  • @Emiola_1
    @Emiola_1 หลายเดือนก่อน +1

    Eranko gbaa ni ibi oju ladeyi
    Always abusive in everywhere he speaks imagine him calling an old man dindinrin kan eranko eeyan

  • @johnsonsamuel758
    @johnsonsamuel758 หลายเดือนก่อน

    E je ki won mo pe a le da ifa ninu Mosque ati Church.Bi won se da ninu oko ni igbaani ti won fi mo pe jonah lo nfa ti iji ati riru omi fi beere lojiji.ki oko won ma ba ba danu won so Jonah si omi, eja nla si gbe mi, o si lo po si eti odo ilu ti o ko lati lo jise Orunmila.
    E wo ashiri awon elesin ajoji sin ma tu bi ti jonah.

  • @Ayanwola1
    @Ayanwola1 หลายเดือนก่อน

    Hun un. Ododo ORO.

  • @FadojuOlatunji
    @FadojuOlatunji หลายเดือนก่อน

    Agba ofo onisonuso

  • @BamideleGabriel-me7nj
    @BamideleGabriel-me7nj หลายเดือนก่อน

    Ojo wo ni eyin omo Yoruba maa se gbogbo radarada yi da bai? E je ka ronu

  • @goldtvwalegold8616
    @goldtvwalegold8616 หลายเดือนก่อน +1

    Wahala…. Lol

  • @yankeeebony5149
    @yankeeebony5149 หลายเดือนก่อน

    It was the monent akeugbagold wrote a note and whispered to him, after that, he stood up and tried to manipulate things in the Islamic way

    • @Kantz1
      @Kantz1 หลายเดือนก่อน

      @@yankeeebony5149 Oníkátikàti l’Akeugbagold. Ṣekuṣẹyẹ ẹ̀dá ni. Bó ṣe ńp’olè wá jà, ló ńp’olóko wá mu.

    • @Kantz1
      @Kantz1 หลายเดือนก่อน

      @@yankeeebony5149 Ṣeku-ṣẹyẹ ni akeugbasand.

    • @Kantz1
      @Kantz1 หลายเดือนก่อน

      Ṣeku-ṣẹyẹ ni akeugbasand.

  • @akinwandetaiwo3263
    @akinwandetaiwo3263 หลายเดือนก่อน

    2 ti ge 4, lobatann 😂😂😂

  • @akinsolakunle-t5h
    @akinsolakunle-t5h หลายเดือนก่อน

    Kole werk.
    Wen ajanguwa and iropoju never desist from their lie lie nd arrangee comparative with dawah😅

  • @ditty6828
    @ditty6828 หลายเดือนก่อน

    😂😂😂😂 won o pe sibe.

  • @debraolufunlalemi7826
    @debraolufunlalemi7826 หลายเดือนก่อน

    Tani Olorun be careful, the man did not talked bad against isese,and why abusive words ,se omolubi yoruba niyen. Stop it and talk with wisdom same time careful. Ma bu eyan now. Oro Internet ma yato ni 2025. Don't pull wahala out.

    • @Kantz1
      @Kantz1 หลายเดือนก่อน

      @@debraolufunlalemi7826 Internet ló tú àṣírí ẹ̀sìn jù ní gbogbo àgbáyé. Kí lo fẹ́ rí ṣe síi ní 2025? O máa ríṣẹ́ ṣe gan-an o.

    • @Kantz1
      @Kantz1 หลายเดือนก่อน

      @@debraolufunlalemi7826 Internet ló tú àṣírí ẹ̀sìn jù ní gbogbo àgbáyé. Kí lo fẹ́ rí ṣe síi ní 2025? O máa ríṣẹ́ ṣe gan-an o.

    • @Kantz1
      @Kantz1 หลายเดือนก่อน

      @@debraolufunlalemi7826 Internet ló tú àṣírí ẹ̀sìn jù ní gbogbo àgbáyé. Kí lo fẹ́ rí ṣe síi ní 2025? O máa ríṣẹ́ ṣe gan-an o.

    • @Kantz1
      @Kantz1 หลายเดือนก่อน

      @@debraolufunlalemi7826 Internet ló tú àṣírí ẹ̀sìn jù ní gbogbo àgbáyé. Kí lo fẹ́ rí ṣe síi ní 2025? O máa ríṣẹ́ ṣe gan-an o.

    • @Kantz1
      @Kantz1 หลายเดือนก่อน

      @@debraolufunlalemi7826 Internet ló tú àṣírí ẹ̀sìn jù ní gbogbo àgbáyé. Kí lo fẹ́ rí ṣe síi ní 2025? O máa ríṣẹ́ ṣe gan-an o.

  • @shollyjshollyj2163
    @shollyjshollyj2163 หลายเดือนก่อน +1

    you are too much

  • @Iyandaeleniyan
    @Iyandaeleniyan หลายเดือนก่อน +1

    mandaru ni iwo tiwon npeni taani olorun yi,oosini ibi koda rara ati rara

    • @halfnigeriaandhalfghana6447
      @halfnigeriaandhalfghana6447 หลายเดือนก่อน +7

      Agbako gbaa ni Islam. Esin ofo.

    • @waleikujuni9463
      @waleikujuni9463 หลายเดือนก่อน +5

      Isilamu Esin Madaru, Alakatakiti, Jagidijagan

    • @binaryworld4000
      @binaryworld4000 หลายเดือนก่อน +1

      Esin islamu esin ikonileru, esin ofo, koni ye allah ati odaran muhamMAD.

    • @binaryworld4000
      @binaryworld4000 หลายเดือนก่อน

      Losi Afghanistan or saudi omo eru

    • @WaleWale-d7y
      @WaleWale-d7y หลายเดือนก่อน

      Omo eru, Oro eru lo maa jade lenu e nitori e o niran.

  • @YusufOlohunkemi-t6y
    @YusufOlohunkemi-t6y หลายเดือนก่อน +1

    Ki ni esin ile yoruba ??

    • @tanimowookusaga4856
      @tanimowookusaga4856 หลายเดือนก่อน +4

      Isese ni esin to da ile Yoruba sile. Oro yiyan Oba ko kan Musulumi.

    • @binaryworld4000
      @binaryworld4000 หลายเดือนก่อน +4

      Losi saudi omo eru, eyin musulumi abo okuta Quraishi. Abo sigidi allah 😂

    • @WaleWale-d7y
      @WaleWale-d7y หลายเดือนก่อน +3

      Oponu se oro niye lenu omo Yoruba. Omo ale lasan.

    • @LewisMuturi-b7u
      @LewisMuturi-b7u หลายเดือนก่อน +1

      Kinni ẹranko àjèjì ọmọ irankinran Gambari-Fulani fẹ́ mọ̀ nípa ìyẹn

    • @LewisMuturi-b7u
      @LewisMuturi-b7u หลายเดือนก่อน +1

      Oloriburuku àjèjì ọmọ irankinran Gambari-Fulani

  • @AkeemJimoh-pf5ru
    @AkeemJimoh-pf5ru หลายเดือนก่อน

    Se jeje boboyi

    • @ibiyimikaige4814
      @ibiyimikaige4814 หลายเดือนก่อน +5

      Tani Olohun is a champion of the Yoruba. We don’t want barbaric sharia in our peaceful Yorubaland. Our fathers have governed Yorubaland for centuries without problems. We don’t need backwardness in Yorubaland.

    • @Kantz1
      @Kantz1 หลายเดือนก่อน +5

      Ki lo kan Musulumi pelu a nf'Oba je jare? S'alaye fun mi. A ti njoba ki iran larubawa to wo ilu wa. Sharia ti e ngbe bo yen ko ni ye yin o.

    • @kiniun5221
      @kiniun5221 หลายเดือนก่อน +3

      Eyin musulumi ẹlẹsin ajoji ọmọale Niyin elo se jẹjẹ Olodumare will continue to guide and protect you adegbola

    • @binaryworld4000
      @binaryworld4000 หลายเดือนก่อน +4

      Omo eru Akeemu. Kini itum oruko re??

    • @WaleWale-d7y
      @WaleWale-d7y หลายเดือนก่อน +3

      Gbenu e soun were

  • @binaryworld4000
    @binaryworld4000 หลายเดือนก่อน

    th-cam.com/users/postUgkx-0pZCg--6eKbzjG6FmTzg8pdA-RwJ3kb?si=M_awCnLLmr60krEJ